ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 37
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Hẹsikáyà ní kí Àìsáyà bá òun bẹ Ọlọ́run fún ìrànlọ́wọ́ (1-7)

      • Senakérúbù halẹ̀ mọ́ Jerúsálẹ́mù (8-13)

      • Àdúrà tí Hẹsikáyà gbà (14-20)

      • Àìsáyà sọ ohun tí Ọlọ́run sọ (21-35)

      • Áńgẹ́lì kan pa 185,000 àwọn ọmọ Ásíríà (36-38)

Àìsáyà 37:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “aṣọ àpò ìdọ̀họ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 19:1-4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 389-390

Àìsáyà 37:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ààfin.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 26:22; Ais 1:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 389-390

Àìsáyà 37:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “èébú.”

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ ti dé ẹnu ilé ọmọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 26:17, 18

Àìsáyà 37:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 17:45; 2Ọb 18:28, 35
  • +2Kr 32:20; Sm 50:15; Joẹ 2:17
  • +2Ọb 17:18

Àìsáyà 37:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 19:5-7

Àìsáyà 37:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìránṣẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 20:1
  • +2Ọb 18:17

Àìsáyà 37:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹ̀mí kan sínú rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 21:1
  • +2Kr 32:21; Ais 37:37, 38

Àìsáyà 37:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 10:29, 30; 2Ọb 8:22; 19:8-13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 391

Àìsáyà 37:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 18:17

Àìsáyà 37:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 32:15

Àìsáyà 37:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:5, 6; 2Kr 32:13; Ais 10:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 391

Àìsáyà 37:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 36:19
  • +Jẹ 11:31

Àìsáyà 37:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:24; Ais 36:19

Àìsáyà 37:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 19:14-19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 391

Àìsáyà 37:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 8:30; 2Kr 6:20; 20:9; Da 9:3

Àìsáyà 37:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “láàárín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 46:7; Ais 8:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 9/2022,

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1996, ojú ìwé 9

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 26-27

Àìsáyà 37:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 6:40; Sm 65:2
  • +2Kr 16:9; 1Pe 3:12
  • +Ais 37:4

Àìsáyà 37:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 15:29; 16:8, 9; 1Kr 5:26

Àìsáyà 37:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 10:11
  • +Ais 40:19; 41:7; Jer 10:3; Ho 8:6; Iṣe 17:29

Àìsáyà 37:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:31, 39; Sm 83:18; 96:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 391

Àìsáyà 37:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 19:20, 21

Àìsáyà 37:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 391-392

Àìsáyà 37:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 19:4, 16
  • +2Ọb 18:30, 35; Ais 10:12, 13
  • +Ẹk 15:11; 2Ọb 19:22-24; Ais 10:20; Isk 39:7

Àìsáyà 37:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 32:17
  • +Ais 10:10, 11

Àìsáyà 37:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ipa odò Náílì.”

Àìsáyà 37:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ni mo ti ṣe é.”

  • *

    Tàbí “mọ ọ́n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 33:11; Ais 46:10
  • +Ais 55:10, 11
  • +2Ọb 19:25, 26

Àìsáyà 37:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 5:21; 15:3; Heb 4:13
  • +2Ọb 19:27, 28

Àìsáyà 37:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 46:6; Ais 10:15; 37:23
  • +Ais 36:4, 20
  • +Sm 32:9

Àìsáyà 37:30

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Hẹsikáyà.

  • *

    Tàbí “hóró ọkà tó dà sílẹ̀ tó lalẹ̀ hù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 19:29-31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 392

Àìsáyà 37:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 1:9; 10:20, 21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 392

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    8/15/1994, ojú ìwé 31

Àìsáyà 37:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 19:4
  • +Ais 59:17; Joẹ 2:18; Sek 1:14, 15

Àìsáyà 37:33

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 10:24
  • +2Kr 32:22; Ais 10:32
  • +2Ọb 19:32-34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 393-394

Àìsáyà 37:34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 393-394

Àìsáyà 37:35

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 31:5
  • +Di 32:27; 1Sa 12:22; 2Ọb 20:6; Isk 36:22
  • +1Ọb 15:4

Àìsáyà 37:36

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 19:35-37; 2Kr 32:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1993, ojú ìwé 6

    2/1/1991, ojú ìwé 17

Àìsáyà 37:37

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:8, 11; Jon 1:2
  • +2Ọb 19:7, 28

Àìsáyà 37:38

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tẹ́ńpìlì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 32:21
  • +Jẹ 8:4
  • +Ẹsr 4:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2003, ojú ìwé 11

Àwọn míì

Àìsá. 37:12Ọb 19:1-4
Àìsá. 37:22Kr 26:22; Ais 1:1
Àìsá. 37:3Ais 26:17, 18
Àìsá. 37:41Sa 17:45; 2Ọb 18:28, 35
Àìsá. 37:42Kr 32:20; Sm 50:15; Joẹ 2:17
Àìsá. 37:42Ọb 17:18
Àìsá. 37:52Ọb 19:5-7
Àìsá. 37:6Di 20:1
Àìsá. 37:62Ọb 18:17
Àìsá. 37:7Owe 21:1
Àìsá. 37:72Kr 32:21; Ais 37:37, 38
Àìsá. 37:8Joṣ 10:29, 30; 2Ọb 8:22; 19:8-13
Àìsá. 37:92Ọb 18:17
Àìsá. 37:102Kr 32:15
Àìsá. 37:112Ọb 17:5, 6; 2Kr 32:13; Ais 10:11
Àìsá. 37:12Ais 36:19
Àìsá. 37:12Jẹ 11:31
Àìsá. 37:132Ọb 17:24; Ais 36:19
Àìsá. 37:142Ọb 19:14-19
Àìsá. 37:151Ọb 8:30; 2Kr 6:20; 20:9; Da 9:3
Àìsá. 37:16Sm 46:7; Ais 8:13
Àìsá. 37:172Kr 6:40; Sm 65:2
Àìsá. 37:172Kr 16:9; 1Pe 3:12
Àìsá. 37:17Ais 37:4
Àìsá. 37:182Ọb 15:29; 16:8, 9; 1Kr 5:26
Àìsá. 37:19Ais 10:11
Àìsá. 37:19Ais 40:19; 41:7; Jer 10:3; Ho 8:6; Iṣe 17:29
Àìsá. 37:20Di 32:31, 39; Sm 83:18; 96:5
Àìsá. 37:212Ọb 19:20, 21
Àìsá. 37:232Ọb 19:4, 16
Àìsá. 37:232Ọb 18:30, 35; Ais 10:12, 13
Àìsá. 37:23Ẹk 15:11; 2Ọb 19:22-24; Ais 10:20; Isk 39:7
Àìsá. 37:242Kr 32:17
Àìsá. 37:24Ais 10:10, 11
Àìsá. 37:26Sm 33:11; Ais 46:10
Àìsá. 37:26Ais 55:10, 11
Àìsá. 37:262Ọb 19:25, 26
Àìsá. 37:28Owe 5:21; 15:3; Heb 4:13
Àìsá. 37:282Ọb 19:27, 28
Àìsá. 37:29Sm 46:6; Ais 10:15; 37:23
Àìsá. 37:29Ais 36:4, 20
Àìsá. 37:29Sm 32:9
Àìsá. 37:302Ọb 19:29-31
Àìsá. 37:31Ais 1:9; 10:20, 21
Àìsá. 37:322Ọb 19:4
Àìsá. 37:32Ais 59:17; Joẹ 2:18; Sek 1:14, 15
Àìsá. 37:33Ais 10:24
Àìsá. 37:332Kr 32:22; Ais 10:32
Àìsá. 37:332Ọb 19:32-34
Àìsá. 37:35Ais 31:5
Àìsá. 37:35Di 32:27; 1Sa 12:22; 2Ọb 20:6; Isk 36:22
Àìsá. 37:351Ọb 15:4
Àìsá. 37:362Ọb 19:35-37; 2Kr 32:21
Àìsá. 37:37Jẹ 10:8, 11; Jon 1:2
Àìsá. 37:372Ọb 19:7, 28
Àìsá. 37:382Kr 32:21
Àìsá. 37:38Jẹ 8:4
Àìsá. 37:38Ẹsr 4:1, 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 37:1-38

Àìsáyà

37 Gbàrà tí Ọba Hẹsikáyà gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, ó fa ẹ̀wù rẹ̀ ya, ó fi aṣọ ọ̀fọ̀* bora, ó sì lọ sínú ilé Jèhófà.+ 2 Lẹ́yìn náà, ó rán Élíákímù, ẹni tó ń bójú tó agbo ilé* àti Ṣébínà akọ̀wé pẹ̀lú àwọn àgbààgbà nínú àwọn àlùfáà, wọ́n fi aṣọ ọ̀fọ̀ bora, ó sì rán wọn sí wòlíì Àìsáyà,+ ọmọ Émọ́ọ̀sì. 3 Wọ́n sọ fún un pé: “Ohun tí Hẹsikáyà sọ nìyí, ‘Ọjọ́ òní jẹ́ ọjọ́ wàhálà àti ti ìbáwí* àti ti ìtìjú; nítorí a dà bí aboyún tó fẹ́ bímọ,* àmọ́ tí kò ní okun láti bí i.+ 4 Bóyá Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa gbọ́ ọ̀rọ̀ Rábúṣákè tí olúwa rẹ̀ ọba Ásíríà rán láti pẹ̀gàn Ọlọ́run alààyè,+ tí á sì pè é wá jíhìn nítorí àwọn ọ̀rọ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti gbọ́. Torí náà, gbàdúrà+ nítorí àṣẹ́kù tó yè bọ́ yìí.’”+

5 Nítorí náà, àwọn ìránṣẹ́ Ọba Hẹsikáyà lọ sọ́dọ̀ Àìsáyà,+ 6 Àìsáyà sì sọ fún wọn pé: “Ẹ sọ fún olúwa yín pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Má bẹ̀rù+ nítorí àwọn ọ̀rọ̀ tí o gbọ́, àwọn ọ̀rọ̀ tí àwọn ẹmẹ̀wà* ọba Ásíríà+ fi pẹ̀gàn mi. 7 Wò ó, màá fi ohun kan sí i lọ́kàn,* ó máa gbọ́ ìròyìn kan, á sì pa dà sí ilẹ̀ rẹ̀;+ màá sì jẹ́ kí wọ́n fi idà pa á ní ilẹ̀ òun fúnra rẹ̀.”’”+

8 Lẹ́yìn tí Rábúṣákè gbọ́ pé ọba Ásíríà ti kúrò ní Lákíṣì, ó pa dà sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì rí i tó ń bá Líbínà jà.+ 9 Ọba wá gbọ́ tí wọ́n sọ nípa Tíhákà ọba Etiópíà pé: “Ó ti jáde láti wá bá ọ jà.” Nígbà tó gbọ́, ó tún rán àwọn òjíṣẹ́ sí Hẹsikáyà+ pé: 10 “Ẹ sọ fún Hẹsikáyà ọba Júdà pé, ‘Má ṣe jẹ́ kí Ọlọ́run rẹ tí o gbẹ́kẹ̀ lé tàn ọ́ jẹ pé: “A kò ní fi Jerúsálẹ́mù lé ọba Ásíríà lọ́wọ́.”+ 11 Wò ó! O ti gbọ́ ohun tí àwọn ọba Ásíríà ṣe sí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè, bí wọ́n ṣe pa wọ́n run.+ Ṣé o rò pé ìwọ lè bọ́ lọ́wọ́ wa ni? 12 Ǹjẹ́ àwọn ọlọ́run àwọn orílẹ̀-èdè tí àwọn baba ńlá mi pa run gbà wọ́n?+ Ibo ni Gósánì, Háránì,+ Réséfù àti àwọn èèyàn Édẹ́nì tó wà ní Tẹli-ásárì wà? 13 Ibo ni ọba Hámátì, ọba Áápádì, ọba àwọn ìlú Séfáfáímù,+ ọba Hénà àti ọba Ífà wà?’”

14 Hẹsikáyà gba àwọn lẹ́tà náà lọ́wọ́ àwọn òjíṣẹ́ náà, ó sì kà wọ́n. Lẹ́yìn náà, Hẹsikáyà lọ sí ilé Jèhófà, ó sì tẹ́ wọn* síwájú Jèhófà.+ 15 Hẹsikáyà wá bẹ̀rẹ̀ sí í gbàdúrà sí Jèhófà,+ ó sọ pé: 16 “Ìwọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,+ Ọlọ́run Ísírẹ́lì, tí o jókòó sórí ìtẹ́ lókè* àwọn kérúbù, ìwọ nìkan ni Ọlọ́run tòótọ́ lórí gbogbo ìjọba ayé. Ìwọ lo dá ọ̀run àti ayé. 17 Fetí sílẹ̀, Jèhófà, kí o sì gbọ́!+ La ojú rẹ, Jèhófà, kí o sì rí i!+ Kí o gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tí Senakérúbù fi ránṣẹ́ láti pẹ̀gàn Ọlọ́run alààyè.+ 18 Jèhófà, òótọ́ ni pé àwọn ọba Ásíríà ti pa gbogbo ilẹ̀ run,+ títí kan ilẹ̀ wọn. 19 Wọ́n sì ti ju àwọn ọlọ́run wọn sínú iná,+ nítorí wọn kì í ṣe ọlọ́run, iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn ni wọ́n,+ wọ́n jẹ́ igi àti òkúta. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi lè pa wọ́n run. 20 Àmọ́ ní báyìí, ìwọ Jèhófà Ọlọ́run wa, gbà wá lọ́wọ́ rẹ̀, kí gbogbo ìjọba ayé lè mọ̀ pé ìwọ Jèhófà nìkan ṣoṣo ni Ọlọ́run.”+

21 Àìsáyà ọmọ Émọ́ọ̀sì wá ránṣẹ́ sí Hẹsikáyà pé: “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Torí pé o gbàdúrà sí mi nítorí Senakérúbù ọba Ásíríà,+ 22 ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ nípa rẹ̀ nìyí:

“Wúńdíá ọmọbìnrin Síónì pẹ̀gàn rẹ, ó ti fi ọ́ ṣẹ̀sín.

Ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù mi orí rẹ̀ sí ọ.

23 Ta lo pẹ̀gàn,+ tí o sì sọ̀rọ̀ òdì sí?

Ta lo gbé ohùn rẹ sókè sí,+

Tí o sì gbé ojú rẹ ga sí?

Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì mà ni!+

24 O tipasẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ pẹ̀gàn Jèhófà,+ o sọ pé,

‘Pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn kẹ̀kẹ́ ogun mi,

Màá gun ibi gíga àwọn òkè,+

Ibi tó jìnnà jù lọ ní Lẹ́bánónì.

Ṣe ni màá gé àwọn igi kédárì rẹ̀ tó ga fíofío lulẹ̀, àwọn ààyò igi júnípà rẹ̀.

Màá wọ ibi tó ga jù tó máa ń sá sí, igbó kìjikìji rẹ̀.

25 Màá gbẹ́ kànga, màá sì mu omi;

Màá fi àtẹ́lẹsẹ̀ mi mú kí àwọn odò* Íjíbítì gbẹ.’

26 Ṣé o ò tíì gbọ́ ni? Tipẹ́tipẹ́ ni mo ti pinnu rẹ̀.*

Láti ọ̀pọ̀ ọjọ́ sẹ́yìn ni mo ti ṣètò rẹ̀.*+

Ní báyìí, màá ṣe é.+

Wàá sọ àwọn ìlú olódi di àwókù.+

27 Àwọn tó ń gbé inú wọn á di aláìlágbára;

Jìnnìjìnnì á bá wọn, ojú á sì tì wọ́n.

Wọ́n á rọ bí ewéko pápá àti bí koríko tútù ṣe máa ń rọ,

Bíi koríko orí òrùlé tí atẹ́gùn ìlà oòrùn ti jó gbẹ.

28 Àmọ́, mo mọ ìgbà tí o bá jókòó, ìgbà tí o bá jáde àti ìgbà tí o bá wọlé+

Àti ìgbà tí inú rẹ bá ru sí mi,+

29 Torí bí inú rẹ ṣe ń ru sí mi+ àti bí o ṣe ń ké ramúramù ti dé etí mi.+

Torí náà, màá fi ìwọ̀ mi kọ́ imú rẹ, màá fi ìjánu+ mi sáàárín ètè rẹ,

Ọ̀nà tí o gbà wá ni màá sì mú ọ gbà pa dà.”

30 “‘Ohun tó máa jẹ́ àmì fún ọ* nìyí: Lọ́dún yìí, ẹ ó jẹ ohun tó lalẹ̀ hù;* ní ọdún kejì, ọkà tó hù látinú ìyẹn ni ẹ ó jẹ; àmọ́ ní ọdún kẹta, ẹ ó fúnrúgbìn, ẹ ó sì kórè, ẹ ó gbin àwọn ọgbà àjàrà, ẹ ó sì jẹ èso wọn.+ 31 Ìyókù àwọn ará ilé Júdà tó sá àsálà+ máa ta gbòǹgbò nísàlẹ̀, wọ́n á sì so èso lókè. 32 Nítorí àṣẹ́kù kan máa jáde wá láti Jerúsálẹ́mù, àwọn tó là á já sì máa jáde wá láti Òkè Síónì.+ Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa ṣe èyí.+

33 “‘Torí náà, ohun tí Jèhófà sọ nípa ọba Ásíríà+ nìyí:

“Kò ní wọ inú ìlú yìí,+

Bẹ́ẹ̀ ni kò ní ta ọfà sí ibẹ̀,

Tàbí kó fi apata dojú kọ ọ́,

Bẹ́ẹ̀ sì ni kò ní mọ òkìtì láti dó tì í.”’+

34 ‘Ọ̀nà tó gbà wá ló máa gbà pa dà;

Kò ní wọ inú ìlú yìí,’ ni Jèhófà wí.

35 ‘Màá gbèjà ìlú yìí,+ màá sì gbà á sílẹ̀ nítorí orúkọ mi+

Àti nítorí Dáfídì ìránṣẹ́ mi.’”+

36 Áńgẹ́lì Jèhófà wá jáde lọ, ó sì pa ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án ó lé ẹgbẹ̀rún márùn-ún (185,000) ọkùnrin nínú ibùdó àwọn ará Ásíríà. Nígbà tí àwọn èèyàn jí láàárọ̀ kùtù, wọ́n rí òkú nílẹ̀ bẹẹrẹbẹ.+ 37 Torí náà, Senakérúbù ọba Ásíríà kúrò níbẹ̀, ó pa dà sí Nínéfè,+ ó sì ń gbé ibẹ̀.+ 38 Bó ṣe ń forí balẹ̀ ní ilé* Nísírọ́kì ọlọ́run rẹ̀, àwọn ọmọ rẹ̀, Adiramélékì àti Ṣárésà fi idà pa á,+ wọ́n sì sá lọ sí ilẹ̀ Árárátì.+ Esari-hádónì+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́