ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Oníwàásù 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Oníwàásù

      • Àgbéyẹ̀wò àwọn ohun tí Sólómọ́nì ṣe (1-11)

      • Ó níbi tí ọgbọ́n èèyàn wúlò dé (12-16)

      • Asán tó wà nínú iṣẹ́ àṣekára (17-23)

      • Máa jẹ, máa mu, kí o sì gbádùn iṣẹ́ rẹ (24-26)

Oníwàásù 2:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìdùnnú.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    4/2006, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/1997, ojú ìwé 14-15

Oníwàásù 2:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìdùnnú.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2006, ojú ìwé 13-14

    3/15/1997, ojú ìwé 14-15

Oníwàásù 2:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 104:15; Onw 10:19

Oníwàásù 2:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 9:17-19; 2Kr 9:15, 16
  • +1Ọb 7:1, 8
  • +1Ọb 4:25; Sol 8:11

Oníwàásù 2:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “igbó.”

Oníwàásù 2:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ ilé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 8:10, 13; 1Ọb 9:22
  • +1Ọb 4:22, 23

Oníwàásù 2:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “dúkìá tó jẹ́ ti.”

  • *

    Tàbí “ọmọge, àní àwọn ọmọge.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 9:14, 28; 10:10; 2Kr 1:15
  • +1Ọb 10:14, 15; 2Kr 9:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2011, ojú ìwé 7

Oníwàásù 2:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 3:13; 10:23

Oníwàásù 2:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “tí ojú mi béèrè.”

  • *

    Tàbí “ìdùnnú.”

  • *

    Tàbí “ìpín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 11:9
  • +Onw 3:22; 5:18; 9:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/1997, ojú ìwé 3-4

Oníwàásù 2:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “lílépa ẹ̀fúùfù.”

  • *

    Tàbí “ohun tó ṣàǹfààní.”

  • *

    Ní Héb., “lábẹ́ oòrùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 7:1
  • +Sm 49:10; Onw 1:14; 2:16; 1Ti 6:7
  • +Onw 1:3; 2:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2008, ojú ìwé 21

    10/15/1997, ojú ìwé 4

    2/15/1997, ojú ìwé 14

Oníwàásù 2:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 1:17; 7:25

Oníwàásù 2:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 4:7; Onw 7:11, 12

Oníwàásù 2:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ọlọ́gbọ́n la ojú rẹ̀ sílẹ̀.”

  • *

    Tàbí “àtúbọ̀tán.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 4:25
  • +Owe 14:8; 17:24; Jo 3:19; 1Jo 2:11
  • +Onw 3:19, 20; 9:2, 3, 11

Oníwàásù 2:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 49:10

Oníwàásù 2:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 1:8; Onw 1:11
  • +Onw 6:8; Ro 5:12

Oníwàásù 2:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “lábẹ́ oòrùn.”

  • *

    Tàbí “lílépa ẹ̀fúùfù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 19:2, 4; Jer 20:17, 18
  • +Job 7:6; Onw 2:21; Ro 8:20
  • +Onw 1:14; 5:16

Oníwàásù 2:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “lábẹ́ oòrùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 2:4-8
  • +Sm 39:6; Lk 12:20

Oníwàásù 2:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “lábẹ́ oòrùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 12:6, 8; 2Kr 12:1, 9

Oníwàásù 2:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “lábẹ́ oòrùn.”

Oníwàásù 2:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gbogbo rẹ̀.”

  • *

    Tàbí “àjálù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 2:18; 5:15, 16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2004, ojú ìwé 27

Oníwàásù 2:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “bí ọkàn rẹ̀ ṣe ń sapá.”

  • *

    Ní Héb., “lábẹ́ oòrùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 1:3; 3:9

Oníwàásù 2:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 14:1, 2; Lk 12:29
  • +Jẹ 31:40, 41

Oníwàásù 2:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “jẹ́ kí ọkàn rẹ̀ rí ohun rere nínú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 12:18; Onw 3:22; 8:15; Iṣe 14:17
  • +Onw 3:12, 13; 5:18, 19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 37

    Jí!,

    11/2014, ojú ìwé 6

    12/22/1997, ojú ìwé 11

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 7

Oníwàásù 2:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 4:7, 22, 23; 10:4, 5, 21

Oníwàásù 2:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “lílépa ẹ̀fúùfù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 18:14; Owe 3:32, 33; Ais 3:10
  • +Di 6:10, 11; Owe 13:22; 28:8

Àwọn míì

Oníw. 2:3Sm 104:15; Onw 10:19
Oníw. 2:41Ọb 9:17-19; 2Kr 9:15, 16
Oníw. 2:41Ọb 7:1, 8
Oníw. 2:41Ọb 4:25; Sol 8:11
Oníw. 2:71Sa 8:10, 13; 1Ọb 9:22
Oníw. 2:71Ọb 4:22, 23
Oníw. 2:81Ọb 9:14, 28; 10:10; 2Kr 1:15
Oníw. 2:81Ọb 10:14, 15; 2Kr 9:13, 14
Oníw. 2:91Ọb 3:13; 10:23
Oníw. 2:10Onw 11:9
Oníw. 2:10Onw 3:22; 5:18; 9:9
Oníw. 2:111Ọb 7:1
Oníw. 2:11Sm 49:10; Onw 1:14; 2:16; 1Ti 6:7
Oníw. 2:11Onw 1:3; 2:17
Oníw. 2:12Onw 1:17; 7:25
Oníw. 2:13Owe 4:7; Onw 7:11, 12
Oníw. 2:14Owe 4:25
Oníw. 2:14Owe 14:8; 17:24; Jo 3:19; 1Jo 2:11
Oníw. 2:14Onw 3:19, 20; 9:2, 3, 11
Oníw. 2:15Sm 49:10
Oníw. 2:16Ẹk 1:8; Onw 1:11
Oníw. 2:16Onw 6:8; Ro 5:12
Oníw. 2:171Ọb 19:2, 4; Jer 20:17, 18
Oníw. 2:17Job 7:6; Onw 2:21; Ro 8:20
Oníw. 2:17Onw 1:14; 5:16
Oníw. 2:18Onw 2:4-8
Oníw. 2:18Sm 39:6; Lk 12:20
Oníw. 2:191Ọb 12:6, 8; 2Kr 12:1, 9
Oníw. 2:21Onw 2:18; 5:15, 16
Oníw. 2:22Onw 1:3; 3:9
Oníw. 2:23Job 14:1, 2; Lk 12:29
Oníw. 2:23Jẹ 31:40, 41
Oníw. 2:24Di 12:18; Onw 3:22; 8:15; Iṣe 14:17
Oníw. 2:24Onw 3:12, 13; 5:18, 19
Oníw. 2:251Ọb 4:7, 22, 23; 10:4, 5, 21
Oníw. 2:261Sa 18:14; Owe 3:32, 33; Ais 3:10
Oníw. 2:26Di 6:10, 11; Owe 13:22; 28:8
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Oníwàásù 2:1-26

Oníwàásù

2 Nígbà náà, mo sọ lọ́kàn mi pé: “Wá, jẹ́ kí n dán ìgbádùn* wò, kí n sì rí ohun rere tó máa tibẹ̀ wá.” Àmọ́ wò ó! asán ni èyí pẹ̀lú.

 2 Mo sọ nípa ẹ̀rín pé, “Wèrè ni!”

Àti nípa ìgbádùn* pé, “Kí ni ìwúlò rẹ̀?”

3 Mo mu wáìnì,+ kí n lè fi ọkàn mi ṣèwádìí, àmọ́ ní gbogbo àkókò yìí mi ò sọ ọgbọ́n mi nù; kódà, mo fara mọ́ ìwà ẹ̀gọ̀ kí n lè rí ohun tó dáa jù lọ fún ọmọ aráyé láti máa ṣe láàárín ọjọ́ díẹ̀ tí wọ́n máa lò lábẹ́ ọ̀run. 4 Mo ṣe àwọn iṣẹ́ ńlá.+ Mo kọ́ àwọn ilé fún ara mi;+ mo gbin àwọn ọgbà àjàrà fún ara mi.+ 5 Mo ṣe àwọn ọgbà ọ̀gbìn àti ọgbà ìtura fún ara mi, mo sì gbin oríṣiríṣi igi eléso sínú wọn. 6 Mo ṣe àwọn adágún omi fún ara mi, láti máa fi bomi rin ọgbà* tí àwọn igi tó léwé dáadáa wà. 7 Mo ní àwọn ìránṣẹ́ lọ́kùnrin àti lóbìnrin,+ mo sì ní àwọn ìránṣẹ́ tí wọ́n bí ní agbo ilé mi.* Mo tún ní ọ̀pọ̀ ẹran ọ̀sìn, ìyẹn màlúù àti agbo ẹran,+ tó pọ̀ ju ti ẹnikẹ́ni tó wà ṣáájú mi ní Jerúsálẹ́mù. 8 Mo kó fàdákà àti wúrà jọ fún ara mi,+ ìṣúra* àwọn ọba àti ti àwọn ìpínlẹ̀.+ Mo kó àwọn akọrin lọ́kùnrin àti lóbìnrin jọ fún ara mi, títí kan ohun tó ń múnú ọmọ aráyé dùn gidigidi, ìyẹn obìnrin, àní ọ̀pọ̀ obìnrin.* 9 Torí náà, mo dẹni ńlá, mo sì ga ju gbogbo àwọn tó wà ṣáájú mi ní Jerúsálẹ́mù.+ Bẹ́ẹ̀ ni ọgbọ́n mi kò fi mí sílẹ̀.

10 Mi ò fi ohunkóhun tí mo fẹ́* du ara mi.+ Kò sí irú ìgbádùn* tí ọkàn mi fẹ́ tí mi ò fún un, torí ọkàn mi ń yọ̀ nítorí gbogbo iṣẹ́ àṣekára mi, èyí sì ni èrè* mi nínú gbogbo iṣẹ́ àṣekára mi.+ 11 Àmọ́ nígbà tí mo ronú lórí gbogbo iṣẹ́ tí ọwọ́ mi ti ṣe àti gbogbo iṣẹ́ àṣekára tí mo ti sapá láti ṣe yọrí,+ mo rí i pé asán ni gbogbo rẹ̀, ìmúlẹ̀mófo;*+ kò sí ohun gidi kan* lábẹ́ ọ̀run.*+

12 Mo wá fiyè sí ọgbọ́n àti ìwà wèrè àti ìwà ẹ̀gọ̀.+ (Kí ni ẹni tó máa wá lẹ́yìn ọba lè ṣe? Ohun tí àwọn èèyàn ti ṣe tẹ́lẹ̀ ni.) 13 Mo rí i pé àǹfààní wà nínú ọgbọ́n ju ìwà ẹ̀gọ̀ lọ,+ bí àǹfààní ṣe wà nínú ìmọ́lẹ̀ ju òkùnkùn lọ.

14 Ojú ọlọ́gbọ́n wà ní orí rẹ̀;*+ àmọ́ òmùgọ̀ ń rìn nínú òkùnkùn.+ Mo sì wá rí i pé ohun* kan náà ló ń ṣẹlẹ̀ sí gbogbo wọn.+ 15 Lẹ́yìn náà, mo sọ lọ́kàn mi pé: “Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí òmùgọ̀ ló máa ṣẹlẹ̀ sí èmi náà.”+ Kí wá ni èrè ọgbọ́n tí mo gbọ́n ní àgbọ́njù? Mo sì sọ lọ́kàn mi pé: “Asán ni èyí pẹ̀lú.” 16 Nítorí a kì í rántí ọlọ́gbọ́n tàbí òmùgọ̀ títí lọ.+ Bó pẹ́ bó yá, a ò ní rántí ẹnikẹ́ni mọ́. Báwo sì ni ọlọ́gbọ́n ṣe máa kú? Á kú pẹ̀lú àwọn òmùgọ̀.+

17 Ayé wá sú mi,+ nítorí gbogbo ohun tí à ń ṣe lábẹ́ ọ̀run* ló ń kó ìdààmú báni lójú tèmi, torí asán ni gbogbo rẹ̀,+ ìmúlẹ̀mófo.*+ 18 Mo wá kórìíra gbogbo iṣẹ́ àṣekára tí mo ti ṣe lábẹ́ ọ̀run,*+ torí mo gbọ́dọ̀ fi í sílẹ̀ fún ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi.+ 19 Ta ló sì mọ̀ bóyá ó máa jẹ́ ọlọ́gbọ́n tàbí òmùgọ̀?+ Síbẹ̀, òun ni yóò máa darí gbogbo ohun tí mo ti fi akitiyan àti ọgbọ́n kó jọ lábẹ́ ọ̀run.* Asán ni èyí pẹ̀lú. 20 Torí náà, ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn bẹ̀rẹ̀ sí í bá mi nítorí gbogbo iṣẹ́ àṣekára tí mo fi gbogbo agbára mi ṣe lábẹ́ ọ̀run.* 21 Nítorí èèyàn lè fi ọgbọ́n àti ìmọ̀ àti òye ṣiṣẹ́ ní àṣekára, àmọ́ ó gbọ́dọ̀ fi èrè rẹ̀* sílẹ̀ fún ẹni tí kò ṣiṣẹ́ fún un.+ Asán ni èyí pẹ̀lú àti àdánù* ńlá.

22 Kí tiẹ̀ ni èrè tí èèyàn rí jẹ nínú gbogbo iṣẹ́ àṣekára rẹ̀ àti gbogbo bó ṣe ń wù ú* láti ṣiṣẹ́ kára lábẹ́ ọ̀run?*+ 23 Torí ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, iṣẹ́ rẹ̀ ń mú ìrora àti ìjákulẹ̀ bá a,+ kódà kì í rí oorun sùn lóru.+ Asán ni èyí pẹ̀lú.

24 Kò sóhun tó dáa fún èèyàn ju pé kó jẹ, kó mu, kó sì gbádùn* iṣẹ́ àṣekára rẹ̀.+ Èyí pẹ̀lú ni mo ti rí pé ó wá láti ọwọ́ Ọlọ́run tòótọ́,+ 25 àbí ta ló ń jẹ, tó sì ń mu ohun tó dáa ju tèmi lọ?+

26 Ọlọ́run ń fún ẹni tó bá ń ṣe ìfẹ́ rẹ̀ ní ọgbọ́n àti ìmọ̀ àti ìdùnnú,+ àmọ́ ó ń fún àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní iṣẹ́ kíkó jọ àti ṣíṣà jọ kí wọ́n lè fún ẹni tó ń ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run tòótọ́.+ Asán ni èyí pẹ̀lú, ìmúlẹ̀mófo* sì ni.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́