ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 54
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Síónì tó yàgàn máa ní ọmọ púpọ̀ (1-17)

        • Jèhófà, ọkọ Síónì (5)

        • Jèhófà máa kọ́ àwọn ọmọ Síónì (13)

        • Ohun ìjà tí wọ́n bá ṣe sí Síónì kò ní ṣàṣeyọrí (17)

Àìsáyà 54:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọkùnrin.”

  • *

    Tàbí “ọ̀gá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 62:4
  • +Ais 44:23; 49:13
  • +Ais 66:7, 8
  • +Ga 4:26, 27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2006, ojú ìwé 11

    8/1/1995, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 216-221

Àìsáyà 54:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:20
  • +Ais 33:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 221-222

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1995, ojú ìwé 16

Àìsáyà 54:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:8; Isk 36:35

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 221-223

Àìsáyà 54:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:10
  • +Ais 61:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 221, 223-224

Àìsáyà 54:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọ̀gá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 44:2
  • +Isk 16:8; Ho 2:16
  • +Ais 44:6
  • +Sek 14:9; Ro 3:29

Àìsáyà 54:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “tí ẹ̀mí rẹ̀ sì gbọgbẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:14; 62:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 224

Àìsáyà 54:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 30:1, 3; Sm 30:5; 106:47; Ais 27:12; Jer 29:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 224-226

Àìsáyà 54:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 47:6; Isk 39:23
  • +Ais 55:3
  • +Ais 48:17; 49:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 224-226

Àìsáyà 54:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 7:23
  • +Jẹ 8:21
  • +Jer 31:35, 36; Isk 39:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 226-227

Àìsáyà 54:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 51:6
  • +Ais 55:3
  • +Ais 14:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 226-227

Àìsáyà 54:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 52:2
  • +Ida 1:2, 17
  • +Ifi 21:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 227-228

Àìsáyà 54:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òkúta iná.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 227-228

Àìsáyà 54:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọkùnrin.”

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọkùnrin.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 31:34; Jo 6:45
  • +Sm 119:165; Ais 66:12; Jer 33:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 177-178

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 227, 228-229

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    8/1/1995, ojú ìwé 9, 11, 13

    4/1/1994, ojú ìwé 13

    3/1/1991, ojú ìwé 23

Àìsáyà 54:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 1:26; 60:21
  • +Ais 52:1
  • +Jer 23:4; Sef 3:13

Àìsáyà 54:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 38:16, 22; Sek 2:8; 12:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 227, 229

Àìsáyà 54:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 10:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 229

Àìsáyà 54:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ohun àjogúnbá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 2:2, 4; Ais 41:12
  • +Jer 23:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2019, ojú ìwé 6-7

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 28

    9/15/2008, ojú ìwé 7-8

    12/15/2007, ojú ìwé 21-22, 25

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 229-230

Àwọn míì

Àìsá. 54:1Ais 62:4
Àìsá. 54:1Ais 44:23; 49:13
Àìsá. 54:1Ais 66:7, 8
Àìsá. 54:1Ga 4:26, 27
Àìsá. 54:2Ais 49:20
Àìsá. 54:2Ais 33:20
Àìsá. 54:3Ais 49:8; Isk 36:35
Àìsá. 54:4Ais 41:10
Àìsá. 54:4Ais 61:7
Àìsá. 54:5Ais 44:2
Àìsá. 54:5Isk 16:8; Ho 2:16
Àìsá. 54:5Ais 44:6
Àìsá. 54:5Sek 14:9; Ro 3:29
Àìsá. 54:6Ais 49:14; 62:4
Àìsá. 54:7Di 30:1, 3; Sm 30:5; 106:47; Ais 27:12; Jer 29:10
Àìsá. 54:8Ais 47:6; Isk 39:23
Àìsá. 54:8Ais 55:3
Àìsá. 54:8Ais 48:17; 49:26
Àìsá. 54:9Jẹ 7:23
Àìsá. 54:9Jẹ 8:21
Àìsá. 54:9Jer 31:35, 36; Isk 39:29
Àìsá. 54:10Ais 51:6
Àìsá. 54:10Ais 55:3
Àìsá. 54:10Ais 14:1
Àìsá. 54:11Ais 52:2
Àìsá. 54:11Ida 1:2, 17
Àìsá. 54:11Ifi 21:19
Àìsá. 54:13Jer 31:34; Jo 6:45
Àìsá. 54:13Sm 119:165; Ais 66:12; Jer 33:6
Àìsá. 54:14Ais 1:26; 60:21
Àìsá. 54:14Ais 52:1
Àìsá. 54:14Jer 23:4; Sef 3:13
Àìsá. 54:15Isk 38:16, 22; Sek 2:8; 12:3
Àìsá. 54:16Ais 10:5
Àìsá. 54:17Sm 2:2, 4; Ais 41:12
Àìsá. 54:17Jer 23:6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 54:1-17

Àìsáyà

54 “Kígbe ayọ̀, ìwọ àgàn tí kò bímọ!+

Tújú ká, kí o sì kígbe ayọ̀,+ ìwọ tí o kò ní ìrora ìbímọ rí,+

Torí àwọn ọmọ* ẹni tó ti di ahoro pọ̀

Ju àwọn ọmọ obìnrin tó ní ọkọ,”*+ ni Jèhófà wí.

 2 “Mú kí ibi àgọ́ rẹ fẹ̀ sí i.+

Na àwọn aṣọ àgọ́ rẹ tó tóbi.

Má fawọ́ sẹ́yìn, mú kí àwọn okùn àgọ́ rẹ gùn sí i,

Kí o sì jẹ́ kí àwọn èèkàn àgọ́ rẹ lágbára.+

 3 Torí pé o máa tàn sí apá ọ̀tún àti sí apá òsì.

Àwọn ọmọ rẹ máa gba àwọn orílẹ̀-èdè,

Wọ́n sì máa gbé àwọn ìlú tó ti di ahoro.+

 4 Má bẹ̀rù,+ torí ojú ò ní tì ọ́;+

Má sì jẹ́ kí ìtìjú bá ọ, torí o ò ní rí ìjákulẹ̀.

Torí o máa gbàgbé ìtìjú ìgbà ọ̀dọ́ rẹ,

O ò sì ní rántí bí ojú ṣe tì ọ́ nígbà opó rẹ mọ́.”

 5 “Torí pé Aṣẹ̀dá rẹ Atóbilọ́lá+ dà bí ọkọ* rẹ,+

Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀,

Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì sì ni Olùtúnrà rẹ.+

Ọlọ́run gbogbo ayé la ó máa pè é.+

 6 Torí Jèhófà pè ọ́ bí ìyàwó tí wọ́n pa tì, tí ẹ̀dùn ọkàn sì bá,*+

Bí ìyàwó tí wọ́n fẹ́ nígbà ọ̀dọ́, tí wọ́n wá kọ̀ sílẹ̀,” ni Ọlọ́run rẹ wí.

 7 “Torí mo pa ọ́ tì fún ìgbà díẹ̀,

Àmọ́ màá ṣàánú rẹ gidigidi, màá sì kó ọ jọ pa dà.+

 8 Mo fi ojú mi pa mọ́ fún ọ fún àkókò díẹ̀ torí inú bí mi gidigidi,+

Àmọ́ màá ṣàánú rẹ nítorí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, tó wà títí láé,”+ ni Jèhófà, Olùtúnrà rẹ+ wí.

 9 “Bí àwọn ọjọ́ Nóà ló ṣe rí sí mi.+

Bí mo ṣe búra pé omi Nóà ò ní bo ayé mọ́,+

Bẹ́ẹ̀ náà ni mo búra pé mi ò ní bínú sí ọ mọ́, mi ò sì ní bá ọ wí mọ́.+

10 Àwọn òkè ńlá lè ṣí kúrò,

Àwọn òkè kéékèèké sì lè mì tìtì,

Àmọ́ ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ ò ní kúrò lọ́dọ̀ rẹ,+

Májẹ̀mú àlàáfíà mi ò sì ní mì,”+ ni Jèhófà, Ẹni tó ń ṣàánú rẹ wí.+

11 “Ìwọ obìnrin tí ìyà ń jẹ,+ tí ìjì ń gbé síwá-sẹ́yìn, tí a kò tù nínú,+

Màá fi àpòrọ́ líle mọ àwọn òkúta rẹ,

Màá sì fi sàfáyà ṣe ìpìlẹ̀ rẹ.+

12 Òkúta rúbì ni màá fi ṣe odi orí òrùlé rẹ,

Àwọn òkúta tó ń tàn yinrin* ni màá fi ṣe àwọn ẹnubodè rẹ,

Màá sì fi àwọn òkúta iyebíye ṣe gbogbo ààlà rẹ.

13 Jèhófà máa kọ́ gbogbo àwọn ọmọ* rẹ,+

Àlàáfíà àwọn ọmọ* rẹ sì máa pọ̀ gan-an.+

14 O máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in nínú òdodo.+

Ìnilára máa jìnnà réré sí ọ,+

O ò ní bẹ̀rù ohunkóhun, ohunkóhun ò sì ní já ọ láyà,

Torí pé kò ní sún mọ́ ọ.+

15 Tí ẹnikẹ́ni bá gbéjà kò ọ́,

Èmi kọ́ ni mo pa á láṣẹ.

Ẹnikẹ́ni tó bá gbéjà kò ọ́ máa ṣubú nítorí rẹ.”+

16 “Wò ó! Èmi fúnra mi ni mo dá oníṣẹ́ ọnà,

Ẹni tó ń fẹ́ atẹ́gùn sí iná èédú,

Tí iṣẹ́ rẹ̀ sì mú ohun ìjà jáde.

Èmi náà ni mo dá apanirun tó ń pani run.+

17 Ohun ìjà èyíkéyìí tí wọ́n bá ṣe sí ọ kò ní ṣàṣeyọrí,+

Ahọ́n èyíkéyìí tó bá sì dìde sí ọ láti dá ọ lẹ́jọ́ ni wàá dá lẹ́bi.

Ogún* àwọn ìránṣẹ́ Jèhófà nìyí,

Ọ̀dọ̀ mi sì ni òdodo wọn ti wá,” ni Jèhófà wí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́