ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 40
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́kísódù

      • Wọ́n to àgọ́ ìjọsìn (1-33)

      • Ògo Jèhófà kún inú àgọ́ ìjọsìn (34-38)

Ẹ́kísódù 40:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 7:1

Ẹ́kísódù 40:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 25:21
  • +Nọ 4:5; Heb 9:3

Ẹ́kísódù 40:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 26:35
  • +Ẹk 25:31; Heb 9:2
  • +Ẹk 25:37

Ẹ́kísódù 40:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aṣọ ìdábùú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 30:1
  • +Ẹk 26:36

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 10/2020, ojú ìwé 4-5

Ẹ́kísódù 40:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 38:1

Ẹ́kísódù 40:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 30:18

Ẹ́kísódù 40:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aṣọ ìdábùú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 27:9
  • +Ẹk 27:16; 38:18

Ẹ́kísódù 40:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 30:23-25
  • +Le 8:10; Nọ 7:1

Ẹ́kísódù 40:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 29:36, 37; Le 8:11

Ẹ́kísódù 40:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 8:6

Ẹ́kísódù 40:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 29:5; Le 8:7
  • +Le 8:12; Sm 133:2

Ẹ́kísódù 40:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 8:13

Ẹ́kísódù 40:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 8:30
  • +Heb 7:11

Ẹ́kísódù 40:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 39:43; Di 4:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    12/15/1995, ojú ìwé 13

Ẹ́kísódù 40:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 7:1; 9:15

Ẹ́kísódù 40:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 36:24
  • +Ẹk 26:15
  • +Ẹk 36:31

Ẹ́kísódù 40:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 26:7
  • +Ẹk 26:14

Ẹ́kísódù 40:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 31:18
  • +Ẹk 25:22; 37:1
  • +Ẹk 37:4; 1Ọb 8:8
  • +Ẹk 37:6; 1Kr 28:11
  • +Le 16:2

Ẹ́kísódù 40:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 36:35; Heb 10:19, 20
  • +Heb 9:3

Ẹ́kísódù 40:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 37:10; Heb 9:2

Ẹ́kísódù 40:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 25:30; Mt 12:4

Ẹ́kísódù 40:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 37:17

Ẹ́kísódù 40:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 25:37; 37:23

Ẹ́kísódù 40:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 30:1; 37:25

Ẹ́kísódù 40:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 30:34, 35
  • +Ẹk 30:7

Ẹ́kísódù 40:28

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aṣọ ìdábùú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 26:36; 36:37

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2000, ojú ìwé 15

Ẹ́kísódù 40:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 38:1
  • +Ẹk 29:38

Ẹ́kísódù 40:30

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 30:18

Ẹ́kísódù 40:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 30:18, 19

Ẹ́kísódù 40:33

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aṣọ ìdábùú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 27:9; 38:9
  • +Ẹk 38:18

Ẹ́kísódù 40:34

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 9:15; Ifi 15:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 115

Ẹ́kísódù 40:35

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 5:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 115

Ẹ́kísódù 40:36

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 10:11; Ne 9:19

Ẹ́kísódù 40:37

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 9:17, 22

Ẹ́kísódù 40:38

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 13:21; Nọ 9:16; Sm 78:14

Àwọn míì

Ẹ́kís. 40:2Nọ 7:1
Ẹ́kís. 40:3Ẹk 25:21
Ẹ́kís. 40:3Nọ 4:5; Heb 9:3
Ẹ́kís. 40:4Ẹk 26:35
Ẹ́kís. 40:4Ẹk 25:31; Heb 9:2
Ẹ́kís. 40:4Ẹk 25:37
Ẹ́kís. 40:5Ẹk 30:1
Ẹ́kís. 40:5Ẹk 26:36
Ẹ́kís. 40:6Ẹk 38:1
Ẹ́kís. 40:7Ẹk 30:18
Ẹ́kís. 40:8Ẹk 27:9
Ẹ́kís. 40:8Ẹk 27:16; 38:18
Ẹ́kís. 40:9Ẹk 30:23-25
Ẹ́kís. 40:9Le 8:10; Nọ 7:1
Ẹ́kís. 40:10Ẹk 29:36, 37; Le 8:11
Ẹ́kís. 40:12Le 8:6
Ẹ́kís. 40:13Ẹk 29:5; Le 8:7
Ẹ́kís. 40:13Le 8:12; Sm 133:2
Ẹ́kís. 40:14Le 8:13
Ẹ́kís. 40:15Le 8:30
Ẹ́kís. 40:15Heb 7:11
Ẹ́kís. 40:16Ẹk 39:43; Di 4:2
Ẹ́kís. 40:17Nọ 7:1; 9:15
Ẹ́kís. 40:18Ẹk 36:24
Ẹ́kís. 40:18Ẹk 26:15
Ẹ́kís. 40:18Ẹk 36:31
Ẹ́kís. 40:19Ẹk 26:7
Ẹ́kís. 40:19Ẹk 26:14
Ẹ́kís. 40:20Ẹk 31:18
Ẹ́kís. 40:20Ẹk 25:22; 37:1
Ẹ́kís. 40:20Ẹk 37:4; 1Ọb 8:8
Ẹ́kís. 40:20Ẹk 37:6; 1Kr 28:11
Ẹ́kís. 40:20Le 16:2
Ẹ́kís. 40:21Ẹk 36:35; Heb 10:19, 20
Ẹ́kís. 40:21Heb 9:3
Ẹ́kís. 40:22Ẹk 37:10; Heb 9:2
Ẹ́kís. 40:23Ẹk 25:30; Mt 12:4
Ẹ́kís. 40:24Ẹk 37:17
Ẹ́kís. 40:25Ẹk 25:37; 37:23
Ẹ́kís. 40:26Ẹk 30:1; 37:25
Ẹ́kís. 40:27Ẹk 30:34, 35
Ẹ́kís. 40:27Ẹk 30:7
Ẹ́kís. 40:28Ẹk 26:36; 36:37
Ẹ́kís. 40:29Ẹk 38:1
Ẹ́kís. 40:29Ẹk 29:38
Ẹ́kís. 40:30Ẹk 30:18
Ẹ́kís. 40:32Ẹk 30:18, 19
Ẹ́kís. 40:33Ẹk 27:9; 38:9
Ẹ́kís. 40:33Ẹk 38:18
Ẹ́kís. 40:34Nọ 9:15; Ifi 15:8
Ẹ́kís. 40:352Kr 5:14
Ẹ́kís. 40:36Nọ 10:11; Ne 9:19
Ẹ́kís. 40:37Nọ 9:17, 22
Ẹ́kís. 40:38Ẹk 13:21; Nọ 9:16; Sm 78:14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ẹ́kísódù 40:1-38

Ẹ́kísódù

40 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: 2 “Ní ọjọ́ kìíní oṣù kìíní, kí o to àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ ìpàdé náà.+ 3 Gbé àpótí Ẹ̀rí sínú rẹ̀,+ kí o sì ta aṣọ ìdábùú bo ibi tí Àpótí náà wà.+ 4 Kí o gbé tábìlì+ náà wọlé, kí o sì to àwọn nǹkan tó yẹ kó wà lórí rẹ̀ síbẹ̀, kí o wá gbé ọ̀pá fìtílà+ wọlé, kí o sì tan àwọn fìtílà rẹ̀.+ 5 Kí o gbé pẹpẹ tùràrí+ tí wọ́n fi wúrà ṣe síwájú àpótí Ẹ̀rí, kí o sì ta aṣọ* sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìjọsìn.+

6 “Kí o gbé pẹpẹ ẹbọ sísun+ síwájú ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ ìpàdé náà, 7 kí o gbé bàsíà sáàárín àgọ́ ìpàdé àti pẹpẹ, kí o sì bu omi sínú rẹ̀.+ 8 Kí o wá ṣe àgbàlá+ yí i ká, kí o sì ta aṣọ*+ sí ẹnu ọ̀nà àgbàlá náà. 9 Lẹ́yìn náà, kí o gbé òróró àfiyanni,+ kí o fòróró yan àgọ́ ìjọsìn náà àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀,+ kí o sì ya àgọ́ náà àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ sí mímọ́, kó lè di ohun mímọ́. 10 Kí o fòróró yan pẹpẹ ẹbọ sísun àti gbogbo ohun èlò rẹ̀, kí o sì ya pẹpẹ náà sí mímọ́, kó lè di pẹpẹ mímọ́ jù lọ.+ 11 Kí o fòróró yan bàsíà àti ẹsẹ̀ rẹ̀, kí o sì yà á sí mímọ́.

12 “Lẹ́yìn náà, kí o mú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ sún mọ́ ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, kí o sì fi omi wẹ̀ wọ́n.+ 13 Kí o wọ àwọn aṣọ mímọ́ náà fún Áárónì,+ kí o fòróró yàn án,+ kí o sì sọ ọ́ di mímọ́, yóò sì di àlùfáà mi. 14 Kí o wá mú àwọn ọmọ rẹ̀ sún mọ́ tòsí, kí o sì wọ aṣọ fún wọn.+ 15 Kí o fòróró yàn wọ́n bí o ṣe fòróró yan bàbá wọn,+ kí wọ́n lè di àlùfáà mi, ìran wọn á sì máa ṣiṣẹ́ àlùfáà títí lọ torí o ti fòróró yàn wọ́n.”+

16 Mósè ṣe gbogbo ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún un.+ Ó ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́.

17 Ní ọjọ́ kìíní, oṣù kìíní, ọdún kejì, wọ́n to àgọ́ ìjọsìn náà.+ 18 Nígbà tí Mósè to àgọ́ ìjọsìn náà, ó fi àwọn ìtẹ́lẹ̀ oníhò rẹ̀+ sísàlẹ̀, ó to àwọn férémù,+ ó fi àwọn ọ̀pá gbọọrọ rẹ̀+ sí i, ó sì to àwọn òpó rẹ̀. 19 Ó fi aṣọ àgọ́+ bo àgọ́ ìjọsìn náà, ó sì fi ìbòrí+ àgọ́ náà bò ó, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.

20 Lẹ́yìn náà, ó mú Ẹ̀rí,+ ó sì fi sínú Àpótí náà.+ Ó ki àwọn ọ̀pá+ sí ẹ̀gbẹ́ Àpótí náà, ó sì fi ìbòrí+ bo Àpótí náà.+ 21 Ó gbé Àpótí náà wá sínú àgọ́ ìjọsìn, ó sì ta aṣọ ìdábùú+ bo ibẹ̀. Ó fi bo ibi tí àpótí Ẹ̀rí náà+ wà, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.

22 Lẹ́yìn náà, ó gbé tábìlì+ sínú àgọ́ ìpàdé ní apá àríwá àgọ́ ìjọsìn náà ní ìta aṣọ ìdábùú, 23 ó sì to búrẹ́dì+ náà sórí ara wọn lórí rẹ̀ níwájú Jèhófà, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.

24 Ó gbé ọ̀pá fìtílà+ sínú àgọ́ ìpàdé níwájú tábìlì náà, ní apá gúúsù àgọ́ ìjọsìn náà. 25 Ó tan àwọn fìtílà+ náà níwájú Jèhófà, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.

26 Lẹ́yìn náà, ó gbé pẹpẹ wúrà+ sínú àgọ́ ìpàdé níwájú aṣọ ìdábùú, 27 kó lè mú kí tùràrí onílọ́fínńdà+ rú èéfín lórí rẹ̀,+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.

28 Ó wá ta aṣọ*+ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìjọsìn náà.

29 Ó gbé pẹpẹ ẹbọ sísun+ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ ìpàdé náà, kó lè fi ẹbọ sísun+ àti ọrẹ ọkà rúbọ lórí rẹ̀, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.

30 Lẹ́yìn náà, ó gbé bàsíà sí àárín àgọ́ ìpàdé àti pẹpẹ, ó sì bu omi sínú rẹ̀ fún wíwẹ̀.+ 31 Mósè àti Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wẹ ọwọ́ àti ẹsẹ̀ wọn níbẹ̀. 32 Nígbàkigbà tí wọ́n bá wọnú àgọ́ ìpàdé tàbí tí wọ́n bá sún mọ́ pẹpẹ, wọ́n á wẹ̀,+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.

33 Níkẹyìn, ó ṣe àgbàlá+ yí àgọ́ ìjọsìn àti pẹpẹ náà ká, ó sì ta aṣọ* sí ẹnu ọ̀nà àgbàlá náà.+

Bí Mósè ṣe parí iṣẹ́ náà nìyẹn. 34 Ìkùukùu* sì bẹ̀rẹ̀ sí í bo àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+ 35 Mósè ò lè wọnú àgọ́ ìpàdé torí pé ìkùukùu ò kúrò lórí àgọ́ náà, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+

36 Tí ìkùukùu bá ti kúrò lórí àgọ́ ìjọsìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa tú àgọ́ wọn ká bí wọ́n ṣe ń lọ láti ibì kan sí ibòmíì lẹ́nu gbogbo ìrìn àjò wọn.+ 37 Àmọ́, tí ìkùukùu náà ò bá kúrò, wọn ò ní tú àgọ́ wọn ká títí di ọjọ́ tí ìkùukùu náà bá kúrò.+ 38 Torí ìkùukùu Jèhófà máa ń wà lórí àgọ́ ìjọsìn náà ní ọ̀sán, iná sì máa ń wà lórí rẹ̀ ní òru, gbogbo ilé Ísírẹ́lì sì máa ń rí i, bí wọ́n ṣe ń lọ láti ibì kan sí ibòmíì lẹ́nu gbogbo ìrìn àjò wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́