ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 139
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Ọlọ́run mọ àwọn ìránṣẹ́ rẹ dáadáa

        • Kò sẹ́ni tó lè sá mọ́ ẹ̀mí Ọlọ́run lọ́wọ́ (7)

        • “O ṣẹ̀dá mi tìyanutìyanu” (14)

        • ‘O rí mi nígbà tí mo ṣì wà nínú ikùn’ (16)

        • “Darí mi sí ọ̀nà ayérayé” (24)

Sáàmù 139:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 16:6, 7; 1Kr 28:9; Sm 17:3; 139:23; Jer 20:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2011, ojú ìwé 15

    10/1/1993, ojú ìwé 11

Sáàmù 139:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 16:13
  • +Sm 94:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2011, ojú ìwé 15

    10/1/1993, ojú ìwé 11-12

Sáàmù 139:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “díwọ̀n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 28:15; 2Sa 8:14; Job 31:4; Sm 121:8; Owe 5:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2011, ojú ìwé 15

    6/1/2006, ojú ìwé 6

    4/1/1995, ojú ìwé 12-13

    10/1/1993, ojú ìwé 11-12

Sáàmù 139:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 4:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2014, ojú ìwé 4-5

    10/1/1993, ojú ìwé 12

Sáàmù 139:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1993, ojú ìwé 12

Sáàmù 139:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “yà mí lẹ́nu gan-an.”

  • *

    Tàbí “jinlẹ̀ ju ohun tí mo lè lóye.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 26:14; 42:3; Sm 40:5; Ro 11:33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1993, ojú ìwé 12

Sáàmù 139:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jon 1:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2011, ojú ìwé 27

    10/1/1993, ojú ìwé 12-14

    Jí!,

    7/2011, ojú ìwé 24-25

Sáàmù 139:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ṣìọ́ọ̀lù,” ìyẹn ibojì aráyé. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 26:6; Owe 15:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2011, ojú ìwé 27

    10/1/1993, ojú ìwé 12-14

Sáàmù 139:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2011, ojú ìwé 27

    10/1/1993, ojú ìwé 12-14

Sáàmù 139:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 63:8; 73:23; Ais 41:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2011, ojú ìwé 27

    10/1/1993, ojú ìwé 12-14

Sáàmù 139:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1993, ojú ìwé 12-14

Sáàmù 139:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 2:22
  • +Heb 4:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1993, ojú ìwé 12-14

Sáàmù 139:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “hun mí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 22:9; 71:6; Jer 1:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 38

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2007, ojú ìwé 21-22

    10/1/1993, ojú ìwé 14

Sáàmù 139:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ọkàn mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:26
  • +Sm 19:1; 104:24; 111:2; Ifi 15:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 171-173

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2007, ojú ìwé 21

    4/1/1996, ojú ìwé 13-14

    10/1/1993, ojú ìwé 14

    8/1/1992, ojú ìwé 3-4

    Ète Igbesi-Aye, ojú ìwé 9-10

Sáàmù 139:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 10:10, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 38

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2007, ojú ìwé 22

    10/1/1993, ojú ìwé 14

Sáàmù 139:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tí mo ṣì jẹ́ ọlẹ̀.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 38

    Jí!,

    No. 3 2017 ojú ìwé 4

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 172

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2007, ojú ìwé 22-23

    4/15/1999, ojú ìwé 4-5

    10/1/1993, ojú ìwé 14

    5/15/1992, ojú ìwé 4

Sáàmù 139:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 55:9
  • +Ro 11:33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2007, ojú ìwé 23-24

    10/1/1993, ojú ìwé 16-18

Sáàmù 139:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́., “màá ṣì máa kà wọ́n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 40:5
  • +Sm 63:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2007, ojú ìwé 23-24

    10/1/1993, ojú ìwé 18

Sáàmù 139:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹlẹ́bi ẹ̀jẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 5:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1993, ojú ìwé 19

Sáàmù 139:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “lórí èrò tiwọn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1993, ojú ìwé 19

Sáàmù 139:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 19:2; 2Kọ 6:14
  • +Sm 119:158

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    12/8/1997, ojú ìwé 14

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1993, ojú ìwé 19

Sáàmù 139:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 101:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1993, ojú ìwé 19

Sáàmù 139:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó ń dà mí lọ́kàn rú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 20:12
  • +Sm 94:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 60

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2009, ojú ìwé 3

    6/15/2007, ojú ìwé 24-25

    9/1/2006, ojú ìwé 16

    6/15/2001, ojú ìwé 22-23

    3/15/1995, ojú ìwé 6

    10/1/1993, ojú ìwé 19-20

Sáàmù 139:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 17:3
  • +Sm 5:8; 143:8, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 60

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2020, ojú ìwé 29

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2007, ojú ìwé 24-25

    9/1/2006, ojú ìwé 16

    6/15/2001, ojú ìwé 22-23

    10/1/1993, ojú ìwé 19-20

Àwọn míì

Sm 139:11Sa 16:6, 7; 1Kr 28:9; Sm 17:3; 139:23; Jer 20:12
Sm 139:2Jẹ 16:13
Sm 139:2Sm 94:11
Sm 139:3Jẹ 28:15; 2Sa 8:14; Job 31:4; Sm 121:8; Owe 5:21
Sm 139:4Heb 4:12
Sm 139:6Job 26:14; 42:3; Sm 40:5; Ro 11:33
Sm 139:7Jon 1:3
Sm 139:8Job 26:6; Owe 15:11
Sm 139:10Sm 63:8; 73:23; Ais 41:13
Sm 139:12Da 2:22
Sm 139:12Heb 4:13
Sm 139:13Sm 22:9; 71:6; Jer 1:5
Sm 139:14Jẹ 1:26
Sm 139:14Sm 19:1; 104:24; 111:2; Ifi 15:3
Sm 139:15Job 10:10, 11
Sm 139:17Ais 55:9
Sm 139:17Ro 11:33
Sm 139:18Sm 40:5
Sm 139:18Sm 63:6
Sm 139:19Sm 5:6
Sm 139:20Ẹk 20:7
Sm 139:212Kr 19:2; 2Kọ 6:14
Sm 139:21Sm 119:158
Sm 139:22Sm 101:3
Sm 139:23Jer 20:12
Sm 139:23Sm 94:19
Sm 139:24Sm 17:3
Sm 139:24Sm 5:8; 143:8, 10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 139:1-24

Sáàmù

Fún olùdarí. Ti Dáfídì. Orin.

139 Jèhófà, o ti yẹ̀ mí wò látòkè délẹ̀, o sì mọ̀ mí.+

2 O mọ ìgbà tí mo bá jókòó àti ìgbà tí mo bá dìde.+

Láti ibi tó jìnnà réré, o mọ ohun tí mò ń rò.+

3 Ò ń kíyè sí* mi nígbà tí mo bá ń rìnrìn àjò àti nígbà tí mo bá dùbúlẹ̀;

Gbogbo àwọn ọ̀nà mi ò ṣàjèjì sí ọ.+

4 Kí n tó sọ̀rọ̀ jáde lẹ́nu,

Wò ó, Jèhófà, o ti mọ gbogbo ohun tí mo fẹ́ sọ.+

5 Lẹ́yìn mi àti níwájú mi, o yí mi ká;

O sì gbé ọwọ́ rẹ lé mi.

6 Irú ìmọ̀ bẹ́ẹ̀ kọjá òye mi.*

Ó kọjá ohun tí ọwọ́ mi lè tẹ̀.*+

7 Ibo ni mo lè sá sí tí màá fi bọ́ lọ́wọ́ ẹ̀mí rẹ,

Ibo ni mo sì lè sá lọ kí ojú rẹ má bàa tó mi?+

8 Tí mo bá lọ sọ́run, wàá wà níbẹ̀,

Tí mo bá sì tẹ́ ibùsùn mi sínú Isà Òkú,* wò ó! wàá ti wà níbẹ̀.+

9 Tí mo bá fi ìyẹ́ apá ọ̀yẹ̀ fò lọ,

Kí n lè máa gbé létí òkun tó jìnnà jù lọ,

10 Kódà, ọwọ́ rẹ yóò darí mi níbẹ̀,

Ọwọ́ ọ̀tún rẹ yóò sì dì mí mú.+

11 Tí mo bá sọ pé: “Dájúdájú, òkùnkùn yóò fi mí pa mọ́!”

Nígbà náà, òkùnkùn tó yí mi ká yóò di ìmọ́lẹ̀.

12 Kódà, òkùnkùn náà kò ní ṣú jù fún ọ,

Ṣe ni òru yóò mọ́lẹ̀ bí ọ̀sán;+

Ìkan náà ni òkùnkùn àti ìmọ́lẹ̀ lójú rẹ.+

13 Ìwọ lo ṣe àwọn kíndìnrín mi;

O yà mí sọ́tọ̀* ní inú ìyá mi.+

14 Mo yìn ọ́ nítorí pé lọ́nà tó ń bani lẹ́rù ni o ṣẹ̀dá mi tìyanutìyanu.+

Àgbàyanu ni àwọn iṣẹ́ rẹ,+

Mo* mọ èyí dáadáa.

15 Àwọn egungun mi ò pa mọ́ fún ọ

Nígbà tí o ṣẹ̀dá mi ní ìkọ̀kọ̀,

Nígbà tí o hun mí ní ìsàlẹ̀ ayé.+

16 Kódà, ojú rẹ rí mi nígbà tí mo ṣì wà nínú ikùn;*

Gbogbo àwọn ẹ̀yà rẹ̀ wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé rẹ

Ní ti àwọn ọjọ́ tí o ṣẹ̀dá wọn,

Kí ìkankan lára wọn tó wà.

17 Lójú tèmi, àwọn ìrònú rẹ mà ṣeyebíye o!+

Ọlọ́run, àròpọ̀ iye wọn mà pọ̀ o!+

18 Tí mo bá ní kí n máa kà wọ́n, wọ́n pọ̀ ju iyanrìn lọ.+

Nígbà tí mo jí, mo ṣì wà pẹ̀lú rẹ.*+

19 Ọlọ́run, ká ní o bá pa ẹni burúkú!+

Nígbà náà, àwọn oníwà ipá* yóò kúrò lọ́dọ̀ mi,

20 Àwọn tó ń sọ̀rọ̀ rẹ pẹ̀lú èrò ibi lọ́kàn;*

Àwọn ni ọ̀tá rẹ tí wọ́n ń lo orúkọ rẹ lọ́nà tí kò ní láárí.+

21 Mo kórìíra àwọn tó kórìíra rẹ, Jèhófà,+

Mi ò sì nífẹ̀ẹ́ àwọn tó ń dìtẹ̀ sí ọ.+

22 Mo kórìíra wọn gan-an;+

Wọ́n ti di ọ̀tá paraku sí mi.

23 Yẹ̀ mí wò látòkè délẹ̀, Ọlọ́run, kí o sì mọ ọkàn mi.+

Ṣàyẹ̀wò mi, kí o sì mọ àwọn ohun tó ń gbé mi lọ́kàn sókè.*+

24 Wò ó bóyá ìwà burúkú kankan wà nínú mi,+

Kí o sì darí mi+ sí ọ̀nà ayérayé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́