ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Nọ́ńbà

      • Kàkàkí tí wọ́n fi fàdákà ṣe (1-10)

      • Wọ́n kúrò ní Sínáì (11-13)

      • Bí wọ́n ṣe máa tò tẹ̀ léra tí wọ́n bá ń lọ (14-28)

      • Mósè ní kí Hóbábù fi ọ̀nà han Ísírẹ́lì (29-34)

      • Àdúrà Mósè tí wọ́n bá ń tú àgọ́ ká (35, 36)

Nọ́ńbà 10:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 23:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2020, ojú ìwé 30

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1706

Nọ́ńbà 10:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:18; Di 29:10, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2020, ojú ìwé 30-31

Nọ́ńbà 10:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 18:21; Nọ 1:16; 7:2; Di 1:15; 5:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2020, ojú ìwé 31

Nọ́ńbà 10:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 2:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2020, ojú ìwé 31

Nọ́ńbà 10:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 2:10

Nọ́ńbà 10:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 10:3

Nọ́ńbà 10:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 31:6; 1Kr 15:24; 16:6; 2Kr 29:26; Ne 12:35, 41

Nọ́ńbà 10:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 13:12

Nọ́ńbà 10:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 15:28; 2Kr 5:12; 7:6; Ẹsr 3:10
  • +Le 23:24; Nọ 29:1
  • +Nọ 28:11
  • +Le 3:1
  • +Ẹk 6:7; Le 11:45

Nọ́ńbà 10:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:1
  • +Nọ 9:17; Sm 78:14

Nọ́ńbà 10:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 40:36; Nọ 2:9, 16, 17, 24, 31
  • +Nọ 12:16; 13:26; Di 1:1, 2

Nọ́ńbà 10:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 2:34; 9:23

Nọ́ńbà 10:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹgbẹ́ ọmọ ogun kọ̀ọ̀kan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:4, 7; 2:3

Nọ́ńbà 10:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:4, 8; 2:5

Nọ́ńbà 10:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 2:7

Nọ́ńbà 10:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:51
  • +Nọ 3:25, 26
  • +Nọ 3:36, 37

Nọ́ńbà 10:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹgbẹ́ ọmọ ogun kọ̀ọ̀kan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:4, 5; 2:10

Nọ́ńbà 10:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:5, 6; 2:12

Nọ́ńbà 10:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:4, 14; 2:14

Nọ́ńbà 10:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 3:30, 31; 4:15; 7:9

Nọ́ńbà 10:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹgbẹ́ ọmọ ogun kọ̀ọ̀kan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:4, 10; 2:18, 24

Nọ́ńbà 10:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:4, 10; 2:20

Nọ́ńbà 10:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:4, 11; 2:22

Nọ́ńbà 10:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹgbẹ́ ọmọ ogun kọ̀ọ̀kan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:4, 12; 2:25, 31

Nọ́ńbà 10:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:4, 13; 2:27

Nọ́ńbà 10:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:4, 15; 2:29

Nọ́ńbà 10:28

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹgbẹ́ ọmọ ogun kọ̀ọ̀kan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 2:34

Nọ́ńbà 10:29

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Jẹ́tírò.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 2:16, 18; 3:1; 18:1, 5
  • +Jẹ 12:7; 13:14, 15; 15:18
  • +Ond 1:16; 4:11; 1Sa 15:6
  • +Ẹk 3:8; 6:7

Nọ́ńbà 10:31

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣe bí ojú fún wa.”

Nọ́ńbà 10:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 1:16; 4:11

Nọ́ńbà 10:33

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 3:1; 19:3; 24:16; Di 5:2
  • +Ẹk 25:10, 17
  • +Di 1:32, 33; Joṣ 3:3, 4

Nọ́ńbà 10:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 13:21; Ne 9:12; Sm 78:14

Nọ́ńbà 10:35

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 132:8

Nọ́ńbà 10:36

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọ̀kẹ́ àìmọye.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 1:10

Àwọn míì

Nọ́ń. 10:2Le 23:24
Nọ́ń. 10:3Nọ 1:18; Di 29:10, 11
Nọ́ń. 10:4Ẹk 18:21; Nọ 1:16; 7:2; Di 1:15; 5:23
Nọ́ń. 10:5Nọ 2:3
Nọ́ń. 10:6Nọ 2:10
Nọ́ń. 10:7Nọ 10:3
Nọ́ń. 10:8Nọ 31:6; 1Kr 15:24; 16:6; 2Kr 29:26; Ne 12:35, 41
Nọ́ń. 10:92Kr 13:12
Nọ́ń. 10:101Kr 15:28; 2Kr 5:12; 7:6; Ẹsr 3:10
Nọ́ń. 10:10Le 23:24; Nọ 29:1
Nọ́ń. 10:10Nọ 28:11
Nọ́ń. 10:10Le 3:1
Nọ́ń. 10:10Ẹk 6:7; Le 11:45
Nọ́ń. 10:11Nọ 1:1
Nọ́ń. 10:11Nọ 9:17; Sm 78:14
Nọ́ń. 10:12Ẹk 40:36; Nọ 2:9, 16, 17, 24, 31
Nọ́ń. 10:12Nọ 12:16; 13:26; Di 1:1, 2
Nọ́ń. 10:13Nọ 2:34; 9:23
Nọ́ń. 10:14Nọ 1:4, 7; 2:3
Nọ́ń. 10:15Nọ 1:4, 8; 2:5
Nọ́ń. 10:16Nọ 2:7
Nọ́ń. 10:17Nọ 1:51
Nọ́ń. 10:17Nọ 3:25, 26
Nọ́ń. 10:17Nọ 3:36, 37
Nọ́ń. 10:18Nọ 1:4, 5; 2:10
Nọ́ń. 10:19Nọ 1:5, 6; 2:12
Nọ́ń. 10:20Nọ 1:4, 14; 2:14
Nọ́ń. 10:21Nọ 3:30, 31; 4:15; 7:9
Nọ́ń. 10:22Nọ 1:4, 10; 2:18, 24
Nọ́ń. 10:23Nọ 1:4, 10; 2:20
Nọ́ń. 10:24Nọ 1:4, 11; 2:22
Nọ́ń. 10:25Nọ 1:4, 12; 2:25, 31
Nọ́ń. 10:26Nọ 1:4, 13; 2:27
Nọ́ń. 10:27Nọ 1:4, 15; 2:29
Nọ́ń. 10:28Nọ 2:34
Nọ́ń. 10:29Ẹk 2:16, 18; 3:1; 18:1, 5
Nọ́ń. 10:29Jẹ 12:7; 13:14, 15; 15:18
Nọ́ń. 10:29Ond 1:16; 4:11; 1Sa 15:6
Nọ́ń. 10:29Ẹk 3:8; 6:7
Nọ́ń. 10:32Ond 1:16; 4:11
Nọ́ń. 10:33Ẹk 3:1; 19:3; 24:16; Di 5:2
Nọ́ń. 10:33Ẹk 25:10, 17
Nọ́ń. 10:33Di 1:32, 33; Joṣ 3:3, 4
Nọ́ń. 10:34Ẹk 13:21; Ne 9:12; Sm 78:14
Nọ́ń. 10:35Sm 132:8
Nọ́ń. 10:36Di 1:10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Nọ́ńbà 10:1-36

Nọ́ńbà

10 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: 2 “Ṣe kàkàkí+ méjì fún ara rẹ, fàdákà tí wọ́n fi òòlù lù ni kí o fi ṣe é. Kí o máa fi pe àwọn èèyàn náà jọ pọ̀, kí o sì máa fi sọ fún wọn pé kí wọ́n tú àgọ́ wọn ká. 3 Tí wọ́n bá fun kàkàkí méjèèjì, kí gbogbo àpéjọ náà wá sọ́dọ̀ rẹ ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.+ 4 Tó bá jẹ́ pé kàkàkí kan ni wọ́n fun, àwọn ìjòyè, àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún ní Ísírẹ́lì nìkan ni kó pé jọ sọ́dọ̀ rẹ.+

5 “Tí ẹ bá fi kàkàkí náà fun ìró tó ń lọ sókè sódò, kí àwọn tó pàgọ́ sí apá ìlà oòrùn+ gbéra. 6 Tí ẹ bá fi kàkàkí náà fun ìró tó ń lọ sókè sódò lẹ́ẹ̀kejì, kí àwọn tó pàgọ́ sí apá gúúsù+ gbéra. Bí wọ́n á ṣe máa fun kàkàkí náà nìyí ní gbogbo ìgbà tí àwùjọ kọ̀ọ̀kan bá fẹ́ gbéra.

7 “Tí ẹ bá fẹ́ pe àwọn èèyàn náà jọ, kí ẹ fun àwọn kàkàkí+ náà, àmọ́ kí ẹ má ṣe jẹ́ kí ìró rẹ̀ lọ sókè sódò. 8 Àwọn ọmọ Áárónì, àwọn àlùfáà, ni kó máa fun àwọn kàkàkí+ náà. Kí ẹ máa lò ó, kó jẹ́ àṣẹ tó máa wà títí lọ fún yín jálẹ̀ àwọn ìran yín.

9 “Tí ẹ bá lọ bá ọ̀tá tó ń ni yín lára jagun ní ilẹ̀ yín, ẹ fi àwọn kàkàkí+ náà kéde ogun, Jèhófà Ọlọ́run yín yóò sì rántí yín, yóò gbà yín lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá yín.

10 “Bákan náà, ní àwọn ọjọ́ ayọ̀+ yín, ìyẹn, nígbà àwọn àjọyọ̀+ yín àti ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn oṣù yín, kí ẹ fun àwọn kàkàkí náà sórí àwọn ẹbọ sísun+ àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ yín; wọ́n máa jẹ́ ohun ìrántí fún yín níwájú Ọlọ́run yín. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run+ yín.”

11 Ó ṣẹlẹ̀ pé ní ogúnjọ́ oṣù kejì, ọdún kejì,+ ìkùukùu* náà gbéra lórí àgọ́+ Ẹ̀rí. 12 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bẹ̀rẹ̀ sí í kúrò ní aginjù Sínáì, wọ́n tẹ̀ lé ètò tó wà nílẹ̀ nípa bí wọ́n ṣe máa gbéra,+ ìkùukùu náà sì dúró ní aginjù Páránì.+ 13 Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tí wọ́n gbéra bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+

14 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Júdà ló kọ́kọ́ gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Náṣónì+ ọmọ Ámínádábù sì ni olórí àwùjọ náà. 15 Nétánélì+ ọmọ Súárì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísákà. 16 Élíábù+ ọmọ Hélónì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Sébúlúnì.

17 Nígbà tí wọ́n tú àgọ́ ìjọsìn palẹ̀,+ àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì+ àti àwọn ọmọ Mérárì+ tí wọ́n ru àgọ́ ìjọsìn náà gbéra.

18 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Rúbẹ́nì wá gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Élísúrì+ ọmọ Ṣédéúrì sì ni olórí àwùjọ náà. 19 Ṣẹ́lúmíẹ́lì+ ọmọ Súríṣádáì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Síméónì. 20 Élíásáfù+ ọmọ Déúélì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Gádì.

21 Àwọn ọmọ Kóhátì tí wọ́n ru àwọn ohun èlò+ ibi mímọ́ wá gbéra. Wọ́n á ti to àgọ́ ìjọsìn náà tán kí wọ́n tó dé.

22 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Éfúrémù náà gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Élíṣámà+ ọmọ Ámíhúdù sì ni olórí àwùjọ náà. 23 Gàmálíẹ́lì+ ọmọ Pédásúrì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Mánásè. 24 Ábídánì+ ọmọ Gídéónì sì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì.

25 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Dánì wá gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* àwọn ni wọ́n wà lẹ́yìn tí wọ́n ń ṣọ́ gbogbo ibùdó náà. Áhíésérì+ ọmọ Ámíṣádáì ni olórí àwùjọ náà. 26 Págíẹ́lì+ ọmọ Ókíránì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Áṣérì. 27 Áhírà+ ọmọ Énánì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Náfútálì. 28 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti àwọn àwùjọ wọn* ṣe máa ń tò tẹ̀ léra nìyí tí wọ́n bá fẹ́ gbéra.+

29 Mósè sọ fún Hóbábù ọmọ Réúẹ́lì*+ ọmọ ilẹ̀ Mídíánì, bàbá ìyàwó Mósè pé: “À ń lọ síbi tí Jèhófà sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Èmi yóò fún yín.’+ Bá wa lọ,+ a ó sì tọ́jú rẹ dáadáa, torí Jèhófà ti ṣèlérí àwọn ohun rere fún Ísírẹ́lì.”+ 30 Àmọ́ ó fèsì pé: “Mi ò ní bá yín lọ. Mo máa pa dà sí ilẹ̀ mi àti sọ́dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí mi.” 31 Ni Mósè bá sọ fún un pé: “Jọ̀ọ́, má fi wá sílẹ̀, torí o mọ ibi tí a lè pàgọ́ sí nínú aginjù, o sì lè fọ̀nà hàn wá.* 32 Tí o bá sì bá wa lọ,+ ó dájú pé ohun rere èyíkéyìí tí Jèhófà bá ṣe fún wa la máa ṣe fún ọ.”

33 Lẹ́yìn náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í kúrò ní òkè Jèhófà,+ wọ́n rin ìrìn ọjọ́ mẹ́ta, àpótí+ májẹ̀mú Jèhófà sì ń lọ níwájú wọn ní ọjọ́ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta láti wá ibi ìsinmi fún wọn.+ 34 Ìkùukùu+ Jèhófà sì wà lórí wọn ní ọ̀sán nígbà tí wọ́n gbéra ní ibùdó.

35 Nígbàkigbà tí wọ́n bá gbé Àpótí náà, Mósè á sọ pé: “Dìde, Jèhófà,+ jẹ́ kí àwọn ọ̀tá rẹ tú ká, kí àwọn tó kórìíra rẹ sì sá kúrò níwájú rẹ.” 36 Nígbà tí wọ́n bá sì gbé e kalẹ̀, á sọ pé: “Jèhófà, pa dà sọ́dọ̀ àìmọye ẹgbẹẹgbẹ̀rún* Ísírẹ́lì.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́