ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Hébérù 10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Hébérù

      • Fífi ẹran rúbọ ò gbéṣẹ́ (1-4)

        • Òfin jẹ́ òjìji (1)

      • Kristi rúbọ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní ṣe é mọ́ láé (5-18)

      • Ọ̀nà àbáwọlé tuntun tó jẹ́ ọ̀nà ìyè (19-25)

        • Ká má ṣe máa kọ ìpàdé wa sílẹ̀ (24, 25)

      • Ìkìlọ̀ nípa ẹ̀ṣẹ̀ tí a mọ̀ọ́mọ̀ dá (26-31)

      • Ìgboyà àti ìgbàgbọ́ máa jẹ́ ká lè fara dà á (32-39)

Hébérù 10:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “àwọn èèyàn kò lè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 8:5
  • +Kol 2:16, 17
  • +Heb 7:19; 9:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2000, ojú ìwé 17

    Ayọ, ojú ìwé 108-109

Hébérù 10:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 16:34

Hébérù 10:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1991, ojú ìwé 12

Hébérù 10:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 6 2017 ojú ìwé 8

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2000, ojú ìwé 18

    7/1/1996, ojú ìwé 14

Hébérù 10:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 40:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2000, ojú ìwé 18

Hébérù 10:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “àkájọ ìwé inú ìwé náà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 40:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2012, ojú ìwé 28

    8/15/2000, ojú ìwé 18

    3/1/1995, ojú ìwé 14

    3/1/1994, ojú ìwé 30

Hébérù 10:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 40:6-8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 10/2017, ojú ìwé 1

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 161

Hébérù 10:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 1:4
  • +Heb 13:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2020, ojú ìwé 31

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 161

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1996, ojú ìwé 14-15

Hébérù 10:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “iṣẹ́ ìsìn gbogbo èèyàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 2:27, 28
  • +Ẹk 29:38; Nọ 28:3
  • +Heb 7:18; 10:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2000, ojú ìwé 11

Hébérù 10:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 154

Hébérù 10:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 110:1; 1Kọ 15:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 154

Hébérù 10:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 7:19

Hébérù 10:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 31:33; Heb 8:10

Hébérù 10:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 31:34; Heb 8:12

Hébérù 10:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìdánilójú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 9:8, 24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 161

Hébérù 10:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “tó fi lọ́lẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 27:51

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 161

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2000, ojú ìwé 15-16

    7/1/1996, ojú ìwé 15-16

Hébérù 10:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 6:13; Heb 3:6

Hébérù 10:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 1:7
  • +Ef 5:25, 26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2000, ojú ìwé 19-20

Hébérù 10:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ká di ìkéde ìrètí wa ní gbangba mú ṣinṣin.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 15:58; Kol 1:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2000, ojú ìwé 20-21

    12/15/1999, ojú ìwé 23

Hébérù 10:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kí ọ̀rọ̀ ara wa jẹ wá lógún; kíyè sí ara wa.”

  • *

    Tàbí “máa mú kó wù wá; máa ru ara wa sókè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 3:23; 1Ti 6:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 10

    Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 6

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2013, ojú ìwé 19-21

    3/15/2013, ojú ìwé 16

    2/1/2009, ojú ìwé 20

    3/15/2002, ojú ìwé 24-25

    8/15/2000, ojú ìwé 21-22

    12/15/1999, ojú ìwé 22-23

    3/15/1999, ojú ìwé 11

    3/1/1998, ojú ìwé 14-19

    4/1/1995, ojú ìwé 15-18, 20

    8/15/1993, ojú ìwé 8-9

    Ìmọ̀, ojú ìwé 163

Hébérù 10:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:12; Iṣe 2:42
  • +Ais 35:3; Ro 1:11, 12
  • +Ro 13:11; 2Pe 3:11, 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 10

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2018, ojú ìwé 20-24

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 3/2021, ojú ìwé 1

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2016, ojú ìwé 7

    Jí!,

    9/2014, ojú ìwé 11

    10/22/1997, ojú ìwé 31

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2013, ojú ìwé 19, 21-22

    2/1/2009, ojú ìwé 20

    11/15/2002, ojú ìwé 4, 6-8

    3/15/2002, ojú ìwé 24-25

    3/1/2002, ojú ìwé 16

    8/15/2000, ojú ìwé 21-22

    3/15/2000, ojú ìwé 15-17

    12/15/1999, ojú ìwé 22-23

    11/15/1999, ojú ìwé 19-20

    3/1/1998, ojú ìwé 14-19

    4/1/1995, ojú ìwé 15-16, 18-20

    11/15/1993, ojú ìwé 21-22

    8/15/1993, ojú ìwé 8-9

    9/1/1991, ojú ìwé 22

Hébérù 10:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Pe 2:21
  • +Mt 12:32; Heb 6:4-6; 1Jo 5:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2011, ojú ìwé 24

    11/1/2008, ojú ìwé 10

    9/15/1992, ojú ìwé 9-10

Hébérù 10:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 26:11

Hébérù 10:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 17:6

Hébérù 10:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 26:27, 28; Lk 22:20
  • +Heb 6:4-6

Hébérù 10:30

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:35, 36

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2008, ojú ìwé 10

Hébérù 10:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 4:6; Heb 6:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1999, ojú ìwé 17

    1/1/1998, ojú ìwé 9

    12/1/1996, ojú ìwé 29-31

Hébérù 10:33

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “síta bíi ti gbọ̀ngàn ìwòran.”

  • *

    Tàbí “ẹ máa ń dúró ti.”

Hébérù 10:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:12
  • +Lk 16:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2007, ojú ìwé 30-31

    1/1/2006, ojú ìwé 22-23

    5/1/2001, ojú ìwé 13-14

Hébérù 10:35

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “òmìnira yín láti sọ̀rọ̀ fàlàlà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 10:32; 1Kọ 15:58

Hébérù 10:36

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 21:19; Jem 5:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2015, ojú ìwé 30-31

    4/1/1996, ojú ìwé 32

    11/1/1991, ojú ìwé 9

Hébérù 10:37

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 26:20
  • +Hab 2:3; 2Pe 3:9

Hébérù 10:38

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 3:16; Ro 1:17
  • +Hab 2:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 187-188

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 15

    12/15/1999, ojú ìwé 20-21

Hébérù 10:39

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Pe 2:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2006, ojú ìwé 17-18

    12/15/1999, ojú ìwé 14-24

Àwọn míì

Héb. 10:1Heb 8:5
Héb. 10:1Kol 2:16, 17
Héb. 10:1Heb 7:19; 9:9
Héb. 10:3Le 16:34
Héb. 10:6Sm 40:6
Héb. 10:7Sm 40:8
Héb. 10:9Sm 40:6-8
Héb. 10:10Ga 1:4
Héb. 10:10Heb 13:12
Héb. 10:111Sa 2:27, 28
Héb. 10:11Ẹk 29:38; Nọ 28:3
Héb. 10:11Heb 7:18; 10:1
Héb. 10:12Ro 8:34
Héb. 10:13Sm 110:1; 1Kọ 15:25
Héb. 10:14Heb 7:19
Héb. 10:16Jer 31:33; Heb 8:10
Héb. 10:17Jer 31:34; Heb 8:12
Héb. 10:19Heb 9:8, 24
Héb. 10:20Mt 27:51
Héb. 10:21Sek 6:13; Heb 3:6
Héb. 10:221Jo 1:7
Héb. 10:22Ef 5:25, 26
Héb. 10:231Kọ 15:58; Kol 1:23
Héb. 10:24Kol 3:23; 1Ti 6:18
Héb. 10:25Di 31:12; Iṣe 2:42
Héb. 10:25Ais 35:3; Ro 1:11, 12
Héb. 10:25Ro 13:11; 2Pe 3:11, 12
Héb. 10:262Pe 2:21
Héb. 10:26Mt 12:32; Heb 6:4-6; 1Jo 5:16
Héb. 10:27Ais 26:11
Héb. 10:28Di 17:6
Héb. 10:29Mt 26:27, 28; Lk 22:20
Héb. 10:29Heb 6:4-6
Héb. 10:30Di 32:35, 36
Héb. 10:322Kọ 4:6; Heb 6:4
Héb. 10:34Mt 5:12
Héb. 10:34Lk 16:9
Héb. 10:35Mt 10:32; 1Kọ 15:58
Héb. 10:36Lk 21:19; Jem 5:11
Héb. 10:37Ais 26:20
Héb. 10:37Hab 2:3; 2Pe 3:9
Héb. 10:38Jo 3:16; Ro 1:17
Héb. 10:38Hab 2:4
Héb. 10:392Pe 2:20
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
  • 39
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Hébérù 10:1-39

Sí Àwọn Hébérù

10 Nígbà tó jẹ́ pé Òfin ní òjìji+ àwọn nǹkan rere tó ń bọ̀,+ àmọ́ tí kì í ṣe bí àwọn nǹkan náà ṣe máa rí gan-an, kò lè* sọ àwọn tó ń wá sí tòsí di pípé láé nípasẹ̀ àwọn ẹbọ kan náà tí wọ́n ń rú léraléra láti ọdún dé ọdún.+ 2 Tí kò bá rí bẹ́ẹ̀, ṣé wọn ò ti ní dáwọ́ rírú àwọn ẹbọ náà dúró? Torí tí a bá ti wẹ àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ mọ́ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo, wọn ò ní mọ̀ ọ́n lára pé àwọn jẹ́ ẹlẹ́ṣẹ̀ mọ́. 3 Kàkà bẹ́ẹ̀, ṣe ni àwọn ẹbọ yìí ń ránni létí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ láti ọdún dé ọdún,+ 4 torí ẹ̀jẹ̀ àwọn akọ màlúù àti ti àwọn ewúrẹ́ kò lè mú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ kúrò.

5 Torí náà, nígbà tó wá sí ayé, ó sọ pé: “‘Ẹbọ àti ọrẹ kọ́ ni ohun tí o fẹ́, àmọ́ ìwọ pèsè ara kan fún mi. 6 O ò fọwọ́ sí àwọn odindi ẹbọ sísun àti ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.’+ 7 Lẹ́yìn náà, mo sọ pé: ‘Wò ó! Mo ti dé (a ti kọ ọ́ nípa mi sínú àkájọ ìwé*) láti ṣe ìfẹ́ rẹ, Ọlọ́run.’”+ 8 Lẹ́yìn tó kọ́kọ́ sọ pé: “O ò fẹ́ àwọn ẹbọ, ọrẹ, odindi ẹbọ sísun àti ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, o ò sì fọwọ́ sí i”—àwọn ẹbọ tí wọ́n ń rú, bí Òfin ṣe sọ— 9 ó wá sọ pé: “Wò ó! Mo ti dé láti ṣe ìfẹ́ rẹ.”+ Ó fi òpin sí èyí àkọ́kọ́ kó lè fìdí ìkejì múlẹ̀. 10 Nípasẹ̀ “ìfẹ́” yìí,+ a ti fi ara Jésù Kristi tó fi rúbọ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní ṣe é mọ́ láé sọ wá di mímọ́.+

11 Bákan náà, gbogbo àwọn àlùfáà máa ń lọ sẹ́nu iṣẹ́ wọn lójoojúmọ́ kí wọ́n lè ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́,*+ kí wọ́n sì lè rú àwọn ẹbọ kan náà léraléra,+ èyí tí kò lè mú ẹ̀ṣẹ̀ kúrò pátápátá.+ 12 Àmọ́ ẹbọ kan ṣoṣo ni ọkùnrin yìí rú fún ẹ̀ṣẹ̀ láìtún ní ṣe é mọ́ láé, ó sì jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ 13 látìgbà yẹn, ó ń dúró de ìgbà tí a máa fi àwọn ọ̀tá rẹ̀ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀.+ 14 Torí ẹbọ kan ṣoṣo tó rú ló fi sọ àwọn tí à ń sọ di mímọ́ di pípé+ láìtún ní ṣe é mọ́ láé. 15 Bákan náà, ẹ̀mí mímọ́ náà ń jẹ́rìí fún wa, torí lẹ́yìn tó sọ pé: 16 “‘Májẹ̀mú tí màá bá wọn dá lẹ́yìn ìgbà yẹn nìyí,’ ni Jèhófà* wí. ‘Màá fi àwọn òfin mi sínú ọkàn wọn, inú èrò wọn ni màá sì kọ ọ́ sí.’”+ 17 Ó wá sọ pé: “Mi ò sì ní rántí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́ àti àwọn ìwà wọn tí kò bófin mu.”+ 18 Torí náà, tí a bá ti dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yìí jini, kò tún sí ẹbọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mọ́.

19 Torí náà, ẹ̀yin ará, nígbà tó jẹ́ pé a ní ìgboyà* láti wá sí ọ̀nà tó wọnú ibi mímọ́+ nípasẹ̀ ẹ̀jẹ̀ Jésù, 20 èyí tó ṣí sílẹ̀* fún wa bí ọ̀nà tuntun, tó sì jẹ́ ọ̀nà ìyè tó la aṣọ ìdábùú kọjá,+ ìyẹn ẹran ara rẹ̀, 21 nígbà tó sì jẹ́ pé a ní àlùfáà ńlá lórí ilé Ọlọ́run,+ 22 ẹ jẹ́ ká fi ọkàn tòótọ́ àti ìgbàgbọ́ tó kún rẹ́rẹ́ wá, nígbà tí a ti wẹ ọkàn wa mọ́ kúrò nínú ẹ̀rí ọkàn burúkú,+ tí a sì ti fi omi tó mọ́ wẹ ara wa.+ 23 Ẹ jẹ́ ká tẹra mọ́ ìkéde ìrètí wa ní gbangba* láìṣiyèméjì,+ torí pé olóòótọ́ ni ẹni tó ṣèlérí. 24 Ẹ sì jẹ́ ká gba ti ara wa rò* ká lè máa fún ara wa níṣìírí* láti ní ìfẹ́ àti láti ṣe àwọn iṣẹ́ rere,+ 25 ká má ṣe máa kọ ìpàdé wa sílẹ̀,+ bí àṣà àwọn kan, àmọ́ ká máa gba ara wa níyànjú,+ ní pàtàkì jù lọ bí ẹ ṣe ń rí i pé ọjọ́ náà ń sún mọ́lé.+

26 Torí tí a bá mọ̀ọ́mọ̀ sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà lẹ́yìn tí a ti gba ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́,+ kò tún sí ẹbọ kankan fún ẹ̀ṣẹ̀ mọ́,+ 27 àfi ká máa fi ìbẹ̀rù retí ìdájọ́ àti ìbínú tó le, tó sì máa jó àwọn tó ń ṣàtakò run.+ 28 A kì í ṣàánú ẹnikẹ́ni tí kò bá ka Òfin Mósè sí, ó máa kú tí ẹni méjì tàbí mẹ́ta bá ti jẹ́rìí sí i.+ 29 Báwo lẹ ṣe wá rò pé ó yẹ kí ìyà tó máa jẹ ẹni tó tẹ Ọmọ Ọlọ́run mọ́lẹ̀ pọ̀ tó, tó ti ka ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú+ tí a fi sọ ọ́ di mímọ́ sí nǹkan yẹpẹrẹ, tó sì fi ìwà àfojúdi mú ẹ̀mí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí bínú?+ 30 Torí a mọ Ẹni tó sọ pé: “Tèmi ni ẹ̀san; màá gbẹ̀san.” Àti pé: “Jèhófà* máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn rẹ̀.”+ 31 Ohun tó ń bani lẹ́rù ló jẹ́ láti kó sí ọwọ́ Ọlọ́run alààyè.

32 Àmọ́, ẹ máa rántí àwọn ọjọ́ àtijọ́, tí ẹ fara da ìjàkadì ńlá pẹ̀lú ìyà, lẹ́yìn tí a là yín lóye.+ 33 Nígbà míì, wọ́n máa ń tú yín síta gbangba* fún ẹ̀gàn àti ìpọ́njú, nígbà míì sì rèé, ẹ máa ń ṣe alábàápín pẹ̀lú* àwọn tí irú nǹkan bẹ́ẹ̀ ṣẹlẹ̀ sí. 34 Torí ẹ bá àwọn tó wà ní ẹ̀wọ̀n kẹ́dùn, ẹ sì fi ayọ̀ gba bí wọ́n ṣe kó ẹrù yín,+ torí ẹ mọ̀ pé ẹ̀yin fúnra yín ní ohun ìní tó dáa jù, tó sì wà pẹ́ títí.+

35 Torí náà, ẹ má sọ ìgboyà yín* nù, èyí tí a máa torí rẹ̀ fún yín ní èrè tó kún rẹ́rẹ́.+ 36 Nítorí ẹ nílò ìfaradà,+ pé lẹ́yìn tí ẹ ti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run, kí ẹ lè rí ohun tí ó ṣèlérí náà gbà. 37 Torí ní “ìgbà díẹ̀ sí i”+ àti pé “ẹni tó ń bọ̀ máa dé, kò sì ní pẹ́.”+ 38 “Àmọ́ ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo mi wà láàyè”+ àti pé “tó bá fà sẹ́yìn, inú mi* ò ní dùn sí i.”+ 39 Ní báyìí, a kì í ṣe irú àwọn tó ń fà sẹ́yìn sí ìparun,+ àmọ́ irú àwọn tó ní ìgbàgbọ́ kí a lè dá ẹ̀mí* wa sí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́