Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 8, 2004
Ìṣòro Àìkìísùntó—Ǹjẹ́ Ó Ń Yọ Ọ́ Lẹ́nu?
Ǹjẹ́ o máa ń sun oorun tó pọ̀ tó? Báwo lo ṣe lè mọ àwọn ìṣòro líle koko tí kì í jẹ́ kéèyàn rí oorun sùn àti ohun tó o lè ṣe sí irú àwọn ìṣòro bẹ́ẹ̀?
3 Àìkìísùntó—Ṣé Ìṣòro Yìí Ń Burú Sí I Ni?
10 Mímọ Àwọn Ìṣòro Líle Koko Tí Kì Í Jẹ́ Kéèyàn Rí Oorun Sùn
13 Ilẹ̀ Ayé Wa—Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Sí i Lọ́jọ́ Iwájú?
16 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
19 Bí Àwọn Kan Ṣe Gbìyànjú Láti Tẹ Orúkọ Ọlọ́run Rì
24 Bí O Ṣe Lè Mọ Orúkọ Ọlọ́run
31 Orúkọ Ọlọ́run Lára Àwọn Ilé Àtayébáyé
32 Báwo Ni Ohun Tí Ọmọ Rẹ Lè Mọ̀ Ṣe Pọ̀ Tó?
Ṣé Irú Ẹ̀jẹ̀ Rẹ Ló Ń Sọ Irú Ẹni Tó O Jẹ́? 14
Ní àwọn ilẹ̀ kan, ó wọ́pọ̀ káwọn èèyàn máa fi irú ẹ̀jẹ̀ tí ẹnì kan ní pinnu irú ẹni tó jẹ́. Ojú wo ló yẹ kí àwọn Kristẹni fi wo ọ̀ràn yìí?
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ráyè Ṣe Iṣẹ́ Àṣetiléwá Mi? 27
Ṣé ara sábà máa ń ni ọ́ gan-an nítorí iṣẹ́ àṣetiléwá tó pàpọ̀jù?