ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kọ́ríńtì

      • Àwọn ará Kọ́ríńtì ṣì jẹ́ ẹni tara (1-4)

      • Ọlọ́run ń mú kó dàgbà (5-9)

        • Alábàáṣiṣẹ́ pẹ̀lú Ọlọ́run (9)

      • Fi ohun tí kò lè jóná kọ́lé (10-15)

      • Ẹ̀yin ni tẹ́ńpìlì Ọlọ́run (16, 17)

      • Ọgbọ́n ayé jẹ́ òmùgọ̀ lọ́dọ̀ Ọlọ́run (18-23)

1 Kọ́ríńtì 3:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 2:15; Kol 1:9
  • +1Kọ 14:20

1 Kọ́ríńtì 3:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 5:12-14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 29

1 Kọ́ríńtì 3:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:7, 8
  • +Ga 5:19, 20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1991, ojú ìwé 21-22

1 Kọ́ríńtì 3:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 18:24, 25

1 Kọ́ríńtì 3:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 3:5, 6; Kol 1:23; 1Ti 1:12

1 Kọ́ríńtì 3:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 18:4
  • +Iṣe 18:26-28; 19:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2021, ojú ìwé 3

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1999, ojú ìwé 12

    10/1/1996, ojú ìwé 22

    3/1/1993, ojú ìwé 20-23

1 Kọ́ríńtì 3:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 9:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 12, 16

    3/1/1993, ojú ìwé 20-23

1 Kọ́ríńtì 3:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “èrò kan náà ni ẹni tó ń gbìn àti ẹni tó ń bomi rin ní.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 2:6; 1Kọ 4:5; Ifi 22:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2018, ojú ìwé 15

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 92

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 13-14

    Mẹtalọkan, ojú ìwé 24

1 Kọ́ríńtì 3:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 2:22; 1Pe 2:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2021, ojú ìwé 3

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 21

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2018, ojú ìwé 23

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2012, ojú ìwé 17

    7/15/1999, ojú ìwé 12

    11/1/1998, ojú ìwé 8

    3/1/1993, ojú ìwé 21

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 132

1 Kọ́ríńtì 3:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọlọ́gbọ́n olùdarí àwọn iṣẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 15:20; Heb 6:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1999, ojú ìwé 13

    11/1/1998, ojú ìwé 8-10, 14-15

1 Kọ́ríńtì 3:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 118:22; Ais 28:16; Mt 21:42; Ef 2:20; 1Pe 2:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1999, ojú ìwé 13-14

    11/1/1998, ojú ìwé 9-10

    7/1/1991, ojú ìwé 24-25

1 Kọ́ríńtì 3:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1999, ojú ìwé 12-13

    11/1/1998, ojú ìwé 10-13

    7/1/1991, ojú ìwé 26

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 55

1 Kọ́ríńtì 3:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “fara hàn kedere.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 4:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1999, ojú ìwé 12-13

    12/15/1998, ojú ìwé 30

    11/1/1998, ojú ìwé 10-11

    7/1/1991, ojú ìwé 27

1 Kọ́ríńtì 3:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/1998, ojú ìwé 11-12

    7/1/1991, ojú ìwé 27

1 Kọ́ríńtì 3:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/1998, ojú ìwé 11-13

1 Kọ́ríńtì 3:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 6:16; Ef 2:21; 1Pe 2:5
  • +1Kọ 6:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 29

1 Kọ́ríńtì 3:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 2:5

1 Kọ́ríńtì 3:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àsìkò yìí.” Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    9/15/1992, ojú ìwé 24

1 Kọ́ríńtì 3:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 5:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2019, ojú ìwé 21-25

1 Kọ́ríńtì 3:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 94:11

1 Kọ́ríńtì 3:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wọ́n tún ń pè é ní Pétérù.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 1:12

1 Kọ́ríńtì 3:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:9; 2Kọ 10:7

Àwọn míì

1 Kọ́r. 3:11Kọ 2:15; Kol 1:9
1 Kọ́r. 3:11Kọ 14:20
1 Kọ́r. 3:2Heb 5:12-14
1 Kọ́r. 3:3Ro 8:7, 8
1 Kọ́r. 3:3Ga 5:19, 20
1 Kọ́r. 3:4Iṣe 18:24, 25
1 Kọ́r. 3:52Kọ 3:5, 6; Kol 1:23; 1Ti 1:12
1 Kọ́r. 3:6Iṣe 18:4
1 Kọ́r. 3:6Iṣe 18:26-28; 19:1
1 Kọ́r. 3:7Ro 9:16
1 Kọ́r. 3:8Ro 2:6; 1Kọ 4:5; Ifi 22:12
1 Kọ́r. 3:9Ef 2:22; 1Pe 2:5
1 Kọ́r. 3:10Ro 15:20; Heb 6:1
1 Kọ́r. 3:11Sm 118:22; Ais 28:16; Mt 21:42; Ef 2:20; 1Pe 2:6
1 Kọ́r. 3:131Pe 4:12
1 Kọ́r. 3:162Kọ 6:16; Ef 2:21; 1Pe 2:5
1 Kọ́r. 3:161Kọ 6:19
1 Kọ́r. 3:171Pe 2:5
1 Kọ́r. 3:19Job 5:13
1 Kọ́r. 3:20Sm 94:11
1 Kọ́r. 3:221Kọ 1:12
1 Kọ́r. 3:23Jo 17:9; 2Kọ 10:7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kọ́ríńtì 3:1-23

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

3 Nítorí náà, ẹ̀yin ará, mi ò lè bá yín sọ̀rọ̀ bí ẹní ń bá àwọn ẹni tẹ̀mí sọ̀rọ̀,+ àmọ́ bí ẹní ń bá àwọn ẹni ti ara sọ̀rọ̀, bí ẹní ń bá àwọn ìkókó+ nínú Kristi sọ̀rọ̀. 2 Wàrà ni mo fi bọ́ yín, kì í ṣe oúnjẹ líle, torí nígbà yẹn, ẹ ò tíì lágbára tó. Kódà ní báyìí, ẹ ò tíì lágbára tó,+ 3 nítorí ẹ ṣì jẹ́ ẹni ti ara.+ Nígbà tí owú àti wàhálà wà láàárín yín, ṣé ẹ kì í ṣe ẹni ti ara ni,+ ṣé ẹ kì í sì í ṣe bí àwọn èèyàn ayé ni? 4 Torí nígbà tí ẹnì kan bá sọ pé, “Èmi jẹ́ ti Pọ́ọ̀lù,” tí òmíràn sì sọ pé, “Èmi jẹ́ ti Àpólò,”+ ṣé kì í ṣe ìwà àwọn èèyàn ayé lẹ̀ ń hù yẹn?

5 Kí wá ni Àpólò jẹ́? Kí sì ni Pọ́ọ̀lù jẹ́? Àwọn òjíṣẹ́+ tí ẹ tipasẹ̀ wọn di onígbàgbọ́, bí Olúwa ṣe fún kálukú láǹfààní. 6 Èmi gbìn,+ Àpólò bomi rin,+ àmọ́ Ọlọ́run ló mú kó máa dàgbà, 7 tó fi jẹ́ pé kì í ṣe ẹni tó ń gbìn ló ṣe pàtàkì tàbí ẹni tó ń bomi rin, bí kò ṣe Ọlọ́run tó ń mú kó dàgbà.+ 8 Ní báyìí, ọ̀kan náà ni ẹni tó ń gbìn àti ẹni tó ń bomi rin jẹ́,* àmọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan máa gba èrè iṣẹ́ tirẹ̀.+ 9 Nítorí alábàáṣiṣẹ́ pẹ̀lú Ọlọ́run ni wá. Ẹ̀yin jẹ́ pápá Ọlọ́run tí à ń ro lọ́wọ́, ilé Ọlọ́run.+

10 Nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run tí a fún mi, mo fi ìpìlẹ̀ lélẹ̀+ gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá kọ́lékọ́lé tó mọṣẹ́,* àmọ́ ẹlòmíì ń kọ́lé sórí rẹ̀. Kí kálukú máa ṣọ́ bó ṣe ń kọ́lé sórí rẹ̀. 11 Nítorí kò sí ẹni tó lè fi ìpìlẹ̀ èyíkéyìí míì lélẹ̀ ju ohun tí a ti fi lélẹ̀, ìyẹn Jésù Kristi.+ 12 Ní báyìí, tí ẹnikẹ́ni bá ń kọ́ wúrà, fàdákà, àwọn òkúta iyebíye, igi, koríko gbígbẹ tàbí pòròpórò sórí ìpìlẹ̀ náà, 13 ohun tí iṣẹ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan jẹ́ á hàn,* torí ọjọ́ náà yóò tú u síta, nítorí iná yóò fi í hàn,+ iná náà yóò sì fi ohun tí kálukú fi kọ́lé hàn. 14 Bí ohun tí ẹnì kan kọ́ sórí rẹ̀ bá dúró, ẹni náà yóò gba èrè; 15 bí iṣẹ́ ẹnì kan bá jóná, ẹni náà yóò pàdánù, àmọ́ a ó gba òun fúnra rẹ̀ là; síbẹ̀, tó bá rí bẹ́ẹ̀, á dà bí ìgbà téèyàn la iná kọjá.

16 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé ẹ̀yin fúnra yín ni tẹ́ńpìlì Ọlọ́run+ àti pé ẹ̀mí Ọlọ́run ń gbé inú yín?+ 17 Tí ẹnikẹ́ni bá pa tẹ́ńpìlì Ọlọ́run run, Ọlọ́run á pa ẹni náà run; nítorí tẹ́ńpìlì Ọlọ́run jẹ́ mímọ́, ẹ̀yin sì ni tẹ́ńpìlì yẹn.+

18 Kí ẹnì kankan má tan ara rẹ̀ jẹ: Tí ẹnikẹ́ni nínú yín bá rò pé òun gbọ́n nínú ètò àwọn nǹkan yìí,* kí ó di òmùgọ̀, kí ó lè gbọ́n. 19 Nítorí ọgbọ́n ayé yìí jẹ́ òmùgọ̀ lọ́dọ̀ Ọlọ́run, torí ó ti wà lákọsílẹ̀ pé: “Ó ń mú àwọn ọlọ́gbọ́n nínú ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ wọn.”+ 20 Àti pé: “Jèhófà* mọ̀ pé èrò àwọn ọlọ́gbọ́n jẹ́ ìmúlẹ̀mófo.”+ 21 Torí náà, kí ẹnì kankan má ṣe máa fi èèyàn yangàn; nítorí ohun gbogbo jẹ́ tiyín, 22 ì báà jẹ́ Pọ́ọ̀lù tàbí Àpólò tàbí Kéfà*+ tàbí ayé tàbí ìyè tàbí ikú tàbí àwọn ohun tó wà níbí nísinsìnyí tàbí àwọn ohun tó ń bọ̀, ohun gbogbo jẹ́ tiyín; 23 ẹ̀yin náà jẹ́ ti Kristi;+ Kristi ní tirẹ̀ jẹ́ ti Ọlọ́run.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́