ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jémíìsì 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jémíìsì

      • Bí a ṣe lè kápá ahọ́n (1-12)

        • Kí ọ̀pọ̀ má ṣe di olùkọ́ (1)

      • Ọgbọ́n tó wá láti òkè (13-18)

Jémíìsì 3:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “le.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 12:48

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 16

    9/15/1995, ojú ìwé 30

Jémíìsì 3:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣàṣìṣe.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 8:46; Owe 20:9; 1Jo 1:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 51

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2020, ojú ìwé 21

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2013, ojú ìwé 4

    11/15/1997, ojú ìwé 16

Jémíìsì 3:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2020, ojú ìwé 21

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 16

Jémíìsì 3:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 16

Jémíìsì 3:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2015, ojú ìwé 18

    11/15/1997, ojú ìwé 16

    12/15/1995, ojú ìwé 19

    10/1/1993, ojú ìwé 32

Jémíìsì 3:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “àgbá kẹ̀kẹ́ ìbí (orísun).”

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 16:27; Mt 12:36, 37
  • +Sm 39:1; Mt 15:11, 18; Mk 7:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2015, ojú ìwé 18-19

    8/15/2012, ojú ìwé 20-21

    11/15/1997, ojú ìwé 16-17

Jémíìsì 3:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “rákò.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 17

Jémíìsì 3:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 140:3; Owe 12:18; 18:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2006, ojú ìwé 20-21

    11/15/1997, ojú ìwé 17

    3/1/1991, ojú ìwé 24

Jémíìsì 3:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:26, 27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 17-18

    7/15/1993, ojú ìwé 21

Jémíìsì 3:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 4:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 17-18

    7/15/1993, ojú ìwé 21

Jémíìsì 3:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “Omi dídùn.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/15/1993, ojú ìwé 21

Jémíìsì 3:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 7:16

Jémíìsì 3:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 201

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2008, ojú ìwé 21-22

    11/15/1997, ojú ìwé 18

    12/15/1995, ojú ìwé 19

Jémíìsì 3:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “tí ẹ sì ń wá ipò ọlá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 13:13; 1Kọ 3:3
  • +Ef 4:31
  • +1Kọ 13:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2008, ojú ìwé 22-23

    11/15/1997, ojú ìwé 18

Jémíìsì 3:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 2:14; Flp 3:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2008, ojú ìwé 23-24

    11/15/1997, ojú ìwé 18

Jémíìsì 3:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “tí wọ́n sì ń wá ipò ọlá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 14:30; Ga 5:19-21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 18

Jémíìsì 3:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:9; 1Ti 5:1, 2
  • +2Kọ 13:11; 1Tẹ 5:13; 2Pe 3:14
  • +1Ti 3:3; Tit 3:2
  • +Ga 5:22, 23
  • +Jem 2:9
  • +1Pe 1:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    No. 1 2020 ojú ìwé 8

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 221-228

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 30-31

    3/15/2008, ojú ìwé 24-25

    9/1/2005, ojú ìwé 29-30

    11/15/1997, ojú ìwé 18

    12/15/1995, ojú ìwé 19

    8/1/1994, ojú ìwé 11-12

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 251

Jémíìsì 3:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ibi tí àlàáfíà bá wà, ni àwọn tó ń wá àlàáfíà máa ń gbin èso òdodo sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 32:17; Heb 12:11
  • +Mt 5:9; 1Pe 3:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 21

Àwọn míì

Jém. 3:1Lk 12:48
Jém. 3:21Ọb 8:46; Owe 20:9; 1Jo 1:8
Jém. 3:6Owe 16:27; Mt 12:36, 37
Jém. 3:6Sm 39:1; Mt 15:11, 18; Mk 7:23
Jém. 3:8Sm 140:3; Owe 12:18; 18:7
Jém. 3:9Jẹ 1:26, 27
Jém. 3:10Ef 4:29
Jém. 3:12Mt 7:16
Jém. 3:14Ro 13:13; 1Kọ 3:3
Jém. 3:14Ef 4:31
Jém. 3:141Kọ 13:4
Jém. 3:151Kọ 2:14; Flp 3:19
Jém. 3:16Owe 14:30; Ga 5:19-21
Jém. 3:17Ro 12:9; 1Ti 5:1, 2
Jém. 3:172Kọ 13:11; 1Tẹ 5:13; 2Pe 3:14
Jém. 3:171Ti 3:3; Tit 3:2
Jém. 3:17Ga 5:22, 23
Jém. 3:17Jem 2:9
Jém. 3:171Pe 1:22
Jém. 3:18Ais 32:17; Heb 12:11
Jém. 3:18Mt 5:9; 1Pe 3:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jémíìsì 3:1-18

Lẹ́tà Jémíìsì

3 Ẹ̀yin arákùnrin mi, kí púpọ̀ nínú yín má ṣe di olùkọ́, torí ẹ mọ̀ pé a máa gba ìdájọ́ tó wúwo* jù.+ 2 Nítorí gbogbo wa ni a máa ń kọsẹ̀* lọ́pọ̀ ìgbà.+ Tí ẹnì kan kì í bá ṣi ọ̀rọ̀ sọ, á jẹ́ pé ẹni pípé ni, ó sì lè kó gbogbo ara rẹ̀ níjàánu. 3 Tí a bá fi ìjánu sí ẹnu àwọn ẹṣin kí wọ́n lè ṣègbọràn sí wa, gbogbo ara wọn là ń darí pẹ̀lú. 4 Ẹ tún wo àwọn ọkọ̀ òkun: Bó tiẹ̀ jẹ́ pé wọ́n tóbi gan-an, tí atẹ́gùn tó le gan-an sì máa ń gbé wọn kiri, ìtọ́kọ̀ tó kéré gan-an la fi ń darí wọn síbi tí ẹni tó ń darí ọkọ̀ bá fẹ́ kó lọ.

5 Bẹ́ẹ̀ náà ni ahọ́n jẹ́ ẹ̀yà ara tó kéré, síbẹ̀ ó máa ń fọ́nnu gan-an. Ẹ wo bí iná tí kò tó nǹkan ṣe lè jó igbó kìjikìji run! 6 Bákan náà, ahọ́n jẹ́ iná.+ Ahọ́n dúró fún ayé àìṣòdodo lára àwọn ẹ̀yà ara wa, torí ó máa ń sọ gbogbo ara di aláìmọ́,+ ó sì máa ń dáná sí gbogbo ìgbésí ayé* ẹ̀dá, iná Gẹ̀hẹ́nà* á sì sun òun náà. 7 Torí àwọn èèyàn máa ń kápá gbogbo ẹran inú igbó àti ẹyẹ àti ẹran tó ń fàyà fà* àti ẹ̀dá inú òkun, wọ́n sì ti kápá wọn. 8 Àmọ́ kò sí èèyàn tó lè kápá ahọ́n. Aláìgbọràn ni, ó sì ń ṣeni léṣe, ó kún fún májèlé tó ń pani.+ 9 Òun la fi ń yin Jèhófà,* Baba wa, síbẹ̀ òun la tún fi ń gégùn-ún fún àwọn èèyàn tí a dá ní “àwòrán Ọlọ́run.”+ 10 Ẹnu kan náà tí èèyàn fi ń súre ló tún fi ń gégùn-ún.

Ẹ̀yin ará mi, kò yẹ kó máa rí bẹ́ẹ̀.+ 11 Omi tó ṣeé mu* àti omi tó korò kì í jáde láti orísun kan náà, àbí ó ń ṣe bẹ́ẹ̀? 12 Ẹ̀yin ará mi, igi ọ̀pọ̀tọ́ ò lè mú èso ólífì jáde tàbí kí àjàrà mú èso ọ̀pọ̀tọ́ jáde, àbí ó lè ṣe bẹ́ẹ̀?+ Bẹ́ẹ̀ ni omi iyọ̀ ò lè mú omi tó ṣeé mu jáde.

13 Ọlọ́gbọ́n àti olóye wo ló wà láàárín yín? Kó fi ìwà rere rẹ̀ hàn nínú bó ṣe ń fi ìwà tútù ṣe àwọn iṣẹ́ tó fi hàn pé ó gbọ́n. 14 Àmọ́ tí ẹ bá ń jowú gidigidi,+ tó sì ń wù yín láti máa fa ọ̀rọ̀,*+ ẹ má ṣe máa fọ́nnu,+ ẹ má sì máa parọ́ mọ́ òtítọ́. 15 Èyí kì í ṣe ọgbọ́n tó wá láti òkè; ti ayé ni,+ ti ẹranko àti ti ẹ̀mí èṣù. 16 Torí ibikíbi tí wọ́n bá ti ń jowú tí wọ́n sì ń fa ọ̀rọ̀,* ìdàrúdàpọ̀ àti gbogbo nǹkan burúkú máa ń wà níbẹ̀.+

17 Àmọ́, ọgbọ́n tó wá láti òkè á kọ́kọ́ jẹ́ mímọ́,+ lẹ́yìn náà, ó lẹ́mìí àlàáfíà,+ ó ń fòye báni lò,+ ó ṣe tán láti ṣègbọràn, ó máa ń ṣàánú gan-an, ó sì ń so èso rere,+ kì í ṣe ojúsàájú,+ kì í sì í ṣe àgàbàgebè.+ 18 Bákan náà, ibi tí àlàáfíà bá wà+ la máa ń gbin èso òdodo sí fún àwọn tó ń wá àlàáfíà.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́