ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Orin nípa ọgbà àjàrà Jèhófà (1-7)

      • Ó mà ṣe fún ọgbà àjàrà Jèhófà o (8-24)

      • Ọlọ́run bínú sí àwọn èèyàn rẹ̀ (25-30)

Àìsáyà 5:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 80:8; Ais 5:7; Jer 2:21; Lk 20:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2006, ojú ìwé 17

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 73-74, 76

Àìsáyà 5:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 21:33; Mk 12:1
  • +Ho 10:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2006, ojú ìwé 17-18

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 73-74, 76, 77-78

Àìsáyà 5:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mik 6:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 74-76

Àìsáyà 5:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:15; Isk 24:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 74-76

Àìsáyà 5:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:31, 33; Ne 2:3; Sm 79:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 74-76, 77-78

Àìsáyà 5:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìkùukùu.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 29:22, 23; Jer 25:11; 45:4
  • +Ais 32:13
  • +Di 11:16, 17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 77-78

Àìsáyà 5:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ohun ọ̀gbìn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 80:8; Jer 12:10
  • +Mik 6:8
  • +Di 15:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 75-77, 78-79

Àìsáyà 5:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mik 2:1, 2
  • +1Ọb 21:15, 16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 79-80

Àìsáyà 5:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:20, 21; Ais 27:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 79-80

Àìsáyà 5:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún B14.

  • *

    Ìyẹn, ilẹ̀ tí 20 màlúù tí wọ́n so pọ̀ ní méjì-méjì lè túlẹ̀ rẹ̀ ní ọjọ́ kan.

  • *

    Wo Àfikún B14.

  • *

    Wo Àfikún B14.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:15, 17; Joẹ 1:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 79-80

Àìsáyà 5:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 21:34; Ro 13:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 81

    Yiyan, ojú ìwé 157

Àìsáyà 5:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 81

    Yiyan, ojú ìwé 157

Àìsáyà 5:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 27:11; Jer 8:7; Ho 4:6
  • +Ida 4:9

Àìsáyà 5:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ṣìọ́ọ̀lù,” ìyẹn ibojì aráyé. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

  • *

    Tàbí “àwọn èèyàn rẹ̀ pàtàkì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:63

Àìsáyà 5:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ìdájọ́ òdodo.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 6:3; Ifi 4:8
  • +Di 32:4

Àìsáyà 5:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 82-83

Àìsáyà 5:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìpinnu (ìmọ̀ràn) Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 5:12; 17:15; Isk 12:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 82-84

Àìsáyà 5:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 17:15; Mal 2:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2002, ojú ìwé 9

    8/1/2001, ojú ìwé 8-9

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 82-84

Àìsáyà 5:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 3:7; Ro 12:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 84

Àìsáyà 5:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 23:20; 31:4, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 84

Àìsáyà 5:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 16:19; Ais 1:23; Mik 3:11
  • +1Ọb 21:13; Owe 17:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 84

Àìsáyà 5:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìtọ́ni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:20; 2Ọb 17:13, 14; Ne 9:26; Ais 1:4

Àìsáyà 5:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:16, 17; 2Kr 36:15, 16; Ida 2:2
  • +Jer 16:4

Àìsáyà 5:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gbé òpó sókè láti ṣe àmì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 52:4
  • +Di 28:49, 50; Jer 5:15
  • +Jer 4:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 84-86

Àìsáyà 5:28

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Wọ́n sì ti fẹ́ tafà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Hab 1:8

Àìsáyà 5:29

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọmọ kìnnìún tó tó ọdẹ ṣe (onígọ̀gọ̀).”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 86

Àìsáyà 5:30

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 6:23
  • +Jer 4:23

Àwọn míì

Àìsá. 5:1Sm 80:8; Ais 5:7; Jer 2:21; Lk 20:9
Àìsá. 5:2Mt 21:33; Mk 12:1
Àìsá. 5:2Ho 10:1
Àìsá. 5:3Mik 6:2
Àìsá. 5:42Kr 36:15; Isk 24:13
Àìsá. 5:5Le 26:31, 33; Ne 2:3; Sm 79:1
Àìsá. 5:6Di 29:22, 23; Jer 25:11; 45:4
Àìsá. 5:6Ais 32:13
Àìsá. 5:6Di 11:16, 17
Àìsá. 5:7Sm 80:8; Jer 12:10
Àìsá. 5:7Mik 6:8
Àìsá. 5:7Di 15:9
Àìsá. 5:8Mik 2:1, 2
Àìsá. 5:81Ọb 21:15, 16
Àìsá. 5:92Kr 36:20, 21; Ais 27:10
Àìsá. 5:10Di 28:15, 17; Joẹ 1:17
Àìsá. 5:11Lk 21:34; Ro 13:13
Àìsá. 5:13Ais 27:11; Jer 8:7; Ho 4:6
Àìsá. 5:13Ida 4:9
Àìsá. 5:14Di 28:63
Àìsá. 5:16Ais 6:3; Ifi 4:8
Àìsá. 5:16Di 32:4
Àìsá. 5:19Jer 5:12; 17:15; Isk 12:22
Àìsá. 5:20Owe 17:15; Mal 2:17
Àìsá. 5:21Owe 3:7; Ro 12:16
Àìsá. 5:22Owe 23:20; 31:4, 5
Àìsá. 5:23Di 16:19; Ais 1:23; Mik 3:11
Àìsá. 5:231Ọb 21:13; Owe 17:15
Àìsá. 5:24Di 31:20; 2Ọb 17:13, 14; Ne 9:26; Ais 1:4
Àìsá. 5:25Di 31:16, 17; 2Kr 36:15, 16; Ida 2:2
Àìsá. 5:25Jer 16:4
Àìsá. 5:26Jer 52:4
Àìsá. 5:26Di 28:49, 50; Jer 5:15
Àìsá. 5:26Jer 4:13
Àìsá. 5:28Hab 1:8
Àìsá. 5:29Jer 50:17
Àìsá. 5:30Jer 6:23
Àìsá. 5:30Jer 4:23
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 5:1-30

Àìsáyà

5 Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n kọrin fún ẹni tí mo fẹ́ràn,

Orin tó dá lórí ẹni tí mo nífẹ̀ẹ́ àti ọgbà àjàrà rẹ̀.+

Ẹni tí mo fẹ́ràn ní ọgbà àjàrà kan síbi òkè tó lọ́ràá.

 2 Ó gbẹ́ ibẹ̀, ó sì kó àwọn òkúta ibẹ̀ kúrò.

Ó gbin àjàrà pupa tó dáa sínú rẹ̀,

Ó kọ́ ilé gogoro sí àárín rẹ̀,

Ó sì gbẹ́ ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì sínú rẹ̀.+

Ó wá ń retí pé kí àjàrà náà so,

Àmọ́ èso àjàrà igbó nìkan ló mú jáde. +

 3 “Ní báyìí, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé Jerúsálẹ́mù àti ẹ̀yin èèyàn Júdà,

Ẹ jọ̀ọ́, ẹ ṣèdájọ́ láàárín èmi àti ọgbà àjàrà mi.+

 4 Kí ló tún yẹ kí n ṣe fún ọgbà àjàrà mi

Tí mi ò tíì ṣe?+

Nígbà tí mo retí pé kó so èso àjàrà,

Kí ló dé tó jẹ́ àjàrà igbó nìkan ló ń mú jáde?

 5 Ó yá, ẹ jọ̀ọ́, ẹ jẹ́ kí n sọ fún yín,

Ohun tí màá ṣe sí ọgbà àjàrà mi:

Màá mú ọgbà tó yí i ká kúrò,

Màá sì dáná sun ún.+

Màá fọ́ ògiri olókùúta rẹ̀,

Wọ́n sì máa tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀.

 6 Màá sọ ọ́ di ahoro;+

Wọn ò ní rẹ́wọ́ rẹ̀, wọn ò sì ní ro ó.

Igi ẹlẹ́gùn-ún àti èpò ló máa kún ibẹ̀,+

Màá sì pàṣẹ fún àwọsánmà* pé kó má rọ òjò kankan sórí rẹ̀.+

 7 Torí pé ilé Ísírẹ́lì ni ọgbà àjàrà Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun;+

Àwọn èèyàn Júdà sì ni oko* tó fẹ́ràn.

Ó ń retí ìdájọ́ òdodo,+

Àmọ́ wò ó! ìrẹ́jẹ ló wà;

Ó ń retí òdodo,

Àmọ́ wò ó! igbe ìdààmú ló wà.”+

 8 Àwọn tó ń ní ilé kún ilé gbé +

Àti àwọn tí wọ́n ń ní ilẹ̀ kún ilẹ̀,+

Títí kò fi sí àyè mọ́,

Tó sì wá ku ẹ̀yin nìkan lórí ilẹ̀ náà!

 9 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti búra ní etí mi,

Pé ọ̀pọ̀ ilé, bí wọ́n tiẹ̀ tóbi, tí wọ́n sì rẹwà,

Wọ́n máa di ohun àríbẹ̀rù,

Láìsí olùgbé kankan.+

10 Torí pé òṣùwọ̀n báàtì* kan ṣoṣo ni éékà ilẹ̀ mẹ́wàá* tí wọ́n gbin àjàrà sí máa mú jáde,

Eéfà* kan ṣoṣo sì ni irúgbìn tó jẹ́ òṣùwọ̀n hómérì* kan máa mú jáde.+

11 Àwọn tó ń dìde mu ọtí láàárọ̀ kùtù gbé,+

Tí wọ́n ń dúró síbẹ̀ dìgbà tílẹ̀ ṣú títí ọtí fi ń pa wọ́n!

12 Wọ́n ní háàpù àti ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín,

Ìlù tanboríìnì, fèrè àti wáìnì sì wà níbi àsè wọn;

Àmọ́ wọn ò ronú nípa iṣẹ́ Jèhófà,

Wọn ò sì rí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.

13 Torí náà, àwọn èèyàn mi máa lọ sí ìgbèkùn,

Torí wọn ò ní ìmọ̀;+

Ebi máa pa àwọn èèyàn wọn tó lọ́lá,+

Òùngbẹ sì máa gbẹ gbogbo èèyàn wọn gidigidi.

14 Torí náà, Isà Òkú* ti fẹ ara* rẹ̀ sí i,

Ó sì ti la ẹnu rẹ̀ sílẹ̀ gbayawu láìní ààlà;+

Ó dájú pé iyì rẹ̀,* ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn rẹ̀ tí wọ́n ń pariwo àtàwọn èèyàn rẹ̀ tó ń ṣe àríyá aláriwo

Máa sọ̀ kalẹ̀ lọ sínú rẹ̀.

15 Èèyàn sì máa tẹrí ba,

A máa rẹ èèyàn sílẹ̀,

A sì máa rẹ ojú àwọn agbéraga wálẹ̀.

16 Ìdájọ́* Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa gbé e ga,

Ọlọ́run tòótọ́, Ẹni Mímọ́,+ máa fi òdodo+ sọ ara rẹ̀ di mímọ́.

17 Àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn sì máa jẹko bíi pé ibi ìjẹko wọn ni;

Àwọn àjèjì máa jẹun níbi tó ti dahoro táwọn ẹran tí wọ́n bọ́ dáadáa ti jẹun.

18 Àwọn tó ń fi okùn ẹ̀tàn fa ẹ̀bi wọn lọ gbé,

Tí wọ́n sì ń fi okùn kẹ̀kẹ́ ẹṣin fa ẹ̀ṣẹ̀ wọn;

19 Àwọn tó ń sọ pé: “Kó jẹ́ kí iṣẹ́ Rẹ̀ yára kánkán;

Kó tètè dé, ká lè rí i.

Kí ohun tí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì ní lọ́kàn* ṣẹ,

Ká lè mọ̀ ọ́n!”+

20 Àwọn tó ń sọ pé ohun tó dára burú àti pé ohun tó burú dára gbé,+

Àwọn tó ń fi òkùnkùn dípò ìmọ́lẹ̀, tí wọ́n sì ń fi ìmọ́lẹ̀ dípò òkùnkùn,

Àwọn tó ń fi ìkorò dípò adùn àti adùn dípò ìkorò!

21 Àwọn tó gbọ́n lójú ara wọn gbé,

Tí wọ́n jẹ́ olóye lójú ara wọn!+

22 Àwọn akọni nídìí ọtí mímu gbé

Àti àwọn tó mọ àdàlù ọtí ṣe dáadáa,+

23 Àwọn tó dá ẹni burúkú láre torí àbẹ̀tẹ́lẹ̀,+

Tí wọn ò sì jẹ́ kí olódodo rí ìdájọ́ òdodo gbà!+

24 Torí náà, bí ahọ́n iná ṣe máa ń jó àgékù pòròpórò run,

Tí koríko gbígbẹ sì máa ń rún sínú ọwọ́ iná,

Gbòǹgbò wọn gangan máa jẹra,

Ìtànná wọn sì máa fọ́n ká bí eruku,

Torí pé wọ́n kọ òfin* Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,

Wọn ò sì ka ọ̀rọ̀ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì sí.+

25 Ìdí nìyẹn tí Jèhófà fi bínú gidigidi sí àwọn èèyàn rẹ̀,

Ó sì máa na ọwọ́ rẹ̀ lòdì sí wọn, ó máa lù wọ́n.+

Àwọn òkè máa mì tìtì,

Òkú wọn sì máa dà bí ààtàn lójú ọ̀nà.+

Pẹ̀lú gbogbo èyí, ìbínú rẹ̀ kò tíì yí pa dà,

Àmọ́ ó ṣì na ọwọ́ rẹ̀ jáde láti lù wọ́n.

26 Ó ti gbé àmì sókè* sí orílẹ̀-èdè tó wà lọ́nà jíjìn;+

Ó ti súfèé sí wọn pé kí wọ́n wá láti àwọn ìkángun ayé;+

Sì wò ó! wọ́n ń yára bọ̀.+

27 Kò rẹ ẹnì kankan nínú wọn, wọn ò sì kọsẹ̀.

Ìkankan nínú wọn ò tòògbé, wọn ò sì sùn.

Àmùrè tó wà ní ìbàdí wọn ò tú,

Okùn bàtà wọn ò sì já.

28 Gbogbo ọfà wọn mú,

Wọ́n sì ti fa gbogbo ọrun wọn.*

Pátákò àwọn ẹṣin wọn dà bí akọ òkúta,

Àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ wọn sì dà bí ìjì.+

29 Wọ́n ń ké ramúramù bíi kìnnìún;

Wọ́n ń ké ramúramù bí àwọn ọmọ kìnnìún.*+

Wọ́n máa kùn, wọ́n sì máa mú ẹran,

Wọ́n á gbé e lọ, kò sì ní sẹ́ni tó máa gbà á lọ́wọ́ wọn.

30 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa kùn lórí rẹ̀,

Bí òkun ṣe ń ru.+

Òkùnkùn tó ń kó ìdààmú báni ni ẹnikẹ́ni tó bá tẹjú mọ́ ilẹ̀ náà máa rí;

Ìmọ́lẹ̀ pàápàá ti ṣókùnkùn nítorí ìkùukùu.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́