ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Bàbá kan àti àwọn ọmọ rẹ̀ tó ya ọlọ̀tẹ̀ (1-9)

      • Jèhófà kórìíra ìjọsìn ojú lásán (10-17)

      • “Ẹ jẹ́ ká yanjú ọ̀rọ̀” (18-20)

      • Síónì máa pa dà di ìlú olóòótọ́ (21-31)

Àìsáyà 1:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ìgbàlà Jèhófà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 32:32
  • +2Kr 26:22; Ais 6:1
  • +2Kr 27:1, 2
  • +2Kr 28:1
  • +2Kr 29:1, 2; 32:20
  • +Mt 1:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 12-13

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 7-8

Àìsáyà 1:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 50:4
  • +Di 1:31
  • +Di 4:25, 26; Isk 20:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 11-12

Àìsáyà 1:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mọ olúwa rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ho 4:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2006, ojú ìwé 9-10

    10/15/1992, ojú ìwé 24

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 12-14

Àìsáyà 1:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 9:11
  • +Di 31:16; Jer 2:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 14-15

Àìsáyà 1:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 5:3
  • +Ne 9:34, 35; Da 9:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 15-16

Àìsáyà 1:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “tẹ̀ wọ́n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 10:34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 15-17

Àìsáyà 1:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:33, 63
  • +2Ọb 18:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 17-18

Àìsáyà 1:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “apálá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 18:13, 14; Ais 8:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2006, ojú ìwé 8-9

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 18-19

Àìsáyà 1:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 19:24, 25; Di 29:22, 23; Ro 9:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 19-21

Àìsáyà 1:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “alákòóso.”

  • *

    Tàbí “ìtọ́ni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 13:13; Ais 3:8, 9
  • +Di 32:32; Jud 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 22

Àìsáyà 1:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 15:22; Owe 15:8; Ho 6:6; Mik 6:7
  • +Ẹk 29:38
  • +Le 3:14-16
  • +Le 17:11
  • +Le 4:18, 21
  • +Le 16:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 22-23

Àìsáyà 1:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 16:16
  • +Onw 5:1; Mal 1:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 23

Àìsáyà 1:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 21:27; Isk 8:11, 12
  • +Nọ 28:11
  • +Ẹk 31:13
  • +Le 23:2
  • +Le 19:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 23-24

Àìsáyà 1:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ọkàn mi.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 23-24

Àìsáyà 1:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 15:29
  • +Mt 6:7
  • +Owe 28:9; Ais 59:2; Ida 3:44
  • +Mik 3:2-4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 24-25

Àìsáyà 1:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 4:14
  • +Ais 55:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 26-27

Àìsáyà 1:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aláìlóbìí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mik 6:8
  • +Di 10:18; Jer 22:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 26-27

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/1998, ojú ìwé 14

Àìsáyà 1:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mik 6:2; Jem 4:8
  • +Sm 51:7; Ais 44:22; Mik 7:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 57

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 12/2016, ojú ìwé 1

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2017, ojú ìwé 27

    Jọ̀wọ́ Pa Dà Sọ́dọ̀ Jèhófà, ojú ìwé 10-11

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 263-264

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2011, ojú ìwé 21

    12/1/2006, ojú ìwé 9

    7/1/2003, ojú ìwé 17-18

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 28-29

Àìsáyà 1:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:1, 2; Joẹ 2:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 29

Àìsáyà 1:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:33; Owe 29:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 29

Àìsáyà 1:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 48:2
  • +Jer 2:20
  • +2Sa 8:15; 1Ọb 3:28
  • +2Kr 19:9, 10
  • +Mik 3:1-3; Lk 13:34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 29-30

Àìsáyà 1:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “bíà rẹ tí wọ́n fi wíìtì ṣe.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 22:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 30-31

Àìsáyà 1:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aláìlóbìí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 3:14; Mik 3:9-11
  • +Ẹk 23:8
  • +Ẹk 22:22; Jer 5:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 30-31

Àìsáyà 1:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 5:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 31-32

Àìsáyà 1:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 6:29, 30; 9:7; Mal 3:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 32-33

Àìsáyà 1:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 12:3; 1Sa 12:1, 3; Ais 32:1; Isk 34:23
  • +Ais 62:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 33-34

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1992, ojú ìwé 14-15

Àìsáyà 1:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 31:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 33-34

Àìsáyà 1:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 20:38
  • +1Ọb 9:6, 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 34-35

Àìsáyà 1:29

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó jọ pé àwọn igi àti àwọn ọgbà tó jẹ mọ́ ìjọsìn òrìṣà ló ń sọ.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 6:13
  • +Ais 65:3; 66:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 34-35

Àìsáyà 1:30

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 17:5, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 35

Àìsáyà 1:31

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ohun tó rí bí okùn tó sì lè tètè jóná.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 35-36

Àwọn míì

Àìsá. 1:12Kr 32:32
Àìsá. 1:12Kr 26:22; Ais 6:1
Àìsá. 1:12Kr 27:1, 2
Àìsá. 1:12Kr 28:1
Àìsá. 1:12Kr 29:1, 2; 32:20
Àìsá. 1:1Mt 1:9
Àìsá. 1:2Sm 50:4
Àìsá. 1:2Di 1:31
Àìsá. 1:2Di 4:25, 26; Isk 20:8
Àìsá. 1:3Ho 4:6
Àìsá. 1:4Da 9:11
Àìsá. 1:4Di 31:16; Jer 2:5
Àìsá. 1:5Jer 5:3
Àìsá. 1:5Ne 9:34, 35; Da 9:8
Àìsá. 1:6Lk 10:34
Àìsá. 1:7Di 28:33, 63
Àìsá. 1:72Ọb 18:11
Àìsá. 1:82Ọb 18:13, 14; Ais 8:7, 8
Àìsá. 1:9Jẹ 19:24, 25; Di 29:22, 23; Ro 9:29
Àìsá. 1:10Jẹ 13:13; Ais 3:8, 9
Àìsá. 1:10Di 32:32; Jud 7
Àìsá. 1:111Sa 15:22; Owe 15:8; Ho 6:6; Mik 6:7
Àìsá. 1:11Ẹk 29:38
Àìsá. 1:11Le 3:14-16
Àìsá. 1:11Le 17:11
Àìsá. 1:11Le 4:18, 21
Àìsá. 1:11Le 16:5
Àìsá. 1:12Di 16:16
Àìsá. 1:12Onw 5:1; Mal 1:8
Àìsá. 1:13Owe 21:27; Isk 8:11, 12
Àìsá. 1:13Nọ 28:11
Àìsá. 1:13Ẹk 31:13
Àìsá. 1:13Le 23:2
Àìsá. 1:13Le 19:26
Àìsá. 1:15Owe 15:29
Àìsá. 1:15Mt 6:7
Àìsá. 1:15Owe 28:9; Ais 59:2; Ida 3:44
Àìsá. 1:15Mik 3:2-4
Àìsá. 1:16Jer 4:14
Àìsá. 1:16Ais 55:7
Àìsá. 1:17Mik 6:8
Àìsá. 1:17Di 10:18; Jer 22:3
Àìsá. 1:18Mik 6:2; Jem 4:8
Àìsá. 1:18Sm 51:7; Ais 44:22; Mik 7:19
Àìsá. 1:19Di 28:1, 2; Joẹ 2:19
Àìsá. 1:20Le 26:33; Owe 29:1
Àìsá. 1:21Sm 48:2
Àìsá. 1:21Jer 2:20
Àìsá. 1:212Sa 8:15; 1Ọb 3:28
Àìsá. 1:212Kr 19:9, 10
Àìsá. 1:21Mik 3:1-3; Lk 13:34
Àìsá. 1:22Isk 22:18
Àìsá. 1:23Ais 3:14; Mik 3:9-11
Àìsá. 1:23Ẹk 23:8
Àìsá. 1:23Ẹk 22:22; Jer 5:28
Àìsá. 1:24Isk 5:13
Àìsá. 1:25Jer 6:29, 30; 9:7; Mal 3:3
Àìsá. 1:26Nọ 12:3; 1Sa 12:1, 3; Ais 32:1; Isk 34:23
Àìsá. 1:26Ais 62:1
Àìsá. 1:27Jer 31:11
Àìsá. 1:28Isk 20:38
Àìsá. 1:281Ọb 9:6, 7
Àìsá. 1:29Isk 6:13
Àìsá. 1:29Ais 65:3; 66:17
Àìsá. 1:30Jer 17:5, 6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 1:1-31

Àìsáyà

1 Ìran tí Àìsáyà*+ ọmọ Émọ́ọ̀sì rí nípa Júdà àti Jerúsálẹ́mù láyé ìgbà Ùsáyà,+ Jótámù,+ Áhásì+ àti Hẹsikáyà,+ àwọn ọba Júdà:+

 2 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọ̀run, sì fetí sílẹ̀, ìwọ ayé,+

Torí Jèhófà ti sọ pé:

“Mo ti tọ́ àwọn ọmọ,+ mo sì ti tọ́jú wọn dàgbà,

Àmọ́ wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+

 3 Akọ màlúù mọ ẹni tó ra òun dunjú,

Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sì mọ ibùjẹ ẹran olówó rẹ̀;

Àmọ́ Ísírẹ́lì ò mọ̀ mí,*+

Àwọn èèyàn mi ò fi òye hùwà.”

 4 O gbé! Ìwọ orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀,+

Àwọn èèyàn tí ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀ lọ́rùn,

Ìran àwọn èèyàn burúkú, àwọn ọmọ oníwà ìbàjẹ́!

Wọ́n ti fi Jèhófà sílẹ̀;+

Wọ́n ti hùwà àfojúdi sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì;

Wọ́n ti kẹ̀yìn sí i.

 5 Ibo la tún lè lù lára yín nígbà tí ẹ kò jáwọ́ nínú ìwà ọ̀tẹ̀ yín?+

Gbogbo orí yín ló ń ṣàìsàn

Àrùn sì ti kọ lu gbogbo ọkàn yín.+

 6 Láti àtẹ́lẹsẹ̀ dé orí, kò sí ibi tó gbádùn.

Ara yín bó, ó ní ọgbẹ́ àti ojú egbò,

Ẹ ò tọ́jú wọn,* ẹ ò dì wọ́n, ẹ ò sì fi òróró pa wọ́n.+

 7 Ilẹ̀ yín ti di ahoro.

Wọ́n ti dáná sun àwọn ìlú yín.

Àwọn àjèjì jẹ ilẹ̀ yín run níṣojú yín.+

Ó dà bí ilẹ̀ tó di ahoro tí àwọn àjèjì gbà.+

 8 Ó wá ku ọmọbìnrin Síónì nìkan, bí àtíbàbà nínú ọgbà àjàrà,

Bí ahéré nínú oko kùkúńbà,*

Bí ìlú tí wọ́n gbógun tì.+

 9 Tí kì í bá ṣe pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun dá díẹ̀ nínú wa sí,

À bá ti dà bíi Sódómù gẹ́lẹ́,

À bá sì ti jọ Gòmórà.+

10 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà, ẹ̀yin apàṣẹwàá* Sódómù.+

Ẹ fetí sí òfin* Ọlọ́run wa, ẹ̀yin èèyàn Gòmórà.+

11 “Àǹfààní wo ni ọ̀pọ̀ ẹbọ yín ń ṣe mí?”+ ni Jèhófà wí.

“Àwọn ẹbọ sísun yín tí ẹ fi àgbò+ ṣe àti ọ̀rá àwọn ẹran tí ẹ bọ́ dáadáa + ti sú mi,

Inú mi ò dùn sí ẹ̀jẹ̀+ àwọn akọ ọmọ màlúù,+ ọ̀dọ́ àgùntàn àti ewúrẹ́.+

12 Bí ẹ ṣe ń wá síwájú mi,+

Tí ẹ̀ ń tẹ àgbàlá mi mọ́lẹ̀,

Ta ló ní kí ẹ ṣe bẹ́ẹ̀?+

13 Ẹ má ṣe mú àwọn ọrẹ ọkà tí kò ní láárí wá mọ́.

Tùràrí yín ń rí mi lára.+

Àwọn òṣùpá tuntun,+ sábáàtì+ àti pípe àpéjọ,+

Mi ò lè fara da bí ẹ ṣe ń pidán,+ tí ẹ sì tún ń ṣe àpéjọ ọlọ́wọ̀.

14 Mo* kórìíra àwọn òṣùpá tuntun yín àtàwọn àjọyọ̀ yín.

Wọ́n ti di ẹrù ìnira fún mi;

Mi ò lè gbé e mọ́.

15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,

Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+

Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+

Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+

Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+

16 Ẹ wẹ ara yín, ẹ jẹ́ kí ara yín mọ́;+

Ẹ mú ìwà ibi yín kúrò níwájú mi;

Ẹ jáwọ́ nínú ìwà burúkú.+

17 Ẹ kọ́ bí ẹ ṣe máa ṣe rere, ẹ wá ìdájọ́ òdodo,+

Ẹ tọ́ àwọn aninilára sọ́nà;

Ẹ gbèjà àwọn ọmọ aláìníbaba,*

Kí ẹ sì gba ẹjọ́ opó rò.”+

18 “Ní báyìí, ẹ wá, ẹ jẹ́ ká yanjú ọ̀rọ̀ láàárín ara wa,” ni Jèhófà wí.+

“Bí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín tiẹ̀ rí bí aṣọ rírẹ̀dòdò,

Wọ́n máa di funfun bíi yìnyín;+

Bí wọ́n tiẹ̀ pọ́n bí aṣọ tó pupa yòò,

Wọ́n máa dà bí irun àgùntàn.

19 Tó bá tinú yín wá, tí ẹ sì fetí sílẹ̀,

Ẹ máa jẹ àwọn ohun rere ilẹ̀ náà.+

20 Àmọ́ tí ẹ bá kọ̀, tí ẹ sì ṣọ̀tẹ̀,

Idà máa jẹ yín run,+

Torí Jèhófà ti fi ẹnu rẹ̀ sọ ọ́.”

21 Ẹ wo bí ìlú olóòótọ́+ ṣe di aṣẹ́wó!+

Ìdájọ́ òdodo kún inú rẹ̀ tẹ́lẹ̀;+

Òdodo ń gbé inú rẹ̀ nígbà kan,+

Àmọ́ ní báyìí, àwọn apààyàn ló wà níbẹ̀.+

22 Fàdákà rẹ ti di ìdàrọ́,+

Wọ́n sì ti bu omi la ọtí bíà rẹ.*

23 Alágídí ni àwọn ìjòyè rẹ, àwọn àtàwọn olè jọ ń ṣiṣẹ́.+

Gbogbo wọn ló fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n sì ń wá ẹ̀bùn kiri.+

Wọn kì í dá ẹjọ́ àwọn ọmọ aláìníbaba* bó ṣe tọ́,

Ẹjọ́ opó kì í sì í dé iwájú wọn.+

24 Torí náà, Olúwa tòótọ́, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,

Alágbára Ísírẹ́lì, kéde pé:

“Ó tó gẹ́ẹ́! Mi ò ní fàyè gba àwọn elénìní mi mọ́,

Màá sì gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá mi.+

25 Màá yí ọwọ́ mi pa dà sí ọ,

Màá yọ́ ìdàrọ́ rẹ dà nù bíi pé mo fi ọṣẹ fọ ìdọ̀tí,

Màá sì mú gbogbo ìdọ̀tí rẹ kúrò.+

26 Màá dá àwọn adájọ́ rẹ pa dà sí bí wọ́n ṣe wà níbẹ̀rẹ̀,

Àwọn agbani-nímọ̀ràn rẹ á sì rí bíi ti ìbẹ̀rẹ̀.+

Lẹ́yìn èyí, wọ́n máa pè ọ́ ní Ìlú Òdodo, Ìlú Olóòótọ́.+

27 Ìdájọ́ òdodo la máa fi tún Síónì rà pa dà,+

Àwọn èèyàn rẹ̀ tó pa dà la sì máa fi òdodo rà pa dà.

28 Àwọn ọlọ̀tẹ̀ àti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ jọ máa fọ́ sí wẹ́wẹ́,+

Òpin sì máa dé bá àwọn tó ń fi Jèhófà sílẹ̀.+

29 Torí àwọn igi ńlá tó wù yín máa tì wọ́n lójú,+

Ojú sì máa tì yín torí àwọn ọgbà* tí ẹ yàn.+

30 Torí ẹ máa dà bí igi ńlá tí àwọn ewé rẹ̀ rọ+

Àti bí ọgbà tí kò lómi.

31 Ọkùnrin alágbára máa di èétú okùn,*

Iṣẹ́ rẹ̀ sì máa ta pàrà;

Iná máa jó àwọn méjèèjì pa pọ̀,

Kò sì ní sẹ́ni tó máa pa iná náà.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́