ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 52
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Jí, ìwọ Síónì! (1-12)

        • Ẹsẹ̀ àwọn tó ń mú ìhìn rere wá rẹwà (7)

        • Àwọn olùṣọ́ Síónì kígbe níṣọ̀kan (8)

        • Àwọn tó ń gbé àwọn ohun èlò Jèhófà gbọ́dọ̀ mọ́ (11)

      • A máa gbé ìránṣẹ́ Jèhófà ga (13-15)

        • Wọ́n ba ìrísí rẹ̀ jẹ́ (14)

Àìsáyà 52:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kọlà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Hag 2:4
  • +Ais 51:17
  • +Ais 61:3
  • +Ais 35:8; 60:21; Ifi 21:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 180-182

Àìsáyà 52:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 51:14; 61:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 180-182

Àìsáyà 52:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 50:1
  • +Ais 45:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 182

Àìsáyà 52:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 46:5-7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 182-183

Àìsáyà 52:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 137:3; Jer 50:17
  • +Sm 74:10; Ro 2:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 183-184

Àìsáyà 52:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 20:44

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 183-185

Àìsáyà 52:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:9; Na 1:15; Iṣe 8:4; Ro 10:15; Ef 6:14, 15
  • +Lk 2:14; Iṣe 10:36; Ef 2:17
  • +Sm 93:1; Ais 33:22; Mik 4:7; Mt 24:14; Ifi 11:15, 17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 126-127

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2005, ojú ìwé 18-19

    12/15/1997, ojú ìwé 21

    5/1/1997, ojú ìwé 11-12

    4/15/1997, ojú ìwé 27

    1/15/1997, ojú ìwé 10-11, 13

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 185-188

Àìsáyà 52:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “lójúkojú.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 188-190

Àìsáyà 52:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 61:4
  • +Ais 66:13
  • +Ais 44:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 190-191

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/1997, ojú ìwé 12

Àìsáyà 52:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣẹ́gun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 51:9
  • +Sm 22:27; Ais 49:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 190-191

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/1997, ojú ìwé 12

Àìsáyà 52:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 48:20; Jer 50:8; 51:6; Sek 2:6
  • +Le 5:2; Isk 44:23
  • +2Kọ 6:17; Ifi 18:4
  • +Le 10:3; Nọ 3:6, 8; Ẹsr 1:7; 8:30

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 89

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 265-266

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 191-193

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    12/1/1991, ojú ìwé 12-13

Àìsáyà 52:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 13:21; 1Kr 14:15
  • +Ais 58:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 191, 193

Àìsáyà 52:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:1; 61:1; Flp 2:5-7
  • +Sm 2:6; 110:1; Ais 9:6; Mt 28:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 24-25

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 195-197

Àìsáyà 52:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 197-198

Àìsáyà 52:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kò ní lè sọ̀rọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 2:2
  • +Sm 2:10; 72:11
  • +Ro 15:20, 21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 197-198

    Jí!,

    12/8/1998, ojú ìwé 11

Àwọn míì

Àìsá. 52:1Hag 2:4
Àìsá. 52:1Ais 51:17
Àìsá. 52:1Ais 61:3
Àìsá. 52:1Ais 35:8; 60:21; Ifi 21:27
Àìsá. 52:2Ais 51:14; 61:1
Àìsá. 52:3Ais 50:1
Àìsá. 52:3Ais 45:13
Àìsá. 52:4Jẹ 46:5-7
Àìsá. 52:5Sm 137:3; Jer 50:17
Àìsá. 52:5Sm 74:10; Ro 2:24
Àìsá. 52:6Isk 20:44
Àìsá. 52:7Ais 40:9; Na 1:15; Iṣe 8:4; Ro 10:15; Ef 6:14, 15
Àìsá. 52:7Lk 2:14; Iṣe 10:36; Ef 2:17
Àìsá. 52:7Sm 93:1; Ais 33:22; Mik 4:7; Mt 24:14; Ifi 11:15, 17
Àìsá. 52:9Ais 61:4
Àìsá. 52:9Ais 66:13
Àìsá. 52:9Ais 44:23
Àìsá. 52:10Ais 51:9
Àìsá. 52:10Sm 22:27; Ais 49:6
Àìsá. 52:11Ais 48:20; Jer 50:8; 51:6; Sek 2:6
Àìsá. 52:11Le 5:2; Isk 44:23
Àìsá. 52:112Kọ 6:17; Ifi 18:4
Àìsá. 52:11Le 10:3; Nọ 3:6, 8; Ẹsr 1:7; 8:30
Àìsá. 52:12Ẹk 13:21; 1Kr 14:15
Àìsá. 52:12Ais 58:8
Àìsá. 52:13Ais 42:1; 61:1; Flp 2:5-7
Àìsá. 52:13Sm 2:6; 110:1; Ais 9:6; Mt 28:18
Àìsá. 52:15Sm 2:2
Àìsá. 52:15Sm 2:10; 72:11
Àìsá. 52:15Ro 15:20, 21
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 52:1-15

Àìsáyà

52 Jí! Jí! Gbé agbára wọ̀,+ ìwọ Síónì!+

Wọ aṣọ rẹ tó rẹwà,+ ìwọ Jerúsálẹ́mù, ìlú mímọ́!

Torí ẹni tí kò dádọ̀dọ́* àti aláìmọ́ kò ní wọ inú rẹ mọ́.+

 2 Gbọn eruku kúrò, gbéra kí o sì jókòó, ìwọ Jerúsálẹ́mù.

Tú ìdè ọrùn rẹ, ìwọ ọmọbìnrin Síónì tí wọ́n mú lẹ́rú.+

 3 Torí ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

“Ọ̀fẹ́ ni wọ́n tà yín,+

A sì máa tún yín rà láìsan owó.”+

 4 Torí ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí:

“Àwọn èèyàn mi kọ́kọ́ lọ sí Íjíbítì, wọ́n sì gbé níbẹ̀ bí àjèjì;+

Ásíríà wá fìyà jẹ wọ́n láìnídìí.”

 5 “Kí wá ni kí n ṣe níbí?” ni Jèhófà wí.

“Ọ̀fẹ́ ni wọ́n kó àwọn èèyàn mi lọ.

Àwọn tó ń jọba lé wọn lórí ń kígbe pé àwọn ti ṣẹ́gun,”+ ni Jèhófà wí,

“Nígbà gbogbo, láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọn ò bọ̀wọ̀ fún orúkọ mi.+

 6 Ìyẹn máa mú kí àwọn èèyàn mi mọ orúkọ mi;+

Ìyẹn máa mú kí wọ́n mọ̀ ní ọjọ́ yẹn pé èmi ni Ẹni tó ń sọ̀rọ̀.

Wò ó, èmi ni!”

 7 Wo bí ẹsẹ̀ ẹni tó ń mú ìhìn rere wá ṣe rẹwà tó lórí àwọn òkè,+

Ẹni tó ń kéde àlàáfíà,+

Ẹni tó ń mú ìhìn rere wá nípa ohun tó sàn,

Ẹni tó ń kéde ìgbàlà,

Ẹni tó ń sọ fún Síónì pé: “Ọlọ́run rẹ ti di Ọba!”+

 8 Fetí sílẹ̀! Àwọn olùṣọ́ rẹ gbé ohùn wọn sókè.

Wọ́n kígbe ayọ̀ níṣọ̀kan,

Torí wọ́n máa rí i kedere* tí Jèhófà bá pa dà kó Síónì jọ.

 9 Ẹ tújú ká, ẹ kígbe ayọ̀ níṣọ̀kan, ẹ̀yin àwókù Jerúsálẹ́mù,+

Torí Jèhófà ti tu àwọn èèyàn rẹ̀ nínú;+ ó ti tún Jerúsálẹ́mù rà.+

10 Jèhófà ti jẹ́ kí wọ́n rí apá rẹ̀ mímọ́ lójú gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè;+

Gbogbo ìkángun ayé sì máa rí bí Ọlọ́run wa ṣe ń gbani là.*+

11 Ẹ yíjú pa dà, ẹ yíjú pa dà, ẹ jáde kúrò níbẹ̀,+ ẹ má fọwọ́ kan ohun àìmọ́ kankan!+

Ẹ jáde kúrò ní àárín rẹ̀,+ ẹ wà ní mímọ́,

Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé àwọn ohun èlò Jèhófà.+

12 Ẹ ò ní fi ìbẹ̀rù lọ,

Ẹ ò sì ní sá lọ,

Torí Jèhófà máa ṣáájú yín,+

Ọlọ́run Ísírẹ́lì á sì máa ṣọ́ yín láti ẹ̀yìn.+

13 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi+ máa fi ìjìnlẹ̀ òye hùwà.

A máa gbé e ga,

A máa gbé e lékè, a sì máa gbé e ga gidigidi.+

14 Bó ṣe jẹ́ pé ọ̀pọ̀ ló ń wò ó tìyanutìyanu,

Tí wọ́n ba ìrísí rẹ̀ jẹ́ ju ti èèyàn èyíkéyìí míì,

Tí wọ́n sì ba ìrísí rẹ̀ tó buyì kún un jẹ́ ju ti ọmọ aráyé,

15 Bẹ́ẹ̀ ni òun náà máa dẹ́rù ba ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè.+

Àwọn ọba máa pa ẹnu wọn mọ́* níwájú rẹ̀,+

Torí wọ́n máa rí ohun tí wọn ò tíì sọ fún wọn,

Wọ́n sì máa ronú nípa ohun tí wọn ò tíì gbọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́