Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 8, 2000
Bíbá Ẹ̀mí Lò Ṣé ó Ń ranni Lọ́wọ́ Ni Tàbí ó Ń pani Lára?
Èé ṣe tí àwọn èèyàn púpọ̀ tó bẹ́ẹ̀ jákèjádò ayé fi ń bá ẹ̀mí lò? Ó ha léwu bí? Bó bá rí bẹ́ẹ̀, báwo lo ṣe lè dáàbò bo ara rẹ?
3 Èé Ṣe Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Fi Nífẹ̀ẹ́ Sí Ìbẹ́mìílò?
4 Ìdí Tó Fi Yẹ Kí O Yẹra Fún Ìbẹ́mìílò
12 Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Fi Ẹ̀dùn Ọkàn Hàn?
14 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
15 Ìrèké—Àràbà Ni Láàárín Àwọn Koríko
19 Ǹjẹ́ Ó Ti Tó Àkókò Láti Ní Bẹ́ẹ̀dì Tuntun?
27 Pátímọ́sì—Erékùṣù Àpókálíìsì
30 Wíwo Ayé
31 Wọ́n Gbé Òtítọ́ Pa Mọ́ fún Àádọ́ta Ọdún—Èé Ṣe?
32 Títọ́ Àwọn Ọmọ Di Ẹni Tó Lẹ́kọ̀ọ́—Báwo La Ṣe Lè Ṣe É?
Èdè—Òun Ló Ń Ṣínà Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀, Òun Náà Ló Ń Dènà Rẹ̀ 9
Ibo ni èdè ti pilẹ̀ ṣẹ̀? Báwo ni wọ́n ṣe lè mú kí àjọṣe ẹ̀dá dára tàbí kó bà jẹ́?
Ṣíṣe Ara Lọ́ṣọ̀ọ́—Ìdí Tí A Kò Fi Gbọ́dọ̀ Ṣàṣejù