ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 60
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ògo Jèhófà tàn sórí Síónì (1-22)

        • Bí àwọn àdàbà tó ń fò lọ sí ilé wọn (8)

        • Wúrà dípò bàbà (17)

        • Ẹni tó kéré máa di ẹgbẹ̀rún (22)

Àìsáyà 60:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 51:17; 52:1
  • +Ais 60:19, 20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 309-310

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 9-11

    1/15/1993, ojú ìwé 12

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 303-306

Àìsáyà 60:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 9-11

    3/1/2001, ojú ìwé 12

    1/1/2000, ojú ìwé 11-12

    4/1/1993, ojú ìwé 9-10

    1/15/1993, ojú ìwé 12-13

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 303-304, 306-307, 403-404

Àìsáyà 60:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìmọ́lẹ̀ àárọ̀ rẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:10
  • +Ais 49:23
  • +Ifi 21:23, 24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 310

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 9-11

    1/1/2000, ojú ìwé 12

    1/15/1993, ojú ìwé 12-13

    4/15/1992, ojú ìwé 10

    8/15/1991, ojú ìwé 18

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 303-304, 306-307

Àìsáyà 60:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:17, 18; 54:1
  • +Ais 49:21, 22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 91-92

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 11

    1/1/2000, ojú ìwé 12

    4/15/1992, ojú ìwé 10-11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 307, 310

Àìsáyà 60:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 33:9
  • +Ais 61:6; Hag 2:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 307-308, 310

Àìsáyà 60:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “bò ọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 1:32, 33
  • +Mal 1:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 308

Àìsáyà 60:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ilé ẹwà mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:11
  • +Jẹ 25:13
  • +Ẹk 29:39, 42; Ais 56:6, 7
  • +Hag 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 11-13

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 308, 310-311

Àìsáyà 60:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àlàfo ilé ẹyẹ.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 12-13

    1/1/2000, ojú ìwé 13-14

    7/15/1992, ojú ìwé 32

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 309

Àìsáyà 60:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ló wà bíi ti àkọ́kọ́.”

  • *

    Tàbí “ṣe ọ́ lọ́ṣọ̀ọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 51:5
  • +Ais 60:4; 66:20
  • +Sm 149:4; Ais 52:1; 55:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2007, ojú ìwé 18

    7/1/2002, ojú ìwé 12-13

    1/1/2000, ojú ìwé 13

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 309

Àìsáyà 60:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìtẹ́wọ́gbà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 7:27; Ne 2:7, 8; Ais 49:23
  • +Di 30:3; Sm 30:5; Ais 54:7; 57:17, 18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 13-14

    1/1/2000, ojú ìwé 13

    4/15/1992, ojú ìwé 10-11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 311-313

Àìsáyà 60:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 21:25, 26
  • +Ais 60:3, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 13-14

    1/1/2000, ojú ìwé 13-14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 311-314

Àìsáyà 60:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 314

Àìsáyà 60:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 35:1, 2
  • +Ais 41:19; 55:13
  • +Sm 132:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2015, ojú ìwé 7-9

    7/1/2002, ojú ìwé 14-15

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 314-315

Àìsáyà 60:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 62:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 315

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2000, ojú ìwé 14

Àìsáyà 60:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:20, 21; Ais 49:14; Jer 30:17; Ida 1:4
  • +Ais 35:10; 61:7; Jer 33:10, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 15

    1/1/2000, ojú ìwé 14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 315-316

Àìsáyà 60:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 61:6
  • +Ais 49:23
  • +Ais 49:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2021, ojú ìwé 17

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 15-16

    1/1/2000, ojú ìwé 14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 315-316

Àìsáyà 60:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 1:26; 32:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2015, ojú ìwé 9-11

    2/15/2006, ojú ìwé 26-28

    7/1/2002, ojú ìwé 16-17

    6/1/2001, ojú ìwé 18-19

    1/15/2001, ojú ìwé 20, 28

    5/15/1995, ojú ìwé 22

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 119-120, 129

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 316-318

Àìsáyà 60:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 2:4; 11:9; 54:14; Sek 9:8
  • +Ais 26:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 17-18

    6/15/2000, ojú ìwé 32

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 318

Àìsáyà 60:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 36:9; Ais 60:1; Ifi 21:23; 22:5
  • +Sek 2:4, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 309-310

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 18

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 318-319

Àìsáyà 60:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 27:1; 84:11
  • +Ais 25:8; 30:19; 35:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 309-310

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 18

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 318-319

Àìsáyà 60:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 43:6, 7
  • +Ais 44:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2002, ojú ìwé 18-19

    1/1/2000, ojú ìwé 15-16

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 319-320

Àìsáyà 60:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2016, ojú ìwé 20

    6/2016, ojú ìwé 23

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2014, ojú ìwé 28

    7/1/2002, ojú ìwé 19

    1/1/2000, ojú ìwé 16

    9/1/1994, ojú ìwé 16

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 90, 96-97

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 320

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 151

Àwọn míì

Àìsá. 60:1Ais 51:17; 52:1
Àìsá. 60:1Ais 60:19, 20
Àìsá. 60:3Ais 11:10
Àìsá. 60:3Ais 49:23
Àìsá. 60:3Ifi 21:23, 24
Àìsá. 60:4Ais 49:17, 18; 54:1
Àìsá. 60:4Ais 49:21, 22
Àìsá. 60:5Jer 33:9
Àìsá. 60:5Ais 61:6; Hag 2:7, 8
Àìsá. 60:61Kr 1:32, 33
Àìsá. 60:6Mal 1:11
Àìsá. 60:7Ais 42:11
Àìsá. 60:7Jẹ 25:13
Àìsá. 60:7Ẹk 29:39, 42; Ais 56:6, 7
Àìsá. 60:7Hag 2:9
Àìsá. 60:9Ais 51:5
Àìsá. 60:9Ais 60:4; 66:20
Àìsá. 60:9Sm 149:4; Ais 52:1; 55:5
Àìsá. 60:10Ẹsr 7:27; Ne 2:7, 8; Ais 49:23
Àìsá. 60:10Di 30:3; Sm 30:5; Ais 54:7; 57:17, 18
Àìsá. 60:11Ifi 21:25, 26
Àìsá. 60:11Ais 60:3, 5
Àìsá. 60:12Ais 41:11
Àìsá. 60:13Ais 35:1, 2
Àìsá. 60:13Ais 41:19; 55:13
Àìsá. 60:13Sm 132:7
Àìsá. 60:14Ais 62:12
Àìsá. 60:152Kr 36:20, 21; Ais 49:14; Jer 30:17; Ida 1:4
Àìsá. 60:15Ais 35:10; 61:7; Jer 33:10, 11
Àìsá. 60:16Ais 61:6
Àìsá. 60:16Ais 49:23
Àìsá. 60:16Ais 49:26
Àìsá. 60:17Ais 1:26; 32:1
Àìsá. 60:18Ais 2:4; 11:9; 54:14; Sek 9:8
Àìsá. 60:18Ais 26:1
Àìsá. 60:19Sm 36:9; Ais 60:1; Ifi 21:23; 22:5
Àìsá. 60:19Sek 2:4, 5
Àìsá. 60:20Sm 27:1; 84:11
Àìsá. 60:20Ais 25:8; 30:19; 35:10
Àìsá. 60:21Ais 43:6, 7
Àìsá. 60:21Ais 44:23
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 60:1-22

Àìsáyà

60 “Dìde, ìwọ obìnrin,+ tan ìmọ́lẹ̀, torí ìmọ́lẹ̀ rẹ ti dé.

Ògo Jèhófà ń tàn sára rẹ.+

 2 Torí, wò ó! òkùnkùn máa bo ayé,

Ìṣúdùdù tó kàmàmà sì máa bo àwọn orílẹ̀-èdè;

Àmọ́ Jèhófà máa tàn sára rẹ,

Wọ́n sì máa rí ògo rẹ̀ lára rẹ.

 3 Àwọn orílẹ̀-èdè máa lọ sínú ìmọ́lẹ̀ rẹ,+

Àwọn ọba+ sì máa lọ sínú ẹwà rẹ tó ń tàn.*+

 4 Gbé ojú rẹ sókè, kí o sì wò yí ká!

Gbogbo wọn ti kóra jọ; wọ́n ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ.

Àwọn ọmọkùnrin rẹ ń bọ̀ láti ọ̀nà jíjìn,+

Ẹ̀gbẹ́ ni wọ́n sì gbé àwọn ọmọbìnrin rẹ sí.+

 5 Ní àkókò yẹn, o máa rí i, o sì máa tàn yinrin,+

Ọkàn rẹ máa lù kìkì, ó sì máa kún rẹ́rẹ́,

Torí pé a máa darí ọrọ̀ òkun sọ́dọ̀ rẹ;

Àwọn ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè máa wá sọ́dọ̀ rẹ.+

 6 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ràkúnmí máa bo ilẹ̀ rẹ,*

Àwọn akọ ọmọ ràkúnmí Mídíánì àti Eéfà.+

Gbogbo àwọn tó wá láti Ṣébà, wọ́n máa wá;

Wọ́n máa gbé wúrà àti oje igi tùràrí.

Wọ́n máa kéde ìyìn Jèhófà.+

 7 A máa kó gbogbo agbo ẹran Kídárì+ jọ sọ́dọ̀ rẹ.

Àwọn àgbò Nébáótì+ máa sìn ọ́.

Wọ́n máa wá sórí pẹpẹ mi pẹ̀lú ìtẹ́wọ́gbà,+

Màá sì ṣe ilé ológo mi* lọ́ṣọ̀ọ́.+

 8 Àwọn wo nìyí tí wọ́n ń fò kọjá bí ìkùukùu,

Bí àwọn àdàbà tó ń fò lọ sí ilé* wọn?

 9 Torí àwọn erékùṣù máa gbẹ́kẹ̀ lé mi,+

Àwọn ọkọ̀ òkun Táṣíṣì ló ṣíwájú,*

Láti kó àwọn ọmọ rẹ wá láti ọ̀nà jíjìn,+

Pẹ̀lú fàdákà wọn àti wúrà wọn,

Síbi orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ àti sọ́dọ̀ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,

Torí ó máa ṣe ọ́ lógo.*+

10 Àwọn àjèjì máa mọ àwọn ògiri rẹ,

Àwọn ọba wọn sì máa ṣe ìránṣẹ́ fún ọ,+

Torí ìbínú ni mo fi kọ lù ọ́,

Àmọ́ màá fi ojúure* mi ṣàánú rẹ.+

11 Àwọn ẹnubodè rẹ máa wà ní ṣíṣí nígbà gbogbo;+

Wọn ò ní tì wọ́n ní ọ̀sán tàbí ní òru,

Láti mú ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè wá sọ́dọ̀ rẹ,

Àwọn ọba wọn sì máa ṣáájú.+

12 Torí orílẹ̀-èdè àti ìjọba èyíkéyìí tí kò bá sìn ọ́ máa ṣègbé,

Àwọn orílẹ̀-èdè sì máa pa run pátápátá.+

13 Ọ̀dọ̀ rẹ ni ògo Lẹ́bánónì máa wá,+

Igi júnípà, igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì lẹ́ẹ̀kan náà,+

Láti ṣe ibi mímọ́ mi lọ́ṣọ̀ọ́;

Màá ṣe ibi tí ẹsẹ̀ mi wà lógo.+

14 Àwọn ọmọ àwọn tó fìyà jẹ ọ́ máa wá, wọ́n á sì tẹrí ba níwájú rẹ;

Gbogbo àwọn tó ń hùwà àfojúdi sí ọ gbọ́dọ̀ tẹrí ba níbi ẹsẹ̀ rẹ,

Wọ́n sì máa pè ọ́ ní ìlú Jèhófà,

Síónì Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì.+

15 Dípò kí wọ́n pa ọ́ tì, kí wọ́n sì kórìíra rẹ, láìsí ẹni tó ń gbà ọ́ kọjá,+

Màá mú kí o di ohun àmúyangàn títí láé,

Orísun ayọ̀ láti ìran dé ìran.+

16 O sì máa mu wàrà àwọn orílẹ̀-èdè,+

O máa mu ọmú àwọn ọba;+

Wàá sì mọ̀ dájú pé èmi Jèhófà ni Olùgbàlà rẹ,

Alágbára Jékọ́bù sì ni Olùtúnrà rẹ.+

17 Dípò bàbà, màá mú wúrà wá,

Dípò irin, màá mú fàdákà wá

Dípò igi, bàbà

Àti dípò òkúta, irin;

Màá fi àlàáfíà ṣe àwọn alábòójútó rẹ,

Màá sì fi òdodo ṣe àwọn tó ń yan iṣẹ́ fún ọ.+

18 A ò ní gbúròó ìwà ipá mọ́ ní ilẹ̀ rẹ,

A ò sì ní gbúròó ìparun àti ìwópalẹ̀ nínú àwọn ààlà rẹ.+

O máa pe àwọn ògiri rẹ ní Ìgbàlà,+ o sì máa pe àwọn ẹnubodè rẹ ní Ìyìn.

19 Oòrùn ò ní jẹ́ ìmọ́lẹ̀ rẹ mọ́ ní ọ̀sán,

Ìmọ́lẹ̀ òṣùpá ò sì ní mọ́lẹ̀ fún ọ,

Torí Jèhófà máa di ìmọ́lẹ̀ ayérayé fún ọ,+

Ọlọ́run rẹ sì máa di ẹwà rẹ.+

20 Oòrùn rẹ ò ní wọ̀ mọ́,

Òṣùpá rẹ ò sì ní wọ̀ọ̀kùn,

Torí pé Jèhófà máa di ìmọ́lẹ̀ ayérayé fún ọ,+

Àwọn ọjọ́ ọ̀fọ̀ rẹ sì máa dópin.+

21 Gbogbo èèyàn rẹ máa jẹ́ olódodo;

Ilẹ̀ náà máa di tiwọn títí láé.

Àwọn ni èéhù ohun tí mo gbìn,

Iṣẹ́ ọwọ́ mi,+ ká lè ṣe mí lọ́ṣọ̀ọ́.+

22 Ẹni tó kéré máa di ẹgbẹ̀rún,

Ẹni kékeré sì máa di orílẹ̀-èdè alágbára.

Èmi fúnra mi, Jèhófà, máa mú kó yára kánkán ní àkókò rẹ̀.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́