ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 23
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Léfítíkù

      • Àwọn ọjọ́ mímọ́ àti àwọn àjọyọ̀ (1-44)

        • Sábáàtì (3)

        • Ìrékọjá (4, 5)

        • Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú (6-8)

        • Fífi àwọn àkọ́so ṣe ọrẹ (9-14)

        • Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ (15-21)

        • Kíkórè bó ṣe tọ́ (22)

        • Àjọyọ̀ Ìró Kàkàkí (23-25)

        • Ọjọ́ Ètùtù (26-32)

        • Àjọyọ̀ Àtíbàbà (33-43)

Léfítíkù 23:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:14; Le 23:37
  • +Nọ 10:10

Léfítíkù 23:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 16:30; 20:10; Iṣe 15:21
  • +Ne 13:22

Léfítíkù 23:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Láàárín ìrọ̀lẹ́ méjèèjì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 9:2, 3; 28:16
  • +Ẹk 12:3, 6; Di 16:1; 1Kọ 5:7

Léfítíkù 23:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 28:17; 1Kọ 5:8
  • +Ẹk 12:15; 13:6; 34:18

Léfítíkù 23:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 12:16

Léfítíkù 23:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 15:20, 23
  • +Nọ 18:8, 12; Owe 3:9; Isk 44:30

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2007, ojú ìwé 26

Léfítíkù 23:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2007, ojú ìwé 26

Léfítíkù 23:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìdá méjì nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà jẹ́ Lítà 4.4. Wo Àfikún B14.

  • *

    Tàbí “tó tuni lójú.” Ní Héb., “atura.”

  • *

    Òṣùwọ̀n hínì kan jẹ́ Lítà 3.67. Wo Àfikún B14.

Léfítíkù 23:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:22; Di 16:9, 10

Léfítíkù 23:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 2:1
  • +Nọ 28:26-31; Di 16:16

Léfítíkù 23:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìdá méjì nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà jẹ́ Lítà 4.4. Wo Àfikún B14.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 7:11, 13
  • +Ẹk 23:16; 34:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2021,

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/1998, ojú ìwé 13

Léfítíkù 23:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó tuni lójú.” Ní Héb., “atura.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 28:26, 27

Léfítíkù 23:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 4:23
  • +Le 3:1

Léfítíkù 23:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 7:34; 10:14; Nọ 18:9; Di 18:4; 1Kọ 9:13

Léfítíkù 23:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 10:10

Léfítíkù 23:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn tí ìyà ń jẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:9; Di 24:19; Rut 2:2, 3
  • +Ais 58:7
  • +Le 19:33

Léfítíkù 23:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 10:10; 29:1

Léfítíkù 23:27

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn yín.” Kí èèyàn “pọ́n ara rẹ̀ lójú” sábà máa ń túmọ̀ sí kí èèyàn fi oríṣiríṣi nǹkan du ara rẹ̀, irú bíi kó gbààwẹ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 30:10; Le 25:9
  • +Le 16:29, 30; Nọ 29:7

Léfítíkù 23:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 16:34; Heb 9:12, 24-26; 10:10; 1Jo 2:1, 2

Léfítíkù 23:29

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn èyíkéyìí.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “tí kò bá gbààwẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 9:13; 15:30

Léfítíkù 23:30

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ọkàn èyíkéyìí.”

Léfítíkù 23:32

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 16:29-31; 23:27; Nọ 29:7

Léfítíkù 23:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:16; Nọ 29:12; Di 16:13; Ẹsr 3:4; Ne 8:14-18; Jo 7:2

Léfítíkù 23:36

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ne 8:18

Léfítíkù 23:37

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:14; Di 16:16
  • +Nọ 28:26; 29:7
  • +Le 1:3
  • +Le 2:1, 11
  • +Nọ 15:5; 28:6, 7

Léfítíkù 23:38

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 16:23; 20:8; 31:13
  • +Ẹk 28:38; Nọ 18:29
  • +Di 12:11
  • +Nọ 29:39; Di 12:6; 1Kr 29:9; 2Kr 35:8; Ẹsr 2:68

Léfítíkù 23:39

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 16:13
  • +Nọ 29:12

Léfítíkù 23:40

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ne 8:15; Ifi 7:9
  • +Ne 8:10
  • +Di 16:15

Léfítíkù 23:41

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 29:12

Léfítíkù 23:42

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:10, 11

Léfítíkù 23:43

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:13; Sm 78:6
  • +Ẹk 12:37, 38; Nọ 24:5

Àwọn míì

Léf. 23:2Ẹk 23:14; Le 23:37
Léf. 23:2Nọ 10:10
Léf. 23:3Ẹk 16:30; 20:10; Iṣe 15:21
Léf. 23:3Ne 13:22
Léf. 23:5Nọ 9:2, 3; 28:16
Léf. 23:5Ẹk 12:3, 6; Di 16:1; 1Kọ 5:7
Léf. 23:6Nọ 28:17; 1Kọ 5:8
Léf. 23:6Ẹk 12:15; 13:6; 34:18
Léf. 23:7Ẹk 12:16
Léf. 23:101Kọ 15:20, 23
Léf. 23:10Nọ 18:8, 12; Owe 3:9; Isk 44:30
Léf. 23:15Ẹk 34:22; Di 16:9, 10
Léf. 23:16Iṣe 2:1
Léf. 23:16Nọ 28:26-31; Di 16:16
Léf. 23:17Le 7:11, 13
Léf. 23:17Ẹk 23:16; 34:22
Léf. 23:18Nọ 28:26, 27
Léf. 23:19Le 4:23
Léf. 23:19Le 3:1
Léf. 23:20Le 7:34; 10:14; Nọ 18:9; Di 18:4; 1Kọ 9:13
Léf. 23:21Nọ 10:10
Léf. 23:22Le 19:9; Di 24:19; Rut 2:2, 3
Léf. 23:22Ais 58:7
Léf. 23:22Le 19:33
Léf. 23:24Nọ 10:10; 29:1
Léf. 23:27Ẹk 30:10; Le 25:9
Léf. 23:27Le 16:29, 30; Nọ 29:7
Léf. 23:28Le 16:34; Heb 9:12, 24-26; 10:10; 1Jo 2:1, 2
Léf. 23:29Nọ 9:13; 15:30
Léf. 23:32Le 16:29-31; 23:27; Nọ 29:7
Léf. 23:34Ẹk 23:16; Nọ 29:12; Di 16:13; Ẹsr 3:4; Ne 8:14-18; Jo 7:2
Léf. 23:36Ne 8:18
Léf. 23:37Ẹk 23:14; Di 16:16
Léf. 23:37Nọ 28:26; 29:7
Léf. 23:37Le 1:3
Léf. 23:37Le 2:1, 11
Léf. 23:37Nọ 15:5; 28:6, 7
Léf. 23:38Ẹk 16:23; 20:8; 31:13
Léf. 23:38Ẹk 28:38; Nọ 18:29
Léf. 23:38Di 12:11
Léf. 23:38Nọ 29:39; Di 12:6; 1Kr 29:9; 2Kr 35:8; Ẹsr 2:68
Léf. 23:39Di 16:13
Léf. 23:39Nọ 29:12
Léf. 23:40Ne 8:15; Ifi 7:9
Léf. 23:40Ne 8:10
Léf. 23:40Di 16:15
Léf. 23:41Nọ 29:12
Léf. 23:42Di 31:10, 11
Léf. 23:43Di 31:13; Sm 78:6
Léf. 23:43Ẹk 12:37, 38; Nọ 24:5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
  • 39
  • 40
  • 41
  • 42
  • 43
  • 44
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Léfítíkù 23:1-44

Léfítíkù

23 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Àwọn àjọyọ̀ àtìgbàdégbà+ tó jẹ́ ti Jèhófà tí ẹ máa kéde+ jẹ́ àpéjọ mímọ́. Èyí ni àwọn àjọyọ̀ mi àtìgbàdégbà:

3 “‘Ọjọ́ mẹ́fà ni kí ẹ fi ṣiṣẹ́, àmọ́ kí ọjọ́ keje jẹ́ sábáàtì, tí ẹ ò ní ṣiṣẹ́ rárá,+ kó jẹ́ àpéjọ mímọ́. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan. Sábáàtì ni kó jẹ́ sí Jèhófà níbikíbi tí ẹ bá ń gbé.+

4 “‘Èyí ni àwọn àjọyọ̀ àtìgbàdégbà tó jẹ́ ti Jèhófà, àwọn àpéjọ mímọ́ tí ẹ máa kéde ní àwọn àkókò tí mo yàn fún wọn: 5 Ìrọ̀lẹ́* ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní+ ni kí ẹ ṣe Ìrékọjá+ fún Jèhófà.

6 “‘Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù yìí ni Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú+ fún Jèhófà. Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi jẹ búrẹ́dì aláìwú.+ 7 Ní ọjọ́ kìíní, kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣiṣẹ́ agbára kankan. 8 Àmọ́ kí ẹ ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà fún ọjọ́ méje. Ní ọjọ́ keje, àpéjọ mímọ́ máa wà. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára kankan.’”

9 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 10 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí ẹ bá dé ilẹ̀ tí màá fún yín, tí ẹ sì ti kórè oko rẹ̀, kí ẹ mú ìtí àkọ́so+ ìkórè yín wá fún àlùfáà.+ 11 Yóò sì fi ìtí náà síwá-sẹ́yìn níwájú Jèhófà kí ẹ lè rí ìtẹ́wọ́gbà. Ọjọ́ tó tẹ̀ lé sábáàtì ni kí àlùfáà fì í. 12 Ní ọjọ́ tí ẹ bá wá fi ìtí náà, kí ẹ fi ọmọ àgbò ọlọ́dún kan tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá rúbọ, kí ẹ fi rú ẹbọ sísun sí Jèhófà. 13 Ọrẹ ọkà rẹ̀ máa jẹ́ ìyẹ̀fun tó kúnná tó jẹ́ ìdá méjì nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà,* tí wọ́n pò mọ́ òróró, kí ẹ fi ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, tó máa mú òórùn dídùn* jáde. Ọrẹ ohun mímu rẹ̀ máa jẹ́ wáìnì tó kún ìlàrin òṣùwọ̀n hínì.* 14 Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ búrẹ́dì kankan, ọkà tí wọ́n yan tàbí ọkà tuntun títí di ọjọ́ yìí, títí ẹ ó fi mú ọrẹ Ọlọ́run yín wá. Àṣẹ tí gbogbo ìran yín á máa pa mọ́ títí lọ ni, níbikíbi tí ẹ bá ń gbé.

15 “‘Kí ẹ ka sábáàtì méje láti ọjọ́ tó tẹ̀ lé Sábáàtì, láti ọjọ́ tí ẹ mú ìtí ọrẹ fífì+ náà wá. Kí ọjọ́ àwọn ọ̀sẹ̀ náà pé. 16 Kí ẹ ka àádọ́ta (50) ọjọ́+ títí dé ọjọ́ tó tẹ̀ lé Sábáàtì keje, kí ẹ wá mú ọrẹ ọkà tuntun wá fún Jèhófà.+ 17 Kí ẹ mú ìṣù búrẹ́dì méjì wá láti ibi tí ẹ̀ ń gbé kí ẹ fi ṣe ọrẹ fífì. Ìyẹ̀fun tó kúnná tó jẹ́ ìdá méjì nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà* ni kí ẹ fi ṣe é. Kí ẹ fi ìwúkàrà sí i,+ kí ẹ sì yan án, kí ẹ fi ṣe àkọ́pọ́n èso fún Jèhófà.+ 18 Kí ẹ mú akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méje, tí ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ ọlọ́dún kan, tí ara wọn dá ṣáṣá àti ọmọ akọ màlúù kan àti àgbò+ méjì, kí ẹ mú wọn wá pẹ̀lú àwọn búrẹ́dì náà. Kí ẹ fi wọ́n rú ẹbọ sísun sí Jèhófà pẹ̀lú ọrẹ ọkà wọn àti ọrẹ ohun mímu wọn, kó jẹ́ ọrẹ àfinásun sí Jèhófà tó ń mú òórùn dídùn* jáde. 19 Kí ẹ fi ọmọ ewúrẹ́ kan rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀,+ kí ẹ sì fi akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méjì tí ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ ọlọ́dún kan rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀.+ 20 Kí àlùfáà fì wọ́n síwá-sẹ́yìn pẹ̀lú àwọn búrẹ́dì tí ẹ fi ṣe àkọ́pọ́n èso, kó fi ṣe ọrẹ fífì níwájú Jèhófà, pẹ̀lú akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méjì náà. Kí wọ́n jẹ́ ohun mímọ́ sí Jèhófà fún àlùfáà náà.+ 21 Ní ọjọ́ yìí, kí ẹ kéde+ àpéjọ mímọ́ fún ara yín. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára kankan. Àṣẹ tí gbogbo ìran yín á máa pa mọ́ títí lọ ni, ní gbogbo ibi tí ẹ̀ ń gbé.

22 “‘Tí ẹ bá kórè oko yín, ẹ ò gbọ́dọ̀ kárúgbìn eteetí oko yín tán, ẹ má sì ṣa ohun tó bá ṣẹ́ kù lẹ́yìn tí ẹ kórè.+ Kí ẹ fi í sílẹ̀ fún àwọn aláìní*+ àti àjèjì.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.’”

23 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 24 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Ní ọjọ́ kìíní oṣù keje, kí ẹ sinmi, kí ẹ má ṣiṣẹ́ kankan, kí ẹ fi ìró kàkàkí+ kéde rẹ̀ láti máa rántí, yóò jẹ́ àpéjọ mímọ́. 25 Ẹ má ṣiṣẹ́ agbára kankan, kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.’”

26 Jèhófà tún sọ fún Mósè pé: 27 “Ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí ni Ọjọ́ Ètùtù.+ Kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́, kí ẹ pọ́n ara yín* lójú,+ kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. 28 Ẹ má ṣe iṣẹ́ kankan ní ọjọ́ yìí gangan, torí ó jẹ́ ọjọ́ ètùtù tí wọ́n á ṣe ètùtù+ fún yín níwájú Jèhófà Ọlọ́run yín. 29 Kí ẹ pa ẹnikẹ́ni* tí kò bá pọ́n ara rẹ̀ lójú* ní ọjọ́ yìí, kí ẹ lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.+ 30 Ẹnikẹ́ni* tó bá ṣiṣẹ́ kankan lọ́jọ́ náà, ṣe ni màá pa á run kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀. 31 Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan. Àṣẹ tí gbogbo ìran yín á máa pa mọ́ títí lọ ni, níbikíbi tí ẹ bá ń gbé. 32 Sábáàtì ló jẹ́ fún yín, ọjọ́ ìsinmi tí ẹ ò ní ṣiṣẹ́ rárá, kí ẹ sì pọ́n ara yín* lójú+ ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹsàn-án oṣù. Láti ìrọ̀lẹ́ dé ìrọ̀lẹ́ ni kí ẹ máa pa sábáàtì yín mọ́.”

33 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 34 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù keje yìí ni Àjọyọ̀ Àtíbàbà fún Jèhófà, ọjọ́ méje ni kí ẹ fi ṣe é.+ 35 Àpéjọ mímọ́ yóò wà ní ọjọ́ kìíní, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára kankan. 36 Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. Ní ọjọ́ kẹjọ, kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́,+ kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. Àpéjọ ọlọ́wọ̀ ni. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára kankan.

37 “‘Èyí ni àwọn àjọyọ̀ àtìgbàdégbà+ tó jẹ́ ti Jèhófà tí ẹ máa kéde pé wọ́n jẹ́ àpéjọ mímọ́,+ láti máa fi mú ọrẹ àfinásun wá fún Jèhófà: ẹbọ sísun+ àti ọrẹ ọkà+ tó jẹ́ ti ẹbọ àti àwọn ọrẹ ohun mímu+ gẹ́gẹ́ bí ètò ojoojúmọ́. 38 Nǹkan wọ̀nyí jẹ́ àfikún sí ohun tí ẹ fi rúbọ ní àwọn sábáàtì Jèhófà+ àti àwọn ẹ̀bùn yín,+ àwọn ọrẹ tí ẹ jẹ́jẹ̀ẹ́+ àti àwọn ọrẹ àtinúwá yín,+ tí ẹ máa fún Jèhófà. 39 Ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù keje, tí ẹ bá ti kórè èso ilẹ̀ náà, kí ẹ fi ọjọ́ méje+ ṣe àjọyọ̀ fún Jèhófà. Ní ọjọ́ kìíní, kí ẹ sinmi, kí ẹ má ṣiṣẹ́ rárá. Ní ọjọ́ kẹjọ pẹ̀lú, kí ẹ sinmi, kí ẹ má ṣiṣẹ́ rárá.+ 40 Ní ọjọ́ kìíní, kí ẹ mú èso àwọn igi ńláńlá, àwọn imọ̀ ọ̀pẹ,+ àwọn ẹ̀ka igi eléwé púpọ̀ àti àwọn igi pọ́pílà tó wà ní àfonífojì, kí ẹ sì yọ̀+ níwájú Jèhófà Ọlọ́run yín fún ọjọ́ méje.+ 41 Ọjọ́ méje ni kí ẹ máa fi ṣe àjọyọ̀ náà fún Jèhófà lọ́dọọdún.+ Àṣẹ tí gbogbo ìran yín á máa pa mọ́ títí lọ ni. Oṣù keje ni kí ẹ máa ṣe é. 42 Inú àtíbàbà ni kí ẹ gbé fún ọjọ́ méje.+ Kí gbogbo àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Ísírẹ́lì gbé inú àtíbàbà, 43 kí àwọn ìran yín tó ń bọ̀ lè mọ̀+ pé inú àtíbàbà ni mo mú kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbé nígbà tí mo mú wọn kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.’”

44 Mósè sì sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nípa àwọn àjọyọ̀ àtìgbàdégbà ti Jèhófà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́