ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Pétérù 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Pétérù

      • Àwọn olùkọ́ èké máa wá (1-3)

      • Ìdájọ́ àwọn olùkọ́ èké kò ní yẹ̀ (4-10a)

        • Ọlọ́run ju àwọn áńgẹ́lì sínú Tátárọ́sì (4)

        • Ìkún Omi; Sódómù àti Gòmórà (5-7)

      • Bí a ṣe lè dá àwọn olùkọ́ èké mọ̀ (10b-22)

2 Pétérù 2:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 24:24; 1Ti 4:1
  • +1Kọ 6:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2011, ojú ìwé 15-16

    3/1/2006, ojú ìwé 6

    9/1/2004, ojú ìwé 15

    9/1/1997, ojú ìwé 13-14

    Yiyan, ojú ìwé 148-151

2 Pétérù 2:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìwà ọ̀dájú.” Ó ń tọ́ka sí ọ̀rọ̀ Gíríìkì náà, a·selʹgei·a tí wọ́n bá lò ó fún ohun tó ju ẹyọ kan lọ. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 4
  • +Ais 52:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 14

    Yiyan, ojú ìwé 151-152

2 Pétérù 2:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ìparun wọn ò sì ní sùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 4
  • +2Pe 3:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2011, ojú ìwé 15-16

    9/1/2004, ojú ìwé 15

    9/1/1997, ojú ìwé 14-15

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 89

    Yiyan, ojú ìwé 152-153

2 Pétérù 2:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ọ̀gbun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 6:4; Ef 6:12
  • +1Pe 3:19, 20
  • +Jud 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1716

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 22

    1/15/2006, ojú ìwé 7

    12/15/2003, ojú ìwé 28

    9/1/1997, ojú ìwé 15

    3/15/1991, ojú ìwé 31

    Yiyan, ojú ìwé 152-154

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 55, 74-75

2 Pétérù 2:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 7:23
  • +Jẹ 6:9; Heb 11:7
  • +Jẹ 8:18
  • +2Pe 3:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2021, ojú ìwé 26-27

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2018, ojú ìwé 19

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2017, ojú ìwé 9

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2016, ojú ìwé 27-28

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2013, ojú ìwé 14

    6/1/2008, ojú ìwé 6

    12/15/2003, ojú ìwé 18

    10/1/2003, ojú ìwé 20-21

    11/15/2001, ojú ìwé 30

    12/15/1998, ojú ìwé 10-11

    10/15/1997, ojú ìwé 29

    9/1/1997, ojú ìwé 15

    2/15/1995, ojú ìwé 13

    9/15/1992, ojú ìwé 23

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 20

2 Pétérù 2:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 19:24, 25
  • +Jud 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2003, ojú ìwé 20-21

    9/1/1997, ojú ìwé 15

2 Pétérù 2:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìwà ọ̀dájú.” Ní Gíríìkì, a·selʹgei·a. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 19:15, 16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1704

2 Pétérù 2:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

2 Pétérù 2:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Ní Grk., “ìkékúrò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 34:19; 1Kọ 10:13; 2Ti 4:18; Ifi 3:10
  • +Ro 2:5; 2Pe 3:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2012, ojú ìwé 22-26

    Yiyan, ojú ìwé 164

2 Pétérù 2:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tí wọ́n sì fojú kéré ipò àṣẹ wọn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 7
  • +Ẹk 22:28; Jud 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 22

    6/15/2000, ojú ìwé 16

    9/1/1997, ojú ìwé 15-16

    Yiyan, ojú ìwé 152-155

2 Pétérù 2:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wọ́n ń fi ọ̀wọ̀ hàn níwájú.”

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2009, ojú ìwé 23

    6/15/2000, ojú ìwé 16

    9/1/1997, ojú ìwé 16

    Jí!,

    6/8/2003, ojú ìwé 28

    Yiyan, ojú ìwé 154-155

2 Pétérù 2:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wọ́n bí wọn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 155-156

2 Pétérù 2:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wọ́n jẹ́ àwọn tí a bí sínú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 13:13
  • +Jud 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 16-17

    Yiyan, ojú ìwé 155-158

2 Pétérù 2:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 16-17

    Yiyan, ojú ìwé 156, 158-159

2 Pétérù 2:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 22:5, 6; Jud 11; Ifi 2:14
  • +Nọ 22:7; Ne 13:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 17

    Yiyan, ojú ìwé 159-160

2 Pétérù 2:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 22:31, 34; 31:8
  • +Nọ 22:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 3/2021, ojú ìwé 1

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 17

    Yiyan, ojú ìwé 159-160

2 Pétérù 2:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 12, 13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 17-18

    Yiyan, ojú ìwé 160

2 Pétérù 2:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìwà ọ̀dájú.” Ó ń tọ́ka sí ọ̀rọ̀ Gíríìkì náà, a·selʹgei·a tí wọ́n bá lò ó fún ohun tó ju ẹyọ kan lọ. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 16
  • +2Pe 2:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 17-18

    Yiyan, ojú ìwé 160

2 Pétérù 2:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹnikẹ́ni tí ohun kan bá borí rẹ̀ jẹ́ ẹrú ohun náà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 2:16
  • +Ro 6:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 17-18

    Yiyan, ojú ìwé 160-164

2 Pétérù 2:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Pe 1:4
  • +Heb 6:4-6; 10:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2006, ojú ìwé 31

    9/1/1997, ojú ìwé 18

    Yiyan, ojú ìwé 165-166

2 Pétérù 2:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 12:47; Jo 15:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 165-166

2 Pétérù 2:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 26:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 165, 166-167

Àwọn míì

2 Pét. 2:1Mt 24:24; 1Ti 4:1
2 Pét. 2:11Kọ 6:20
2 Pét. 2:2Jud 4
2 Pét. 2:2Ais 52:5
2 Pét. 2:3Jud 4
2 Pét. 2:32Pe 3:9
2 Pét. 2:4Jẹ 6:4; Ef 6:12
2 Pét. 2:41Pe 3:19, 20
2 Pét. 2:4Jud 6
2 Pét. 2:5Jẹ 7:23
2 Pét. 2:5Jẹ 6:9; Heb 11:7
2 Pét. 2:5Jẹ 8:18
2 Pét. 2:52Pe 3:6
2 Pét. 2:6Jẹ 19:24, 25
2 Pét. 2:6Jud 7
2 Pét. 2:7Jẹ 19:15, 16
2 Pét. 2:9Sm 34:19; 1Kọ 10:13; 2Ti 4:18; Ifi 3:10
2 Pét. 2:9Ro 2:5; 2Pe 3:7
2 Pét. 2:10Jud 7
2 Pét. 2:10Ẹk 22:28; Jud 8
2 Pét. 2:11Jud 9
2 Pét. 2:12Jud 10
2 Pét. 2:13Ro 13:13
2 Pét. 2:13Jud 12
2 Pét. 2:14Mt 5:28
2 Pét. 2:15Nọ 22:5, 6; Jud 11; Ifi 2:14
2 Pét. 2:15Nọ 22:7; Ne 13:2
2 Pét. 2:16Nọ 22:31, 34; 31:8
2 Pét. 2:16Nọ 22:28
2 Pét. 2:17Jud 12, 13
2 Pét. 2:18Jud 16
2 Pét. 2:182Pe 2:14
2 Pét. 2:191Pe 2:16
2 Pét. 2:19Ro 6:16
2 Pét. 2:202Pe 1:4
2 Pét. 2:20Heb 6:4-6; 10:26
2 Pét. 2:21Lk 12:47; Jo 15:22
2 Pét. 2:22Owe 26:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Pétérù 2:1-22

Ìwé Kejì Pétérù

2 Àmọ́ o, àwọn wòlíì èké tún wà láàárín àwọn èèyàn náà, bí àwọn olùkọ́ èké ṣe máa wà láàárín ẹ̀yin náà.+ Àwọn yìí máa dọ́gbọ́n mú àwọn ẹ̀ya ìsìn tó ń fa ìparun wọlé, wọ́n tiẹ̀ máa sẹ́ ẹni tó rà wọ́n pàápàá,+ wọ́n á sì mú ìparun wá sórí ara wọn ní kíákíá. 2 Yàtọ̀ síyẹn, ọ̀pọ̀ máa hu ìwà àìnítìjú*+ bíi tiwọn, àwọn èèyàn sì máa sọ̀rọ̀ àbùkù sí ọ̀nà òtítọ́ nítorí wọn.+ 3 Bákan náà, torí wọ́n jẹ́ olójúkòkòrò, wọ́n máa fi àwọn ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn kó yín nífà. Àmọ́ ìdájọ́ wọn tí a ti ṣe tipẹ́tipẹ́+ ò falẹ̀, ìparun wọn ò sì ní yẹ̀.*+

4 Ó dájú pé Ọlọ́run kò fawọ́ sẹ́yìn láti fìyà jẹ àwọn áńgẹ́lì tó ṣẹ̀,+ àmọ́ ó jù wọ́n sínú Tátárọ́sì,*+ ó fi wọ́n sí ìdè* òkùnkùn biribiri de ìdájọ́.+ 5 Kò sì fawọ́ sẹ́yìn láti fìyà jẹ ayé ìgbàanì,+ àmọ́ ó dá ẹ̀mí Nóà, oníwàásù òdodo sí+ pẹ̀lú àwọn méje míì  + nígbà tó mú ìkún omi wá sórí ayé àwọn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.+ 6 Ó mú kí ìlú Sódómù àti Gòmórà jóná di eérú, ó tipa bẹ́ẹ̀ dá wọn lẹ́bi,+ ìyẹn sì jẹ́ àpẹẹrẹ àwọn nǹkan tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.+ 7 Ó gba Lọ́ọ̀tì olódodo là,+ ẹni tó banú jẹ́ gidigidi nítorí ìwà àìnítìjú* àwọn arúfin èèyàn— 8 torí ojoojúmọ́ ni ọkùnrin olódodo yẹn ń mú kí ọkàn* rẹ̀ gbọgbẹ́ nítorí ohun tó rí àti ohun tó gbọ́ tí àwọn arúfin yẹn ń ṣe nígbà tó ń gbé láàárín wọn. 9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+ 10 ní pàtàkì àwọn tó ń wá bí wọ́n ṣe máa sọ ẹran ara àwọn míì di aláìmọ́,+ tí wọn ò sì ka àwọn aláṣẹ sí.*+

Wọ́n gbójúgbóyà, wọ́n jẹ́ aṣetinú-ẹni, wọn ò sì bẹ̀rù láti sọ̀rọ̀ àwọn ẹni ògo láìdáa, 11 bẹ́ẹ̀ sì rèé àwọn áńgẹ́lì, tí wọ́n tiẹ̀ ní okun àti agbára jù wọ́n lọ, kì í sọ̀rọ̀ àbùkù nípa wọn tí wọ́n bá ń fẹ̀sùn kàn wọ́n, torí wọ́n bọ̀wọ̀ fún* Jèhófà.*+ 12 Àmọ́ àwọn èèyàn yìí ń sọ̀rọ̀ tí kò dáa nípa àwọn ohun tí wọn ò mọ̀,+ wọ́n dà bí àwọn ẹranko tí kì í ronú, tí wọ́n kàn máa ń ṣe ohun tí a dá mọ́ wọn, wọ́n wà* ká lè mú wọn, ká sì pa wọ́n. Ọ̀nà ìparun tí wọ́n ń tọ̀ máa mú ìparun wá sórí wọn, 13 àwọn ìwà burúkú tí wọ́n ń hù sì máa kóyà jẹ wọ́n.

Kódà ní ojúmọmọ, wọ́n ka ìgbésí ayé gbẹdẹmukẹ sí ìgbádùn.+ Èérí àti àbààwọ́n ni wọ́n, wọ́n ń gbádùn* àwọn ẹ̀kọ́ tí wọ́n fi ń tanni jẹ, bí wọ́n ṣe ń bá yín jẹ àsè.+ 14 Àgbèrè ló kún ojú wọn,+ wọn ò lè jáwọ́ nínú ẹ̀ṣẹ̀, wọ́n sì ń tan àwọn* tí kò dúró ṣinṣin jẹ. Wọ́n ti fi ojúkòkòrò kọ́ ọkàn wọn. Ọmọ ègún ni wọ́n. 15 Wọ́n pa ọ̀nà tó tọ́ tì, a sì ti ṣì wọ́n lọ́nà. Wọ́n ṣe bíi ti Báláámù,+ ọmọ Béórì, ẹni tó nífẹ̀ẹ́ èrè ìwà àìtọ́,+ 16 àmọ́ a bá a wí torí ó ṣe ohun tí kò tọ́.+ Ẹran akẹ́rù tí kò lè sọ̀rọ̀ tó sọ̀rọ̀ bí èèyàn, kò jẹ́ kí wòlíì náà ṣe ohun tí kò bọ́gbọ́n mu.+

17 Wọ́n jẹ́ ìsun tí kò lómi àti ìkùukùu tí ìjì líle ń fẹ́ kiri, a sì ti fi òkùnkùn biribiri pa mọ́ dè wọ́n.+ 18 Wọ́n ń sọ̀rọ̀ kàǹkà-kàǹkà tí kò nítumọ̀. Wọ́n ń fi ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ara+ àti ìwà àìnítìjú* tan àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ bọ́ lọ́wọ́ àwọn tó ń fi ẹ̀ṣẹ̀ ṣomi mu.+ 19 Wọ́n ń ṣèlérí òmìnira fún wọn, àmọ́ ẹrú ìwà ìbàjẹ́ làwọn fúnra wọn;+ torí ẹnikẹ́ni tí ẹlòmíì bá borí jẹ́ ẹrú ẹni tó borí rẹ̀.*+ 20 Ó dájú pé, lẹ́yìn tí ìmọ̀ tó péye nípa Jésù Kristi Olúwa àti Olùgbàlà bá ti mú kí wọ́n bọ́ lọ́wọ́ àwọn ẹ̀gbin ayé,+ tí wọ́n bá tún pa dà sí àwọn nǹkan yìí tó sì borí wọn, ìgbẹ̀yìn wọn ti burú ju ìbẹ̀rẹ̀ wọn.+ 21 Torí ì bá sàn kí wọ́n má mọ ọ̀nà òdodo lọ́nà tó péye ju pé lẹ́yìn tí wọ́n ti mọ̀ ọ́n kí wọ́n yí pa dà kúrò nínú àṣẹ mímọ́ tí wọ́n ti gbà.+ 22 Ohun tí òwe tòótọ́ náà sọ ti ṣẹlẹ̀ sí wọn: “Ajá ti pa dà sídìí èébì rẹ̀, abo ẹlẹ́dẹ̀ tí a ti wẹ̀ ti ń yíra mọ́lẹ̀ nínú ẹrẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́