ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 31
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Diutarónómì

      • Ikú Mósè sún mọ́lé (1-8)

      • Kí wọ́n máa ka Òfin Ọlọ́run sí wọn létí (9-13)

      • Ó faṣẹ́ lé Jóṣúà lọ́wọ́ (14, 15)

      • Àsọtẹ́lẹ̀ bí Ísírẹ́lì ṣe máa ya ọlọ̀tẹ̀ (16-30)

        • Orin láti fi kọ́ Ísírẹ́lì (19, 22, 30)

Diutarónómì 31:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Mi ò lè máa jáde kí n sì máa wọlé mọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 7:7; Di 34:7; Iṣe 7:23
  • +Nọ 20:12; Di 3:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2006, ojú ìwé 31

Diutarónómì 31:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 9:3
  • +Nọ 27:18; Di 3:28; Joṣ 1:2

Diutarónómì 31:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 21:23, 24
  • +Nọ 21:33, 35
  • +Ẹk 23:23

Diutarónómì 31:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 33:52; Di 7:2, 24; 20:16

Diutarónómì 31:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 1:6; Sm 27:14; 118:6
  • +Nọ 14:9; Di 7:18
  • +Di 4:31; Joṣ 1:5; Heb 13:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/1998, ojú ìwé 10-11

Diutarónómì 31:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 10:25
  • +Di 1:38

Diutarónómì 31:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 33:14
  • +Joṣ 1:9

Diutarónómì 31:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:27

Diutarónómì 31:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 15:1
  • +Le 23:34

Diutarónómì 31:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 16:16
  • +Ne 8:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2007, ojú ìwé 20

Diutarónómì 31:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ kéékèèké.”

  • *

    Ní Héb., “ẹnubodè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 4:10; Heb 10:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2010, ojú ìwé 3

    9/15/2004, ojú ìwé 27

    3/15/2000, ojú ìwé 17

Diutarónómì 31:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 6:6, 7; Ef 6:4
  • +Di 30:16

Diutarónómì 31:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “lọ dúró níwájú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 27:13
  • +Di 3:28

Diutarónómì 31:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà tó rí bí òpó.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 33:9; 40:38

Diutarónómì 31:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “dùbúlẹ̀ pẹ̀lú àwọn bàbá rẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 2:17; Sm 106:37-39
  • +1Ọb 11:33
  • +Ond 2:12, 20

Diutarónómì 31:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 29:20
  • +1Kr 28:9; 2Kr 15:2; 24:20
  • +Di 32:20; Sm 104:29; Isk 39:23
  • +Ne 9:27
  • +Ond 6:13

Diutarónómì 31:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 59:2

Diutarónómì 31:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Ẹ fi sí wọn lẹ́nu.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:30; 32:44
  • +Di 4:9; 11:19
  • +Di 31:21

Diutarónómì 31:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “tí wọ́n sì sanra.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 15:18
  • +Ẹk 3:8; Nọ 13:26, 27
  • +Ne 9:25
  • +Ẹk 24:7; Di 8:12-14; 29:1; Ne 9:26

Diutarónómì 31:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:59
  • +Ẹk 16:4

Diutarónómì 31:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ṣe kedere pé Ọlọ́run ló ń tọ́ka sí.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 27:18; Di 31:14
  • +Joṣ 1:6, 9
  • +Di 1:38; 3:28

Diutarónómì 31:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:27

Diutarónómì 31:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 17:18; 2Kr 34:14
  • +1Ọb 8:9

Diutarónómì 31:27

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹ sì jẹ́ ọlọ́rùn líle.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 9:24; Ne 9:26
  • +Ẹk 32:9; Sm 78:8

Diutarónómì 31:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 30:19

Diutarónómì 31:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 2:19
  • +Di 28:15

Diutarónómì 31:30

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:44

Àwọn míì

Diu. 31:2Ẹk 7:7; Di 34:7; Iṣe 7:23
Diu. 31:2Nọ 20:12; Di 3:27
Diu. 31:3Di 9:3
Diu. 31:3Nọ 27:18; Di 3:28; Joṣ 1:2
Diu. 31:4Nọ 21:23, 24
Diu. 31:4Nọ 21:33, 35
Diu. 31:4Ẹk 23:23
Diu. 31:5Nọ 33:52; Di 7:2, 24; 20:16
Diu. 31:6Joṣ 1:6; Sm 27:14; 118:6
Diu. 31:6Nọ 14:9; Di 7:18
Diu. 31:6Di 4:31; Joṣ 1:5; Heb 13:5
Diu. 31:7Joṣ 10:25
Diu. 31:7Di 1:38
Diu. 31:8Ẹk 33:14
Diu. 31:8Joṣ 1:9
Diu. 31:9Ẹk 34:27
Diu. 31:10Di 15:1
Diu. 31:10Le 23:34
Diu. 31:11Di 16:16
Diu. 31:11Ne 8:7
Diu. 31:12Di 4:10; Heb 10:25
Diu. 31:13Di 6:6, 7; Ef 6:4
Diu. 31:13Di 30:16
Diu. 31:14Nọ 27:13
Diu. 31:14Di 3:28
Diu. 31:15Ẹk 33:9; 40:38
Diu. 31:16Ond 2:17; Sm 106:37-39
Diu. 31:161Ọb 11:33
Diu. 31:16Ond 2:12, 20
Diu. 31:17Di 29:20
Diu. 31:171Kr 28:9; 2Kr 15:2; 24:20
Diu. 31:17Di 32:20; Sm 104:29; Isk 39:23
Diu. 31:17Ne 9:27
Diu. 31:17Ond 6:13
Diu. 31:18Ais 59:2
Diu. 31:19Di 31:30; 32:44
Diu. 31:19Di 4:9; 11:19
Diu. 31:19Di 31:21
Diu. 31:20Jẹ 15:18
Diu. 31:20Ẹk 3:8; Nọ 13:26, 27
Diu. 31:20Ne 9:25
Diu. 31:20Ẹk 24:7; Di 8:12-14; 29:1; Ne 9:26
Diu. 31:21Di 28:59
Diu. 31:21Ẹk 16:4
Diu. 31:23Nọ 27:18; Di 31:14
Diu. 31:23Joṣ 1:6, 9
Diu. 31:23Di 1:38; 3:28
Diu. 31:24Ẹk 34:27
Diu. 31:26Di 17:18; 2Kr 34:14
Diu. 31:261Ọb 8:9
Diu. 31:27Di 9:24; Ne 9:26
Diu. 31:27Ẹk 32:9; Sm 78:8
Diu. 31:28Di 30:19
Diu. 31:29Ond 2:19
Diu. 31:29Di 28:15
Diu. 31:30Di 32:44
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Diutarónómì 31:1-30

Diutarónómì

31 Lẹ́yìn náà, Mósè jáde lọ sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí fún gbogbo Ísírẹ́lì, 2 ó sọ fún wọn pé: “Ẹni ọgọ́fà (120) ọdún ni mí lónìí.+ Mi ò lè darí yín mọ́,* torí Jèhófà ti sọ fún mi pé, ‘O ò ní sọdá Jọ́dánì yìí.’+ 3 Jèhófà Ọlọ́run rẹ ló máa sọdá ṣáájú rẹ, òun fúnra rẹ̀ máa pa àwọn orílẹ̀-èdè yìí run kúrò níwájú rẹ, wàá sì lé wọn kúrò.+ Jóṣúà ló máa kó yín sọdá,+ bí Jèhófà ṣe sọ gẹ́lẹ́. 4 Ohun tí Jèhófà ṣe sí Síhónì+ àti Ógù,+ àwọn ọba Ámórì àti sí ilẹ̀ wọn, nígbà tó pa wọ́n run ló máa ṣe sí wọn gẹ́lẹ́.+ 5 Jèhófà máa bá yín ṣẹ́gun wọn, gbogbo ohun tí mo sì pa láṣẹ fún yín ni kí ẹ ṣe sí wọn gẹ́lẹ́.+ 6 Ẹ jẹ́ onígboyà àti alágbára.+ Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì gbọ̀n rìrì níwájú wọn,+ torí Jèhófà Ọlọ́run yín ló ń bá yín lọ. Kò ní pa yín tì, kò sì ní fi yín sílẹ̀.”+

7 Mósè wá pe Jóṣúà, ó sì sọ fún un níṣojú gbogbo Ísírẹ́lì pé: “Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú àwọn èèyàn yìí wọ ilẹ̀ tí Jèhófà búra fún àwọn baba ńlá wọn pé òun máa fún wọn, wàá sì fún wọn kí wọ́n lè jogún rẹ̀.+ 8 Jèhófà ló ń lọ níwájú rẹ, ó sì máa wà pẹ̀lú rẹ.+ Kò ní pa ọ́ tì, kò sì ní fi ọ́ sílẹ̀. Má bẹ̀rù, má sì jáyà.”+

9 Mósè wá kọ Òfin yìí,+ ó sì fún àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì, tí wọ́n ń gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà àti gbogbo àgbààgbà Ísírẹ́lì. 10 Mósè pàṣẹ fún wọn pé: “Ní òpin ọdún méje-méje, ní àkókò rẹ̀ nígbà ọdún ìtúsílẹ̀,+ ní àkókò Àjọyọ̀ Àtíbàbà,+ 11 nígbà tí gbogbo Ísírẹ́lì bá wá síwájú Jèhófà+ Ọlọ́run rẹ ní ibi tó yàn, kí ẹ ka Òfin yìí sí gbogbo Ísírẹ́lì létí.+ 12 Ẹ kó àwọn èèyàn náà jọ,+ àwọn ọkùnrin, àwọn obìnrin, àwọn ọmọdé* àti àwọn àjèjì yín tó ń gbé nínú àwọn ìlú* yín, kí wọ́n lè fetí sílẹ̀, kí wọ́n sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa Jèhófà Ọlọ́run yín, kí wọ́n máa bẹ̀rù rẹ̀, kí wọ́n sì lè máa rí i dájú pé àwọn ń tẹ̀ lé gbogbo ọ̀rọ̀ Òfin yìí. 13 Àwọn ọmọ wọn tí kò tíì mọ Òfin yìí á wá fetí sílẹ̀,+ wọ́n á sì kọ́ láti máa bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run yín ní gbogbo ọjọ́ tí ẹ bá fi wà lórí ilẹ̀ tí ẹ̀ ń sọdá Jọ́dánì lọ gbà.”+

14 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wò ó! Ọjọ́ ikú rẹ ti sún mọ́lé.+ Pe Jóṣúà, kí ẹ sì lọ síwájú* àgọ́ ìpàdé, kí n lè faṣẹ́ lé e lọ́wọ́.”+ Mósè àti Jóṣúà wá lọ síwájú àgọ́ ìpàdé. 15 Jèhófà wá fara hàn ní àgọ́ náà nínú ọwọ̀n ìkùukùu,* ọwọ̀n ìkùukùu náà sì dúró ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ náà.+

16 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wò ó! O ò ní pẹ́ kú,* àwọn èèyàn yìí á sì bẹ̀rẹ̀ sí í bá àwọn ọlọ́run àjèjì tó yí wọn ká ní ilẹ̀ tí wọ́n ń lọ ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+ Wọ́n á pa mí tì,+ wọ́n á sì da májẹ̀mú mi tí mo bá wọn dá.+ 17 Màá bínú sí wọn gidigidi nígbà yẹn,+ màá pa wọ́n tì,+ màá sì fi ojú mi pa mọ́ fún wọn+ títí wọ́n á fi pa run. Tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àjálù àti wàhálà bá wá dé bá wọn,+ wọ́n á sọ pé, ‘Ṣebí torí Ọlọ́run wa ò sí láàárín wa ni àjálù yìí ṣe dé bá wa?’+ 18 Àmọ́ màá fi ojú mi pa mọ́ fún wọn lọ́jọ́ yẹn torí gbogbo ìwà ibi tí wọ́n hù, tí wọ́n lọ ń tọ àwọn ọlọ́run míì lẹ́yìn.+

19 “Ẹ kọ ọ̀rọ̀ orin yìí sílẹ̀ fún ara yín,+ kí ẹ sì fi kọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Ẹ fi kọ́ wọn,* kí orin yìí lè ṣe ẹlẹ́rìí mi lòdì sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ 20 Tí mo bá mú wọn dé ilẹ̀ tí mo búra nípa rẹ̀ fún àwọn baba ńlá wọn,+ ilẹ̀ tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn,+ tí wọ́n jẹun tẹ́rùn, tí nǹkan sì ń lọ dáadáa fún wọn,*+ wọ́n á lọ máa tọ àwọn ọlọ́run míì lẹ́yìn, wọ́n á sì máa sìn wọ́n, wọ́n á hùwà àfojúdi sí mi, wọ́n á sì da májẹ̀mú mi.+ 21 Tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àjálù àti wàhálà bá dé bá wọn,+ orin yìí máa jẹ́ ẹlẹ́rìí fún wọn, (torí àwọn àtọmọdọ́mọ wọn ò gbọ́dọ̀ gbàgbé rẹ̀), torí mo ti mọ ohun tí wọ́n ń rò lọ́kàn+ kí n tiẹ̀ tó mú wọn dé ilẹ̀ tí mo búra nípa rẹ̀.”

22 Mósè wá kọ ọ̀rọ̀ orin yìí sílẹ̀ ní ọjọ́ yẹn, ó sì fi kọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

23 Lẹ́yìn náà, Ó* fa iṣẹ́ lé Jóṣúà+ ọmọ Núnì lọ́wọ́, ó sọ pé: “Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wọ ilẹ̀ tí mo búra fún wọn nípa rẹ̀,+ mi ò sì ní fi ọ́ sílẹ̀.”

24 Gbàrà tí Mósè kọ gbogbo ọ̀rọ̀ Òfin yìí sínú ìwé tán,+ 25 Mósè pàṣẹ fún àwọn ọmọ Léfì tó ń gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà, pé: 26 “Ẹ gba ìwé Òfin yìí,+ kí ẹ fi sí ẹ̀gbẹ́ àpótí+ májẹ̀mú Jèhófà Ọlọ́run yín, kó sì jẹ́ ẹlẹ́rìí lòdì sí yín níbẹ̀. 27 Torí mo mọ̀ dáadáa pé ọlọ̀tẹ̀ ni yín,+ ẹ sì lágídí.*+ Tí ẹ bá ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà tó báyìí nígbà tí mo ṣì wà láàyè pẹ̀lú yín, tí mo bá wá kú ńkọ́! 28 Ẹ kó gbogbo àgbààgbà ẹ̀yà yín àti àwọn olórí yín jọ sọ́dọ̀ mi, kí n lè fi àwọn ọ̀rọ̀ yìí tó wọn létí, kí n sì fi ọ̀run àti ayé ṣe ẹlẹ́rìí lòdì sí wọn.+ 29 Torí mo mọ̀ dáadáa pé tí mo bá ti kú, ó dájú pé ẹ máa ṣe ohun tó burú,+ ẹ sì máa yà kúrò lójú ọ̀nà tí mo pa láṣẹ fún yín. Ó dájú pé àjálù máa dé bá yín+ nígbẹ̀yìn ọjọ́, torí ẹ máa ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà, iṣẹ́ ọwọ́ yín sì máa múnú bí i.”

30 Mósè wá ka àwọn ọ̀rọ̀ orin yìí sí gbogbo ìjọ Ísírẹ́lì létí, láti ìbẹ̀rẹ̀ dé ìparí:+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́