ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 145
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Ẹ yin Ọlọ́run, Ọba ńlá

        • ‘Màá kéde títóbi Ọlọ́run’ (6)

        • “Jèhófà ń ṣoore fún gbogbo ẹ̀dá” (9)

        • ‘Àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ yóò máa yìn ọ́’ (10)

        • Ìjọba Ọlọ́run tó máa wà títí láé (13)

        • Ọwọ́ Ọlọ́run ń tẹ́ gbogbo ẹ̀dá lọ́rùn (16)

Sáàmù 145:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 33:22; Ifi 11:17
  • +1Kr 29:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 10-11

Sáàmù 145:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 119:164
  • +Sm 146:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 10-11

Sáàmù 145:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Títóbi rẹ̀ kọjá òye ẹ̀dá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 150:2; Ro 1:20; Ifi 15:3
  • +Job 26:14; Sm 139:6; Ro 11:33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 11-13

Sáàmù 145:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 12:26, 27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 13-14

Sáàmù 145:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 8:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2008, ojú ìwé 14

    1/15/2004, ojú ìwé 13-14

Sáàmù 145:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “nípa agbára.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2008, ojú ìwé 14

    1/15/2004, ojú ìwé 13-14

Sáàmù 145:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 8:66; Sm 13:6; 31:19; Ais 63:7; Jer 31:12
  • +Sm 51:14; Ifi 15:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 279

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 14-15

Sáàmù 145:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “olóore ọ̀fẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 30:9; Ef 2:4
  • +Ẹk 34:6; Ne 9:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 14-15

Sáàmù 145:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 25:8; Na 1:7; Mt 5:44, 45; Iṣe 14:17; Jem 1:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 271-272

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 14-15

Sáàmù 145:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 19:1
  • +Sm 30:4; Heb 13:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 16

Sáàmù 145:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 10:8, 9
  • +Di 3:24; 1Kr 29:11; Ifi 15:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 16

Sáàmù 145:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 98:1
  • +Sm 103:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 16-17

Sáàmù 145:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 146:10; 1Ti 1:17

Sáàmù 145:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 37:23, 24; 94:18
  • +Sm 146:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 17-18

Sáàmù 145:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:30; Sm 136:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 18-19

Sáàmù 145:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 104:27, 28; 107:9; 132:14, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 33

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 18-19

Sáàmù 145:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 18:25; Di 32:4
  • +Sm 18:25; Ifi 15:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 19

Sáàmù 145:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó ń fòótọ́ inú ké pè é.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 34:18; Jem 4:8
  • +Sm 17:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    No. 1 2021 ojú ìwé 14

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 20

Sáàmù 145:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 34:9
  • +Sm 37:39, 40; 50:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    No. 1 2021 ojú ìwé 14

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 20

Sáàmù 145:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 31:23; 97:10
  • +Owe 2:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 20

    12/15/2002, ojú ìwé 14-16

Sáàmù 145:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “gbogbo ẹran ara.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 34:1; 51:15
  • +Sm 117:1; 150:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 20

Àwọn míì

Sm 145:1Ais 33:22; Ifi 11:17
Sm 145:11Kr 29:10
Sm 145:2Sm 119:164
Sm 145:2Sm 146:2
Sm 145:3Sm 150:2; Ro 1:20; Ifi 15:3
Sm 145:3Job 26:14; Sm 139:6; Ro 11:33
Sm 145:4Ẹk 12:26, 27
Sm 145:5Sm 8:1
Sm 145:71Ọb 8:66; Sm 13:6; 31:19; Ais 63:7; Jer 31:12
Sm 145:7Sm 51:14; Ifi 15:3
Sm 145:82Kr 30:9; Ef 2:4
Sm 145:8Ẹk 34:6; Ne 9:17
Sm 145:9Sm 25:8; Na 1:7; Mt 5:44, 45; Iṣe 14:17; Jem 1:17
Sm 145:10Sm 19:1
Sm 145:10Sm 30:4; Heb 13:15
Sm 145:11Lk 10:8, 9
Sm 145:11Di 3:24; 1Kr 29:11; Ifi 15:3
Sm 145:12Sm 98:1
Sm 145:12Sm 103:19
Sm 145:13Sm 146:10; 1Ti 1:17
Sm 145:14Sm 37:23, 24; 94:18
Sm 145:14Sm 146:8
Sm 145:15Jẹ 1:30; Sm 136:25
Sm 145:16Sm 104:27, 28; 107:9; 132:14, 15
Sm 145:17Jẹ 18:25; Di 32:4
Sm 145:17Sm 18:25; Ifi 15:3, 4
Sm 145:18Sm 34:18; Jem 4:8
Sm 145:18Sm 17:1
Sm 145:19Sm 34:9
Sm 145:19Sm 37:39, 40; 50:15
Sm 145:20Sm 31:23; 97:10
Sm 145:20Owe 2:22
Sm 145:21Sm 34:1; 51:15
Sm 145:21Sm 117:1; 150:6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 145:1-21

Sáàmù

Ìyìn Dáfídì.

א [Áléfì]

145 Màá gbé ọ ga, ìwọ Ọlọ́run mi Ọba,+

Màá yin orúkọ rẹ títí láé àti láéláé.+

ב [Bétì]

2 Màá yìn ọ́ láti àárọ̀ ṣúlẹ̀;+

Màá yin orúkọ rẹ títí láé àti láéláé.+

ג [Gímélì]

3 Jèhófà tóbi, òun sì ni ìyìn yẹ jù lọ,+

Àwámáridìí ni títóbi rẹ̀.*+

ד [Dálétì]

4 Ìran dé ìran yóò máa yin àwọn iṣẹ́ rẹ;

Wọ́n á máa sọ nípa iṣẹ́ ńlá rẹ.+

ה [Híì]

5 Wọ́n á máa sọ nípa ọlá ńlá ológo iyì rẹ,+

Màá sì máa ṣe àṣàrò lórí àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ.

ו [Wọ́ọ̀]

6 Wọ́n á máa sọ nípa àwọn iṣẹ́* àgbàyanu rẹ,

Màá sì máa kéde títóbi rẹ.

ז [Sáyìn]

7 Wọ́n á máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀ bí wọ́n ṣe ń sọ nípa ọ̀pọ̀ oore rẹ,+

Wọ́n á sì máa kígbe ayọ̀ nítorí òdodo rẹ.+

ח [Hétì]

8 Jèhófà jẹ́ agbatẹnirò* àti aláàánú,+

Kì í tètè bínú, ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ sì pọ̀ gidigidi.+

ט [Tétì]

9 Jèhófà ń ṣoore fún gbogbo ẹ̀dá,+

Àánú rẹ̀ sì wà lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ̀.

י [Yódì]

10 Jèhófà, gbogbo iṣẹ́ rẹ yóò máa yìn ọ́ lógo,+

Àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ yóò sì máa yìn ọ́.+

כ [Káfì]

11 Wọ́n á máa kéde ògo ìjọba rẹ,+

Wọ́n á sì máa sọ̀rọ̀ nípa agbára rẹ,+

ל [Lámédì]

12 Kí aráyé lè mọ àwọn iṣẹ́ ńlá rẹ+

Àti ògo ọlá ńlá ìjọba rẹ.+

מ [Mémì]

13 Ìjọba ayérayé ni ìjọba rẹ,

Àkóso rẹ sì wà láti ìran dé ìran.+

ס [Sámékì]

14 Jèhófà ń gbé gbogbo àwọn tó ti fẹ́ ṣubú ró,+

Ó sì ń gbé gbogbo àwọn tó dorí kodò dìde.+

ע [Áyìn]

15 Ojú rẹ ni gbogbo ẹ̀dá ń wò,

Ò ń fún wọn ní oúnjẹ wọn lásìkò.+

פ [Péè]

16 O ṣí ọwọ́ rẹ,

O sì fún gbogbo ohun alààyè ní ohun tí wọ́n ń fẹ́.+

צ [Sádì]

17 Jèhófà jẹ́ olódodo ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀,+

Ó sì jẹ́ adúróṣinṣin nínú gbogbo ohun tó ń ṣe.+

ק [Kófì]

18 Jèhófà wà nítòsí gbogbo àwọn tó ń ké pè é,+

Nítòsí gbogbo àwọn tó ń ké pè é ní òtítọ́.*+

ר [Réṣì]

19 Ó ń fún àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀ ní ohun tí ọkàn wọn ń fẹ́;+

Ó ń gbọ́ igbe wọn fún ìrànlọ́wọ́, ó sì ń gbà wọ́n.+

ש [Ṣínì]

20 Jèhófà ń ṣọ́ gbogbo àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀,+

Àmọ́ yóò pa gbogbo ẹni burúkú run.+

ת [Tọ́ọ̀]

21 Ẹnu mi yóò kéde ìyìn Jèhófà;+

Kí gbogbo ohun alààyè* máa yin orúkọ mímọ́ rẹ̀ títí láé àti láéláé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́