ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 40
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • A tu àwọn èèyàn Ọlọ́run nínú (1-11)

        • Ohùn kan nínú aginjù (3-5)

      • Ọlọ́run tóbi (12-31)

        • Àwọn orílẹ̀-èdè dà bí ẹ̀kán omi kan látinú korobá (15)

        • Ọlọ́run ń gbé orí “òbìrìkìtì ayé” (22)

        • Ó ń fi orúkọ pe gbogbo ìràwọ̀ (26)

        • Kì í rẹ Ọlọ́run (28)

        • Ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Jèhófà ń mú kéèyàn jèrè okun pa dà (29-31)

Àìsáyà 40:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:13; 51:3; 2Kọ 1:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 398-399

Àìsáyà 40:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹ sọ ọ̀rọ̀ ìtùnú fún Jerúsálẹ́mù.”

  • *

    Tàbí “ìlọ́po méjì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 79:8, 9; Jer 31:34; 33:8
  • +Jer 16:18; Da 9:11, 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 398-399

Àìsáyà 40:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹ múra ọ̀nà Jèhófà sílẹ̀!”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 35:8; 57:14; Mal 3:1
  • +Ais 11:16
  • +Mt 3:1, 3; Mk 1:2-4; Lk 3:3-6; Jo 1:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?, ojú ìwé 19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 399-401

Àìsáyà 40:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 399-401

Àìsáyà 40:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Gbogbo èèyàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 24:15
  • +Ais 49:6; 52:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 399-401

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/15/1994, ojú ìwé 25

Àìsáyà 40:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gbogbo èèyàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 14:1, 2; Sm 90:5, 6

Àìsáyà 40:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹ̀mí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 1:11
  • +Sm 103:15, 16

Àìsáyà 40:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 46:10; 1Pe 1:24, 25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 5

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2017, ojú ìwé 18-22

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 401-402

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/1997, ojú ìwé 10-15

Àìsáyà 40:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 52:7
  • +Ais 12:2; 25:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 402-404, 406

Àìsáyà 40:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 53:1; Jo 12:37, 38
  • +Ais 62:11; Ifi 22:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2019, ojú ìwé 5-6

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2007, ojú ìwé 26-27

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 402-404, 406

Àìsáyà 40:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “darí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:10; Isk 34:15, 16; 1Pe 2:25
  • +Jẹ 33:13; 1Pe 5:2, 3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2019, ojú ìwé 7

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 20-21, 70

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2013, ojú ìwé 27

    4/1/2007, ojú ìwé 26-27

    7/1/2003, ojú ìwé 11

    1/1/1993, ojú ìwé 19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 402, 405-407

Àìsáyà 40:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Àlàfo tó wà láàárín orí àtàǹpàkò àti ìka tó kéré jù téèyàn bá yàka. Wo Àfikún B14.

  • *

    Tàbí “díwọ̀n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 30:4
  • +Job 38:4, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2022,

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 407-408

Àìsáyà 40:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “lóye.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 36:22, 23; Ro 11:34; 1Kọ 2:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 407-408

Àìsáyà 40:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 147:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 407-408

Àìsáyà 40:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 62:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 408-409

Àìsáyà 40:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kò lè mú igi ìdáná tó máa tó jáde.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 408-409

Àìsáyà 40:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 4:35
  • +Ais 41:11, 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 408-409

Àìsáyà 40:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 8:10; Sm 86:8; Jer 10:6, 7
  • +Di 4:15, 16; Iṣe 17:29

Àìsáyà 40:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ère dídà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 115:4-8

Àìsáyà 40:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 44:14, 15
  • +Ais 41:7; 46:6, 7; Jer 10:3, 4

Àìsáyà 40:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 19:1; Ro 1:20

Àìsáyà 40:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òbìrí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 66:1
  • +Ais 44:24; Jer 10:12; Sek 12:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2018 ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 25-26

    9/15/1993, ojú ìwé 32

    5/15/1992, ojú ìwé 5

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 409, 412

    Ìwé fún Gbogbo Ènìyàn, ojú ìwé 18-19

    Ìmọ̀, ojú ìwé 17

Àìsáyà 40:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn alákòóso.”

Àìsáyà 40:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 21:20, 21; 2Ọb 10:10, 11; Jer 22:24, 30

Àìsáyà 40:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 409-410

Àìsáyà 40:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 102:25
  • +Sm 147:4
  • +Sm 89:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2018, ojú ìwé 8

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 50-51

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 28

    2/15/2011, ojú ìwé 6-7

    5/1/2008, ojú ìwé 6

    2/1/2005, ojú ìwé 5

    6/15/1999, ojú ìwé 19-20

    4/1/1996, ojú ìwé 10-11

    3/1/1991, ojú ìwé 4

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 409-411

Àìsáyà 40:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:14; Isk 37:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2007, ojú ìwé 9

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 411-413, 415

Àìsáyà 40:28

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Òye rẹ̀ kò ṣeé lóye.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 21:33; Sm 90:2; Jer 10:10; 1Ti 1:17
  • +Sm 121:4; Ais 27:3
  • +Sm 139:4, 6; 147:5; Ais 55:9; Ro 11:33; 1Kọ 2:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2018, ojú ìwé 8

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2012, ojú ìwé 16

    6/15/1999, ojú ìwé 14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 411-413

Àìsáyà 40:29

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tí kò ní agbára (okun) láti ṣiṣẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 29:11; Ais 40:26; Flp 4:13; Heb 11:33, 34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2018, ojú ìwé 8-9

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    5/2007, ojú ìwé 1

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 413-415

Àìsáyà 40:30

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2018, ojú ìwé 9

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 413-415

Àìsáyà 40:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 103:5
  • +1Ọb 18:46; Sm 84:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àlàyé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì, àpilẹ̀kọ 21

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2018, ojú ìwé 9

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    1/2017, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 6 2016 ojú ìwé 9

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 413-415

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/15/1996, ojú ìwé 8, 10

    12/1/1995, ojú ìwé 14-19

Àwọn míì

Àìsá. 40:1Ais 49:13; 51:3; 2Kọ 1:3, 4
Àìsá. 40:2Sm 79:8, 9; Jer 31:34; 33:8
Àìsá. 40:2Jer 16:18; Da 9:11, 12
Àìsá. 40:3Ais 35:8; 57:14; Mal 3:1
Àìsá. 40:3Ais 11:16
Àìsá. 40:3Mt 3:1, 3; Mk 1:2-4; Lk 3:3-6; Jo 1:23
Àìsá. 40:4Ais 42:16
Àìsá. 40:5Ais 24:15
Àìsá. 40:5Ais 49:6; 52:10
Àìsá. 40:6Job 14:1, 2; Sm 90:5, 6
Àìsá. 40:7Jem 1:11
Àìsá. 40:7Sm 103:15, 16
Àìsá. 40:8Ais 46:10; 1Pe 1:24, 25
Àìsá. 40:9Ais 52:7
Àìsá. 40:9Ais 12:2; 25:9
Àìsá. 40:10Ais 53:1; Jo 12:37, 38
Àìsá. 40:10Ais 62:11; Ifi 22:12
Àìsá. 40:11Ais 49:10; Isk 34:15, 16; 1Pe 2:25
Àìsá. 40:11Jẹ 33:13; 1Pe 5:2, 3
Àìsá. 40:12Owe 30:4
Àìsá. 40:12Job 38:4, 5
Àìsá. 40:13Job 36:22, 23; Ro 11:34; 1Kọ 2:16
Àìsá. 40:14Sm 147:5
Àìsá. 40:15Sm 62:9
Àìsá. 40:17Da 4:35
Àìsá. 40:17Ais 41:11, 12
Àìsá. 40:18Ẹk 8:10; Sm 86:8; Jer 10:6, 7
Àìsá. 40:18Di 4:15, 16; Iṣe 17:29
Àìsá. 40:19Sm 115:4-8
Àìsá. 40:20Ais 44:14, 15
Àìsá. 40:20Ais 41:7; 46:6, 7; Jer 10:3, 4
Àìsá. 40:21Sm 19:1; Ro 1:20
Àìsá. 40:22Ais 66:1
Àìsá. 40:22Ais 44:24; Jer 10:12; Sek 12:1
Àìsá. 40:241Ọb 21:20, 21; 2Ọb 10:10, 11; Jer 22:24, 30
Àìsá. 40:26Sm 102:25
Àìsá. 40:26Sm 147:4
Àìsá. 40:26Sm 89:13
Àìsá. 40:27Ais 49:14; Isk 37:11
Àìsá. 40:28Jẹ 21:33; Sm 90:2; Jer 10:10; 1Ti 1:17
Àìsá. 40:28Sm 121:4; Ais 27:3
Àìsá. 40:28Sm 139:4, 6; 147:5; Ais 55:9; Ro 11:33; 1Kọ 2:16
Àìsá. 40:29Sm 29:11; Ais 40:26; Flp 4:13; Heb 11:33, 34
Àìsá. 40:31Sm 103:5
Àìsá. 40:311Ọb 18:46; Sm 84:7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 40:1-31

Àìsáyà

40 “Ẹ tu àwọn èèyàn mi nínú, ẹ tù wọ́n nínú,” ni Ọlọ́run yín wí.+

 2 “Ẹ sọ ọ̀rọ̀ tó máa wọ Jerúsálẹ́mù lọ́kàn,*

Kí ẹ sì kéde fún un pé iṣẹ́ rẹ̀ tó pọn dandan ti parí,

Pé a ti san gbèsè ẹ̀bi tó jẹ.+

Ó ti gba ohun tó kún rẹ́rẹ́* lọ́wọ́ Jèhófà fún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.”+

 3 Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé:

“Ẹ tún ọ̀nà Jèhófà ṣe!*+

Ẹ la ọ̀nà tó tọ́  + gba inú aṣálẹ̀ fún Ọlọ́run wa.+

 4 Kí ẹ mú kí gbogbo àfonífojì ga sókè,

Kí ẹ sì mú kí gbogbo òkè ńlá àti òkè kéékèèké wálẹ̀.

Kí ilẹ̀ tó rí gbágungbàgun di ilẹ̀ tó tẹ́jú,

Kí ilẹ̀ kángunkàngun sì di pẹ̀tẹ́lẹ̀.+

 5 A máa ṣí ògo Jèhófà payá,+

Gbogbo ẹran ara* sì jọ máa rí i,+

Torí Jèhófà ti fi ẹnu ara rẹ̀ sọ ọ́.”

 6 Fetí sílẹ̀! Ẹnì kan ń sọ pé: “Ké jáde!”

Ẹlòmíì béèrè pé: “Igbe kí ni kí n ké?”

“Koríko tútù ni gbogbo ẹran ara.*

Gbogbo ìfẹ́ wọn tí kì í yẹ̀ dà bí ìtànná àwọn ewéko.+

 7 Koríko tútù máa ń gbẹ dà nù,

Ìtànná máa ń rọ,+

Torí pé èémí* Jèhófà fẹ́ lù ú.+

Ó dájú pé koríko tútù ni àwọn èèyàn náà.

 8 Koríko tútù máa ń gbẹ dà nù,

Ìtànná máa ń rọ,

Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wa máa wà títí láé.”+

 9 Lọ sórí òkè tó ga,

Ìwọ obìnrin tó ń mú ìròyìn ayọ̀ wá fún Síónì.+

Gbé ohùn rẹ sókè tagbáratagbára,

Ìwọ obìnrin tó ń mú ìròyìn ayọ̀ wá fún Jerúsálẹ́mù.

Gbé e sókè, má bẹ̀rù.

Kéde fún àwọn ìlú Júdà pé: “Ọlọ́run yín rèé.”+

10 Wò ó! Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ máa wá tagbáratagbára,

Apá rẹ̀ sì máa bá a ṣàkóso.+

Wò ó! Èrè rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,

Ẹ̀san rẹ̀ sì wà níwájú rẹ̀.+

11 Ó máa bójú tó* agbo ẹran rẹ̀ bíi ti olùṣọ́ àgùntàn.+

Ó máa fi apá rẹ̀ kó àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn jọ,

Ó sì máa gbé wọn sí àyà rẹ̀.

Ó máa rọra da àwọn tó ń fọ́mọ lọ́mú.+

12 Ta ló ti fi àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀ wọn omi,+

Tó sì ti fi ìbú àtẹ́lẹwọ́* rẹ̀ wọn* ọ̀run?

Ta ló ti kó gbogbo erùpẹ̀ ilẹ̀ sínú òṣùwọ̀n,+

Tàbí tó ti wọn àwọn òkè ńlá lórí ìwọ̀n,

Tó sì ti wọn àwọn òkè kéékèèké lórí òṣùwọ̀n?

13 Ta ló ti díwọ̀n* ẹ̀mí Jèhófà,

Ta ló sì lè dá a lẹ́kọ̀ọ́ gẹ́gẹ́ bí agbani-nímọ̀ràn rẹ̀?+

14 Ta ló ti bá fikùn lukùn kó lè ní òye,

Tàbí ta ló kọ́ ọ ní ọ̀nà ìdájọ́ òdodo,

Tó kọ́ ọ ní ìmọ̀,

Tàbí tó fi ọ̀nà òye tòótọ́ hàn án?+

15 Wò ó! Àwọn orílẹ̀-èdè dà bí ẹ̀kán omi kan látinú korobá,

A sì kà wọ́n sí eruku fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ lórí òṣùwọ̀n.+

Wò ó! Ó ń gbé àwọn erékùṣù sókè bí eruku lẹ́búlẹ́bú.

16 Lẹ́bánónì pàápàá kò tó láti mú kí iná máa jó,*

Àwọn ẹran igbó rẹ̀ kò sì tó fún ẹbọ sísun.

17 Gbogbo orílẹ̀-èdè dà bí ohun tí kò sí ní iwájú rẹ̀;+

Ó kà wọ́n sí ohun tí kò já mọ́ nǹkan kan, bí ohun tí kò sí rárá.+

18 Ta ni ẹ lè fi Ọlọ́run wé?+

Kí lẹ lè fi sẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ tó máa jọ ọ́?+

19 Oníṣẹ́ ọnà ṣe ère,*

Oníṣẹ́ irin fi wúrà bò ó,+

Ó sì fi fàdákà rọ ẹ̀wọ̀n.

20 Ó mú igi láti fi ṣe ọrẹ,+

Igi tí kò ní jẹrà.

Ó wá oníṣẹ́ ọnà tó já fáfá,

Láti ṣe ère gbígbẹ́ tí kò ní ṣubú.+

21 Ṣé ẹ kò mọ̀ ni?

Ṣé ẹ kò tíì gbọ́ ni?

Ṣé wọn ò sọ fún yín láti ìbẹ̀rẹ̀ ni?

Ṣé kò yé yín látìgbà tí a ti dá ayé?+

22 Ẹnì kan wà tó ń gbé orí òbìrìkìtì* ayé,+

Àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ sì dà bíi tata,

Ó ń na ọ̀run bí aṣọ fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tó ní ihò wínníwínní,

Ó sì tẹ́ ẹ bí àgọ́ láti máa gbé.+

23 Ó ń sọ àwọn aláṣẹ di ẹni tí kò já mọ́ nǹkan kan,

Ó sì ń sọ àwọn adájọ́* ayé di ohun tí kò sí rárá.

24 Bóyá la gbìn wọ́n rí,

Bóyá la fúnrúgbìn wọn rí,

Bóyá ni kùkùté wọn ta gbòǹgbò rí nínú ilẹ̀,

A fẹ́ atẹ́gùn lù wọ́n, wọ́n sì gbẹ dà nù,

Afẹ́fẹ́ gbé wọn lọ bí àgékù pòròpórò.+

25 “Ta lẹ lè fi mí wé bóyá mo bá a dọ́gba?” ni Ẹni Mímọ́ wí.

26 “Ẹ gbé ojú yín sókè ọ̀run, kí ẹ sì wò ó.

Ta ló dá àwọn nǹkan yìí?+

Òun ni Ẹni tó ń mú wọn jáde bí ẹgbẹ́ ọmọ ogun ní iye-iye;

Ó ń fi orúkọ pe gbogbo wọn.+

Torí okun rẹ̀ tó fi ń ṣiṣẹ́ pọ̀ yanturu, agbára rẹ̀ sì ń bani lẹ́rù,+

Ìkankan nínú wọn ò di àwátì.

27 Ìwọ Jékọ́bù, kí ló dé tí o fi sọ báyìí, àti ìwọ Ísírẹ́lì, kí ló dé tí o fi kéde pé,

‘Jèhófà ò rí ọ̀nà mi,

Mi ò sì rí ìdájọ́ òdodo gbà lọ́dọ̀ Ọlọ́run’?+

28 Ṣé o ò mọ̀ ni? Ṣé o ò tíì gbọ́ ni?

Jèhófà, Ẹlẹ́dàá àwọn ìkángun ayé, jẹ́ Ọlọ́run títí ayé.+

Kì í rẹ̀ ẹ́, okun rẹ̀ kì í sì í tán.+

Àwámáridìí ni òye rẹ̀.*+

29 Ó ń fún ẹni tó ti rẹ̀ ní agbára,

Ó sì ń fún àwọn tí kò lókun* ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ okun.+

30 Ó máa rẹ àwọn ọmọdékùnrin, okun wọn sì máa tán,

Àwọn ọ̀dọ́kùnrin máa kọsẹ̀, wọ́n á sì ṣubú,

31 Àmọ́ àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà máa jèrè okun pa dà.

Wọ́n máa fi ìyẹ́ fò lọ sókè réré bí ẹyẹ idì.+

Wọ́n máa sáré, okun ò ní tán nínú wọn;

Wọ́n máa rìn, kò sì ní rẹ̀ wọ́n.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́