ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 53
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ìyà tó máa jẹ ìránṣẹ́ Jèhófà, bó ṣe máa kú àti bí wọ́n ṣe máa sin ín (1-12)

        • Wọ́n kórìíra rẹ̀, wọ́n sì yẹra fún un (3)

        • Ó gbé àìsàn àti ìrora (4)

        • “Bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á” (7)

        • Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn (12)

Àìsáyà 53:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ohun tí a gbọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 10:16
  • +Ais 51:9
  • +Ais 40:5; Jo 12:37, 38

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 11

    10/1/2008, ojú ìwé 5

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 199

Àìsáyà 53:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ọ̀rọ̀ náà “rẹ̀” lè tọ́ka sí ẹnikẹ́ni tọ́rọ̀ ṣojú ẹ̀ tàbí Ọlọ́run.

  • *

    Tàbí “ìrísí rẹ̀ kò ṣàrà ọ̀tọ̀ débi pé ó máa wù wá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:1; Sek 6:12
  • +Ais 52:14; Jo 1:10; Flp 2:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 199-201

Àìsáyà 53:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “tí a pète fún ìrora.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “Ó dà bí ẹni tí àwọn èèyàn ń gbójú kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 22:7; Mt 26:67, 68; Jo 6:66; 1Pe 2:4
  • +Sek 11:13; Jo 18:39, 40; Iṣe 3:13, 14; 4:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    2/2017, ojú ìwé 3

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 26

    8/1/2000, ojú ìwé 32

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 201-202

Àìsáyà 53:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 8:14-17
  • +Le 16:21, 22; 1Pe 2:24; 1Jo 2:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    2/2017, ojú ìwé 3

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 11

    1/15/2009, ojú ìwé 26

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 202-205

Àìsáyà 53:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 12:10; Jo 19:34
  • +Da 9:24; Ro 4:25
  • +Mt 20:28; Ro 5:6, 19
  • +Kol 1:19, 20
  • +1Pe 2:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 15

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 27

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 202-205

Àìsáyà 53:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 2:25
  • +1Pe 3:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 27

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 202-205

Àìsáyà 53:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 22:12; 69:4
  • +1Pe 2:23
  • +Jo 1:29; 1Kọ 5:7
  • +Mt 27:12-14; Iṣe 8:32, 33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 14

    1/15/2009, ojú ìwé 27

    10/1/2008, ojú ìwé 5

    7/15/1996, ojú ìwé 8

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 205-207

    Yiyan, ojú ìwé 129

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 146

Àìsáyà 53:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìyà.”

  • *

    Tàbí “bí ìgbésí ayé rẹ̀ ṣe rí?”

  • *

    Tàbí “Wọ́n pa á.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 9:26; Mt 27:50
  • +Sek 13:7; Jo 11:49, 50; Ro 5:6; Heb 9:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2021, ojú ìwé 3

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 13-14

    7/15/1996, ojú ìwé 8

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 207-209

Àìsáyà 53:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹnì kan máa fún un ní ibi ìsìnkú.”

  • *

    Ní Héb., “ọkùnrin ọlọ́rọ̀.”

  • *

    Tàbí “kò hùwà ipá kankan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 27:38
  • +Mt 27:57-60; Mk 15:46; Jo 19:41
  • +1Pe 2:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 19-20

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 16

    10/1/2008, ojú ìwé 5-6

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 209

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 152

Àìsáyà 53:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Àmọ́ inú Jèhófà dùn sí i.”

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

  • *

    Ní Héb., “èso.”

  • *

    Tàbí “Ìfẹ́ Jèhófà; Ohun tó múnú Jèhófà dùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 16:11; 2Kọ 5:21; Heb 7:27
  • +Ais 9:7; 1Ti 6:16
  • +Kol 1:19, 20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    2/2017, ojú ìwé 3

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 26-27

    1/15/2007, ojú ìwé 10

    8/15/2000, ojú ìwé 31

    10/1/1992, ojú ìwé 14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 209-210

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 134

Àìsáyà 53:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìdààmú ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:1
  • +Ro 5:18, 19
  • +1Pe 2:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 28-29

    10/1/2008, ojú ìwé 5-6

    1/15/2007, ojú ìwé 10

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 209-211

Àìsáyà 53:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 22:14; Mt 26:27, 28; Heb 2:14
  • +Mk 15:27; Lk 22:37; 23:32, 33
  • +Mt 20:28; 1Ti 2:5, 6; Tit 2:13, 14; Heb 9:28
  • +Ro 8:34; Heb 7:25; 9:26; 1Jo 2:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 14

    1/15/2009, ojú ìwé 28-29

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 213-214

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 146, 151-152

Àwọn míì

Àìsá. 53:1Ro 10:16
Àìsá. 53:1Ais 51:9
Àìsá. 53:1Ais 40:5; Jo 12:37, 38
Àìsá. 53:2Ais 11:1; Sek 6:12
Àìsá. 53:2Ais 52:14; Jo 1:10; Flp 2:7
Àìsá. 53:3Sm 22:7; Mt 26:67, 68; Jo 6:66; 1Pe 2:4
Àìsá. 53:3Sek 11:13; Jo 18:39, 40; Iṣe 3:13, 14; 4:11
Àìsá. 53:4Mt 8:14-17
Àìsá. 53:4Le 16:21, 22; 1Pe 2:24; 1Jo 2:1, 2
Àìsá. 53:5Sek 12:10; Jo 19:34
Àìsá. 53:5Da 9:24; Ro 4:25
Àìsá. 53:5Mt 20:28; Ro 5:6, 19
Àìsá. 53:5Kol 1:19, 20
Àìsá. 53:51Pe 2:24
Àìsá. 53:61Pe 2:25
Àìsá. 53:61Pe 3:18
Àìsá. 53:7Sm 22:12; 69:4
Àìsá. 53:71Pe 2:23
Àìsá. 53:7Jo 1:29; 1Kọ 5:7
Àìsá. 53:7Mt 27:12-14; Iṣe 8:32, 33
Àìsá. 53:8Da 9:26; Mt 27:50
Àìsá. 53:8Sek 13:7; Jo 11:49, 50; Ro 5:6; Heb 9:26
Àìsá. 53:9Mt 27:38
Àìsá. 53:9Mt 27:57-60; Mk 15:46; Jo 19:41
Àìsá. 53:91Pe 2:22
Àìsá. 53:10Le 16:11; 2Kọ 5:21; Heb 7:27
Àìsá. 53:10Ais 9:7; 1Ti 6:16
Àìsá. 53:10Kol 1:19, 20
Àìsá. 53:11Ais 42:1
Àìsá. 53:11Ro 5:18, 19
Àìsá. 53:111Pe 2:24
Àìsá. 53:12Sm 22:14; Mt 26:27, 28; Heb 2:14
Àìsá. 53:12Mk 15:27; Lk 22:37; 23:32, 33
Àìsá. 53:12Mt 20:28; 1Ti 2:5, 6; Tit 2:13, 14; Heb 9:28
Àìsá. 53:12Ro 8:34; Heb 7:25; 9:26; 1Jo 2:1, 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 53:1-12

Àìsáyà

53 Ta ló ti nígbàgbọ́ nínú ohun tó gbọ́ lọ́dọ̀ wa?*+

Ní ti apá Jèhófà,+ ta la ti fi hàn?+

 2 Ó máa jáde wá bí ẹ̀ka igi+ níwájú rẹ̀,* bíi gbòǹgbò látinú ilẹ̀ tó gbẹ táútáú.

Ìrísí rẹ̀ kò buyì kún un, kò sì rẹwà rárá;+

Tí a bá sì rí i, ìrísí rẹ̀ kò fà wá sún mọ́ ọn.*

 3 Àwọn èèyàn kórìíra rẹ̀, wọ́n sì yẹra fún un,+

Ọkùnrin tó mọ bí ìrora ṣe ń rí,* tó sì mọ àìsàn dunjú.

Ó dà bí ẹni pé ojú rẹ̀ pa mọ́ fún wa.*

Wọ́n kórìíra rẹ̀, a sì kà á sí ẹni tí kò já mọ́ nǹkan kan.+

 4 Lóòótọ́, òun fúnra rẹ̀ gbé àwọn àìsàn wa,+

Ó sì ru àwọn ìrora wa.+

Àmọ́ a kà á sí ẹni tí ìyọnu bá, ẹni tí Ọlọ́run kọ lù, tó sì ń jìyà.

 5 Wọ́n gún un+ torí àṣìṣe wa;+

Wọ́n tẹ̀ ẹ́ rẹ́ torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.+

Ó jìyà ká lè ní àlàáfíà,+

A sì rí ìwòsàn nítorí àwọn ọgbẹ́ rẹ̀.+

 6 Gbogbo wa ti rìn gbéregbère bí àgùntàn,+

Kálukú ti yíjú sí ọ̀nà tirẹ̀,

Jèhófà sì ti mú kó ru ẹ̀ṣẹ̀ gbogbo wa.+

 7 Wọ́n ni ín lára,+ ó sì jẹ́ kí wọ́n fìyà jẹ òun,+

Àmọ́ kò la ẹnu rẹ̀.

Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á,+

Bí abo àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀,

Kò sì la ẹnu rẹ̀.+

 8 Wọ́n mú un lọ torí àìṣẹ̀tọ́* àti ìdájọ́;

Ta ló sì máa da ara rẹ̀ láàmú nípa kúlẹ̀kúlẹ̀ ìran rẹ̀?*

Torí wọ́n mú un kúrò lórí ilẹ̀ alààyè;+

Ó jẹ ìyà* torí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn mi.+

 9 Wọ́n sin ín* pẹ̀lú àwọn ẹni burúkú+

Àti àwọn ọlọ́rọ̀,* nígbà tó kú,+

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé kò ṣe ohunkóhun tí kò dáa,*

Kò sì sí ẹ̀tàn kankan lẹ́nu rẹ̀.+

10 Àmọ́ ó wu Jèhófà* láti tẹ̀ ẹ́ rẹ́, ó sì jẹ́ kó ṣàìsàn.

Tí o bá máa fi ẹ̀mí* rẹ̀ rú ẹbọ ẹ̀bi,+

Ó máa rí ọmọ* rẹ̀, ó máa mú kí àwọn ọjọ́ rẹ̀ gùn,+

Ohun tí inú Jèhófà dùn sí* sì máa yọrí sí rere nípasẹ̀ rẹ̀.+

11 Torí ìrora* rẹ̀, ó máa rí i, ó sì máa tẹ́ ẹ lọ́rùn.

Nípasẹ̀ ìmọ̀ rẹ̀, ìránṣẹ́ mi+ tó jẹ́ olódodo

Máa mú kí a ka ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn sí olódodo,+

Ó sì máa ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+

12 Torí ìyẹn, màá fún un ní ìpín láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀,

Ó sì máa pín ẹrù ogun pẹ̀lú àwọn alágbára,

Torí ó tú ẹ̀mí* rẹ̀ jáde, àní títí dé ikú,+

Wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀;+

Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn,+

Ó sì bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bẹ̀bẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́