ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 19
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Léfítíkù

      • Onírúurú òfin nípa ìjẹ́mímọ́ (1-37)

        • Kíkórè bó ṣe tọ́ (9, 10)

        • Híhu ìwà tó yẹ sí adití àti afọ́jú (14)

        • Bíbani lórúkọ jẹ́ (16)

        • Má ṣe di ẹnikẹ́ni sínú (18)

        • Ẹ ò gbọ́dọ̀ pidán, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ bá ẹ̀mí lò (26, 31)

        • Ẹ ò gbọ́dọ̀ fín àmì sára yín (28)

        • Máa bọ̀wọ̀ fún àgbàlagbà (32)

        • Bó ṣe yẹ kí ẹ ṣe sí àjèjì (33, 34)

Léfítíkù 19:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 11:44; Ais 6:3; 1Pe 1:15, 16; Ifi 4:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 3-4

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2009, ojú ìwé 9

    8/1/1996, ojú ìwé 10-11

    Yiyan, ojú ìwé 24-25

Léfítíkù 19:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “bẹ̀rù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:12; Ef 6:2; Heb 12:9
  • +Ẹk 20:8, 11; 31:13; Lk 6:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 4-5, 8

Léfítíkù 19:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:1; Sm 96:5; Hab 2:18; 1Kọ 10:14
  • +Ẹk 20:4, 23; Di 27:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 5-6

Léfítíkù 19:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 3:1
  • +Le 7:11, 12

Léfítíkù 19:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 7:17, 18

Léfítíkù 19:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 11/2020, ojú ìwé 2

Léfítíkù 19:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 11/2020, ojú ìwé 2

Léfítíkù 19:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kó ohun tó bá ṣẹ́ kù lára.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 23:22; Di 24:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2006, ojú ìwé 22-23

    12/1/2003, ojú ìwé 17

Léfítíkù 19:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn tí ìyà ń jẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 15:7

Léfítíkù 19:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:15; Ef 4:28
  • +Le 6:2; Owe 12:22; Ef 4:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 10

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2016, ojú ìwé 11-12

Léfítíkù 19:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:7; Mt 5:33, 37; Jem 5:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 10

Léfítíkù 19:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 22:16; Mk 10:19
  • +Owe 22:22
  • +Di 24:15; Jer 22:13; Jem 5:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 10

Léfítíkù 19:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “pe ibi wá sórí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 27:18
  • +Le 25:17; Ne 5:15; Owe 1:7; 8:13; 1Pe 2:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 9

Léfítíkù 19:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:3; Di 1:16, 17; 16:19; 2Kr 19:6; Ro 2:11; Jem 2:9

Léfítíkù 19:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹ̀jẹ̀.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “O ò gbọ́dọ̀ máa wò tí ẹ̀mí ọmọnìkejì rẹ bá wà nínú ewu.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 15:1, 3
  • +Ẹk 20:16; 1Ọb 21:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 14

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2021,

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/15/1992, ojú ìwé 20

Léfítíkù 19:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 10:18; 1Jo 2:9; 3:15
  • +Sm 141:5; Owe 9:8; Mt 18:15

Léfítíkù 19:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 20:22; Ro 12:19
  • +Mt 5:43, 44; 22:39; Ro 13:9; Ga 5:14; Jem 2:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 10-12

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2011, ojú ìwé 22

    12/1/2006, ojú ìwé 26-27

Léfítíkù 19:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 22:9
  • +Di 22:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 6

Léfítíkù 19:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 6:6, 7

Léfítíkù 19:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “tó jẹ́ aláìkọlà.”

  • *

    Ní Héb., “aláìkọlà.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 6-7

Léfítíkù 19:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 26:1, 2; Owe 3:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 6-7

Léfítíkù 19:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 6-7

Léfítíkù 19:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 3:17; 17:13; Di 12:23; Iṣe 15:20, 29
  • +Ẹk 8:7; Di 18:10-12; Ga 5:19, 20; Ifi 21:8

Léfítíkù 19:27

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 21:1, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2004, ojú ìwé 24

    Jí!,

    2/8/2000, ojú ìwé 12-14

Léfítíkù 19:28

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “torí ọkàn kan.” Ní ẹsẹ yìí, ọ̀rọ̀ Hébérù náà neʹphesh ń tọ́ka sí ẹni tó ti kú.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 14:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2021,

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2003, ojú ìwé 27

    Jí!,

    8/8/2000, ojú ìwé 22-23

Léfítíkù 19:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 23:17
  • +Heb 13:4; 1Pe 4:3

Léfítíkù 19:30

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “bẹ̀rù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:10; 31:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2021,

Léfítíkù 19:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:6; Di 18:10-12; 1Kr 10:13; Ais 8:19
  • +Le 20:27; Iṣe 16:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 24

Léfítíkù 19:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 16:31; 20:29
  • +Job 32:6; Owe 23:22; 1Ti 5:1
  • +Job 28:28; Owe 1:7; 8:13; 1Pe 2:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2008, ojú ìwé 21

    6/15/2000, ojú ìwé 21

    8/1/1999, ojú ìwé 20

    8/1/1994, ojú ìwé 27

    3/15/1993, ojú ìwé 27

    Jí!,

    10/8/2004, ojú ìwé 22-23

    4/8/1999, ojú ìwé 31

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 149

Léfítíkù 19:33

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:9

Léfítíkù 19:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 12:49
  • +Ẹk 22:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 12

Léfítíkù 19:35

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 25:13, 15; Owe 20:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 10

Léfítíkù 19:36

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “òṣùwọ̀n eéfà tó péye.” Wo Àfikún B14.

  • *

    Ní Héb., “òṣùwọ̀n hínì tó péye.” Wo Àfikún B14.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 11:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 10

Léfítíkù 19:37

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 18:5; Di 4:6

Àwọn míì

Léf. 19:2Le 11:44; Ais 6:3; 1Pe 1:15, 16; Ifi 4:8
Léf. 19:3Ẹk 20:12; Ef 6:2; Heb 12:9
Léf. 19:3Ẹk 20:8, 11; 31:13; Lk 6:5
Léf. 19:4Le 26:1; Sm 96:5; Hab 2:18; 1Kọ 10:14
Léf. 19:4Ẹk 20:4, 23; Di 27:15
Léf. 19:5Le 3:1
Léf. 19:5Le 7:11, 12
Léf. 19:6Le 7:17, 18
Léf. 19:9Le 23:22; Di 24:19
Léf. 19:10Di 15:7
Léf. 19:11Ẹk 20:15; Ef 4:28
Léf. 19:11Le 6:2; Owe 12:22; Ef 4:25
Léf. 19:12Ẹk 20:7; Mt 5:33, 37; Jem 5:12
Léf. 19:13Owe 22:16; Mk 10:19
Léf. 19:13Owe 22:22
Léf. 19:13Di 24:15; Jer 22:13; Jem 5:4
Léf. 19:14Di 27:18
Léf. 19:14Le 25:17; Ne 5:15; Owe 1:7; 8:13; 1Pe 2:17
Léf. 19:15Ẹk 23:3; Di 1:16, 17; 16:19; 2Kr 19:6; Ro 2:11; Jem 2:9
Léf. 19:16Sm 15:1, 3
Léf. 19:16Ẹk 20:16; 1Ọb 21:13
Léf. 19:17Owe 10:18; 1Jo 2:9; 3:15
Léf. 19:17Sm 141:5; Owe 9:8; Mt 18:15
Léf. 19:18Owe 20:22; Ro 12:19
Léf. 19:18Mt 5:43, 44; 22:39; Ro 13:9; Ga 5:14; Jem 2:8
Léf. 19:19Di 22:9
Léf. 19:19Di 22:11
Léf. 19:21Le 6:6, 7
Léf. 19:24Di 26:1, 2; Owe 3:9
Léf. 19:26Le 3:17; 17:13; Di 12:23; Iṣe 15:20, 29
Léf. 19:26Ẹk 8:7; Di 18:10-12; Ga 5:19, 20; Ifi 21:8
Léf. 19:27Le 21:1, 5
Léf. 19:28Di 14:1
Léf. 19:29Di 23:17
Léf. 19:29Heb 13:4; 1Pe 4:3
Léf. 19:30Ẹk 20:10; 31:13
Léf. 19:31Le 20:6; Di 18:10-12; 1Kr 10:13; Ais 8:19
Léf. 19:31Le 20:27; Iṣe 16:16
Léf. 19:32Owe 16:31; 20:29
Léf. 19:32Job 32:6; Owe 23:22; 1Ti 5:1
Léf. 19:32Job 28:28; Owe 1:7; 8:13; 1Pe 2:17
Léf. 19:33Ẹk 23:9
Léf. 19:34Ẹk 12:49
Léf. 19:34Ẹk 22:21
Léf. 19:35Di 25:13, 15; Owe 20:10
Léf. 19:36Owe 11:1
Léf. 19:37Le 18:5; Di 4:6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Léfítíkù 19:1-37

Léfítíkù

19 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: 2 “Sọ fún gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Kí ẹ jẹ́ mímọ́, torí èmi Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ mímọ́.+

3 “‘Kí kálukú yín máa bọ̀wọ̀ fún* ìyá rẹ̀ àti bàbá rẹ̀,+ kí ẹ sì máa pa àwọn sábáàtì+ mi mọ́. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín. 4 Ẹ má ṣe yíjú sí àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí+ tàbí kí ẹ fi irin rọ àwọn ọlọ́run+ fún ara yín. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.

5 “‘Tí ẹ bá rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀ sí Jèhófà,+ kí ẹ rú ẹbọ náà lọ́nà tí ẹ ó fi rí ìtẹ́wọ́gbà.+ 6 Kí ẹ jẹ ẹ́ ní ọjọ́ tí ẹ bá rúbọ àti ní ọjọ́ kejì, àmọ́ kí ẹ fi iná sun+ èyí tó bá ṣẹ́ kù di ọjọ́ kẹta. 7 Tí ẹ bá jẹ èyíkéyìí nínú rẹ̀ ní ọjọ́ kẹta, ohun tí kò tọ́ lẹ ṣe, kò sì ní rí ìtẹ́wọ́gbà. 8 Ẹni tó bá jẹ ẹ́ yóò jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, torí ó ti sọ ohun mímọ́ Jèhófà di aláìmọ́, ṣe ni kí ẹ pa ẹni* náà, kí ẹ lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.

9 “‘Tí ẹ bá ń kórè oko yín, ẹ ò gbọ́dọ̀ kárúgbìn eteetí oko yín tán, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ pèéṣẹ́* irè oko yín.+ 10 Bákan náà, ẹ ò gbọ́dọ̀ kó àwọn ohun tó ṣẹ́ kù sílẹ̀ nínú ọgbà àjàrà yín tàbí kí ẹ ṣa àwọn èso àjàrà tó fọ́n ká sínú ọgbà àjàrà yín. Ẹ fi í sílẹ̀ fún àwọn aláìní*+ àti àjèjì. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.

11 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ jalè,+ ẹ ò gbọ́dọ̀ tanni jẹ,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ hùwà àìṣòótọ́ sí ara yín. 12 Ẹ ò gbọ́dọ̀ fi orúkọ mi búra èké,+ kí ẹ má bàa sọ orúkọ Ọlọ́run yín di aláìmọ́. Èmi ni Jèhófà. 13 Ẹ ò gbọ́dọ̀ lu ọmọnìkejì yín ní jìbìtì,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ jalè.+ Owó iṣẹ́ alágbàṣe ò gbọ́dọ̀ wà lọ́wọ́ yín di àárọ̀ ọjọ́ kejì.+

14 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣépè fún* adití tàbí kí ẹ fi ohun ìdènà síwájú afọ́jú,+ ẹ sì gbọ́dọ̀ máa bẹ̀rù Ọlọ́run yín.+ Èmi ni Jèhófà.

15 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ yí ìdájọ́ po. Ẹ ò gbọ́dọ̀ rẹ́ aláìní jẹ tàbí kí ẹ ṣe ojúsàájú sí ọlọ́rọ̀.+ Máa ṣe ìdájọ́ òdodo tí o bá ń dá ẹjọ́ ẹnì kejì rẹ.

16 “‘O ò gbọ́dọ̀ máa bani lórúkọ jẹ́ káàkiri láàárín àwọn èèyàn rẹ.+ O ò gbọ́dọ̀ dìde lòdì sí ẹ̀mí* ẹnì kejì rẹ.*+ Èmi ni Jèhófà.

17 “‘O ò gbọ́dọ̀ kórìíra arákùnrin rẹ nínú ọkàn rẹ.+ Kí o rí i pé o bá ẹnì kejì rẹ wí,+ kí o má bàa jẹ nínú ìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.

18 “‘O ò gbọ́dọ̀ gbẹ̀san+ tàbí kí o di ọmọ àwọn èèyàn rẹ sínú, o sì gbọ́dọ̀ nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.+ Èmi ni Jèhófà.

19 “‘Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi mọ́: Ẹ ò gbọ́dọ̀ mú kí oríṣi ẹran ọ̀sìn yín méjì bá ara wọn lò pọ̀. Ẹ ò gbọ́dọ̀ gbin oríṣi irúgbìn méjì sínú oko yín,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ wọ aṣọ tó ní oríṣi òwú méjì tí wọ́n hun pọ̀.+

20 “‘Tí ọkùnrin kan bá dùbúlẹ̀ ti obìnrin kan, tó sì bá a lò pọ̀, tó sì jẹ́ pé ìránṣẹ́ ọkùnrin míì ni obìnrin náà, àmọ́ tí wọn ò tíì rà á pa dà tàbí dá a sílẹ̀, ẹ gbọ́dọ̀ fìyà jẹ wọ́n. Àmọ́, ẹ má pa wọ́n, torí wọn ò tíì dá obìnrin náà sílẹ̀. 21 Kí ọkùnrin náà mú ẹbọ ẹ̀bi rẹ̀ wá fún Jèhófà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, àgbò kan fún ẹbọ ẹ̀bi.+ 22 Kí àlùfáà fi àgbò ẹbọ ẹ̀bi náà ṣe ètùtù fún un níwájú Jèhófà torí ẹ̀ṣẹ̀ tó dá, yóò sì rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ gbà.

23 “‘Tí ẹ bá dé ilẹ̀ náà, tí ẹ sì gbin igi èyíkéyìí fún oúnjẹ, kí ẹ ka èso rẹ̀ sí ohun àìmọ́ àti èèwọ̀.* Ọdún mẹ́ta ni yóò fi jẹ́ èèwọ̀* fún yín. Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ́. 24 Àmọ́ ní ọdún kẹrin, gbogbo èso rẹ̀ yóò di ohun mímọ́ láti fi yọ̀ níwájú Jèhófà.+ 25 Tó bá di ọdún karùn-ún, ẹ lè jẹ èso rẹ̀, kí ohun tí ẹ máa kórè lè pọ̀ sí i. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.

26 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tòun ti ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.+

“‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ woṣẹ́, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ pidán.+

27 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ fá* irun ẹ̀gbẹ́ orí yín tàbí kí ẹ ba eteetí irùngbọ̀n yín jẹ́.+

28 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ kọ ara yín lábẹ torí ẹni tó kú,*+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ fín àmì sí ara yín. Èmi ni Jèhófà.

29 “‘Má ba ọmọbìnrin rẹ jẹ́ nípa sísọ ọ́ di aṣẹ́wó,+ kí ilẹ̀ náà má bàa ṣiṣẹ́ aṣẹ́wó, kí ìwà ìbàjẹ́+ sì kún ibẹ̀.

30 “‘Ẹ gbọ́dọ̀ máa pa àwọn sábáàtì mi mọ́,+ kí ẹ sì máa bọ̀wọ̀ fún* ibi mímọ́ mi. Èmi ni Jèhófà.

31 “‘Ẹ má tọ àwọn abẹ́mìílò lọ.+ Ẹ má sì wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ àwọn woṣẹ́woṣẹ́,+ kí wọ́n má bàa sọ yín di aláìmọ́. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.

32 “‘Kí o dìde níwájú orí ewú,+ kí o máa bọlá fún àgbàlagbà,+ kí o sì máa bẹ̀rù Ọlọ́run+ rẹ. Èmi ni Jèhófà.

33 “‘Tí àjèjì kan bá ń gbé pẹ̀lú yín ní ilẹ̀ yín, ẹ ò gbọ́dọ̀ fìyà jẹ ẹ́.+ 34 Kí ẹ máa ṣe àjèjì tó ń bá yín gbé bí ọmọ ìbílẹ̀;+ kí ẹ nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara yín, torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.

35 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ lo ìwọ̀n èké tí ẹ bá ń díwọ̀n bí ohun kan ṣe gùn tó, bó ṣe wúwo tó tàbí bó ṣe pọ̀ tó.+ 36 Kí ẹ máa lo òṣùwọ̀n tó péye, ìwọ̀n tó péye, òṣùwọ̀n tó péye fún ohun tí kò lómi* àti òṣùwọ̀n tó péye fún nǹkan olómi.*+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, ẹni tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì. 37 Torí náà, kí ẹ máa pa gbogbo àṣẹ mi àti gbogbo ìdájọ́ mi mọ́, kí ẹ sì máa tẹ̀ lé wọn.+ Èmi ni Jèhófà.’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́