ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kọ́ríńtì 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Kọ́ríńtì

      • Ìkíni (1, 2)

      • Ọlọ́run ń tù wá nínú nínú gbogbo ìpọ́njú wa (3-11)

      • Ìrìn àjò Pọ́ọ̀lù yí pa dà (12-24)

2 Kọ́ríńtì 1:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 16:1, 2; Flp 2:19, 20
  • +1Tẹ 1:8

2 Kọ́ríńtì 1:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 20:17
  • +Ẹk 34:6; Sm 86:5; Mik 7:18
  • +Ais 51:3; Ro 15:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    4/2019, ojú ìwé 7

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2017, ojú ìwé 13, 16

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2011, ojú ìwé 23-24

    6/1/2009, ojú ìwé 28

    9/1/2008, ojú ìwé 18

    7/1/2008, ojú ìwé 7

    3/15/2008, ojú ìwé 15

    12/15/2007, ojú ìwé 5

    12/15/1996, ojú ìwé 30

    11/1/1996, ojú ìwé 13-14

    6/1/1995, ojú ìwé 11-12

    7/15/1992, ojú ìwé 21

2 Kọ́ríńtì 1:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó ń fún wa níṣìírí.”

  • *

    Tàbí “ìpọ́njú.”

  • *

    Tàbí “ìpọ́njú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 23:4; 2Kọ 7:6
  • +Ro 15:4; 2Tẹ 2:16, 17
  • +Ef 6:21, 22; 1Tẹ 4:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    4/2019, ojú ìwé 7

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2011, ojú ìwé 23-24

    9/1/2008, ojú ìwé 18

    3/15/2008, ojú ìwé 15

    2/15/1998, ojú ìwé 26

    11/1/1996, ojú ìwé 13-14

    6/1/1995, ojú ìwé 11-12

    7/15/1992, ojú ìwé 21

2 Kọ́ríńtì 1:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 4:11-13; Kol 1:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/1/1996, ojú ìwé 14

2 Kọ́ríńtì 1:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìpọ́njú.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/1/1996, ojú ìwé 14

2 Kọ́ríńtì 1:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:18; 2Ti 2:11, 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/1/1996, ojú ìwé 12-13, 14-16

2 Kọ́ríńtì 1:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 20:18, 19
  • +1Kọ 15:32

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2014, ojú ìwé 23

    12/15/1996, ojú ìwé 24

    11/1/1996, ojú ìwé 16-17

    Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, ojú ìwé 163

2 Kọ́ríńtì 1:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 12:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/1/1996, ojú ìwé 16-17

2 Kọ́ríńtì 1:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 34:7, 19; 2Ti 4:18; 2Pe 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/1/1996, ojú ìwé 16

2 Kọ́ríńtì 1:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “nítorí ọ̀pọ̀ àwọn tó tẹ́wọ́ àdúrà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Flp 1:19; Flm 22
  • +Iṣe 12:5; Ro 15:30-32

2 Kọ́ríńtì 1:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 2:4, 5

2 Kọ́ríńtì 1:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “tí ẹ ti mọ̀ dáadáa, tí ẹ sì.”

  • *

    Ní Grk., “títí dé òpin.”

2 Kọ́ríńtì 1:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “kí ẹ lè jàǹfààní lẹ́ẹ̀mejì.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2014, ojú ìwé 30-31

2 Kọ́ríńtì 1:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 16:5, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2014, ojú ìwé 30-31

    10/15/2012, ojú ìwé 28-29

2 Kọ́ríńtì 1:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2014, ojú ìwé 31

2 Kọ́ríńtì 1:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wọ́n tún ń pè é ní Sílà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 18:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2014, ojú ìwé 31

2 Kọ́ríńtì 1:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 15:8
  • +Ifi 3:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2014, ojú ìwé 31

    12/15/2008, ojú ìwé 13

2 Kọ́ríńtì 1:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 2:20, 27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1995, ojú ìwé 10

2 Kọ́ríńtì 1:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àsansílẹ̀; ìdánilójú (ẹ̀jẹ́) ohun tó ń bọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 4:30
  • +Ro 8:23; 2Kọ 5:5; Ef 1:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2016, ojú ìwé 32

    1/2016, ojú ìwé 15-16

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2007, ojú ìwé 31

    7/1/1995, ojú ìwé 10

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 115

2 Kọ́ríńtì 1:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2012, ojú ìwé 28-29

2 Kọ́ríńtì 1:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 13:17; 1Pe 5:2, 3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2013, ojú ìwé 27-28

    1/15/2003, ojú ìwé 16

    6/1/1999, ojú ìwé 15-16

    3/15/1998, ojú ìwé 21-22

    9/1/1996, ojú ìwé 22-23

    4/1/1995, ojú ìwé 18

    10/1/1994, ojú ìwé 20

    9/1/1994, ojú ìwé 14

    Ìwé Ọdọọdún—2013, ojú ìwé 5

Àwọn míì

2 Kọ́r. 1:1Iṣe 16:1, 2; Flp 2:19, 20
2 Kọ́r. 1:11Tẹ 1:8
2 Kọ́r. 1:3Jo 20:17
2 Kọ́r. 1:3Ẹk 34:6; Sm 86:5; Mik 7:18
2 Kọ́r. 1:3Ais 51:3; Ro 15:5
2 Kọ́r. 1:4Sm 23:4; 2Kọ 7:6
2 Kọ́r. 1:4Ro 15:4; 2Tẹ 2:16, 17
2 Kọ́r. 1:4Ef 6:21, 22; 1Tẹ 4:18
2 Kọ́r. 1:51Kọ 4:11-13; Kol 1:24
2 Kọ́r. 1:7Ro 8:18; 2Ti 2:11, 12
2 Kọ́r. 1:8Iṣe 20:18, 19
2 Kọ́r. 1:81Kọ 15:32
2 Kọ́r. 1:92Kọ 12:10
2 Kọ́r. 1:10Sm 34:7, 19; 2Ti 4:18; 2Pe 2:9
2 Kọ́r. 1:11Flp 1:19; Flm 22
2 Kọ́r. 1:11Iṣe 12:5; Ro 15:30-32
2 Kọ́r. 1:121Kọ 2:4, 5
2 Kọ́r. 1:161Kọ 16:5, 6
2 Kọ́r. 1:19Iṣe 18:5
2 Kọ́r. 1:20Ro 15:8
2 Kọ́r. 1:20Ifi 3:14
2 Kọ́r. 1:211Jo 2:20, 27
2 Kọ́r. 1:22Ef 4:30
2 Kọ́r. 1:22Ro 8:23; 2Kọ 5:5; Ef 1:13, 14
2 Kọ́r. 1:24Heb 13:17; 1Pe 5:2, 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Kọ́ríńtì 1:1-24

Ìwé Kejì sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

1 Pọ́ọ̀lù, àpọ́sítélì Kristi Jésù nípasẹ̀ ìfẹ́ Ọlọ́run àti Tímótì+ arákùnrin wa, sí ìjọ Ọlọ́run tó wà ní Kọ́ríńtì, títí kan gbogbo ẹni mímọ́ tó wà ní gbogbo Ákáyà:+

2 Kí ẹ ní inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti àlàáfíà látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, Baba wa àti Jésù Kristi Olúwa.

3 Ìyìn ni fún Ọlọ́run àti Baba Olúwa wa Jésù Kristi,+ Baba àánú oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́+ àti Ọlọ́run ìtùnú gbogbo,+ 4 ẹni tó ń tù wá nínú* nínú gbogbo àdánwò* wa,+ kí a lè fi ìtùnú tí a gbà lọ́dọ̀ rẹ̀+ tu àwọn míì nínú+ lábẹ́ àdánwò* èyíkéyìí tí wọ́n bá wà. 5 Torí pé bí ìyà tí à ń jẹ nítorí Kristi ṣe pọ̀,+ bẹ́ẹ̀ náà ni ìtùnú tí à ń rí gbà nípasẹ̀ Kristi ṣe pọ̀. 6 Nígbà náà, tí a bá dojú kọ àdánwò,* torí ìtùnú àti ìgbàlà yín ni; tí a bá sì ń tù wá nínú, torí kí ẹ lè rí ìtùnú ni, èyí tó máa jẹ́ kí ẹ lè fara da ìyà kan náà tí à ń jẹ. 7 Ìrètí wa lórí yín dájú, nítorí a mọ̀ pé bí ẹ ṣe ń jìyà bíi tiwa, bẹ́ẹ̀ ni ẹ máa rí ìtùnú bíi tiwa.+

8 Ẹ̀yin ará, a fẹ́ kí ẹ mọ̀ nípa ìpọ́njú tó bá wa ní ìpínlẹ̀ Éṣíà.+ A wà nínú ìdààmú tó lé kenkà, kódà ó kọjá agbára wa, a ò tiẹ̀ mọ̀ pé ẹ̀mí wa ò ní bọ́.+ 9 Ká sòótọ́, ṣe ló ń ṣe wá bíi pé a ti gba ìdájọ́ ikú. Èyí jẹ́ kí a má bàa gbẹ́kẹ̀ lé ara wa, àmọ́ ká lè gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run+ tó ń gbé òkú dìde. 10 Ó gbà wá sílẹ̀ látinú irú ewu ikú tó lágbára bẹ́ẹ̀, ó sì máa gbà wá sílẹ̀, òun la gbẹ́kẹ̀ lé pé á máa gbà wá sílẹ̀ nìṣó.+ 11 Ẹ̀yin náà lè máa fi ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ yín ràn wá lọ́wọ́,+ kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ lè máa dúpẹ́ nítorí wa pé a rí inú rere gbà, èyí tó jẹ́ ìdáhùn àdúrà ọ̀pọ̀ èèyàn.*+

12 Nítorí ohun tí a fi ń yangàn nìyí, ẹ̀rí ọkàn wa ń jẹ́rìí pé a ti fi ìjẹ́mímọ́ àti òótọ́ inú lọ́nà ti Ọlọ́run hùwà nínú ayé, pàápàá sí yín, kì í ṣe pẹ̀lú ọgbọ́n ti ara,+ àmọ́ pẹ̀lú inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run. 13 Lóòótọ́, àwọn nǹkan tí ẹ lè kà kí ẹ sì* lóye nìkan là ń kọ ránṣẹ́ sí yín, mo sì retí pé ẹ̀ẹ́ túbọ̀ lóye àwọn nǹkan yìí ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́,* 14 bí ẹ̀yin náà ṣe mọ̀ dé àyè kan pé a wà lára ohun tí ẹ lè fi yangàn, bí ẹ̀yin pẹ̀lú ṣe máa jẹ́ fún wa ní ọjọ́ Olúwa wa Jésù.

15 Torí náà, pẹ̀lú ìdánilójú yìí, mo fẹ́ kọ́kọ́ wá sọ́dọ̀ yín tẹ́lẹ̀, kí ẹ lè ní ìdí láti dunnú lẹ́ẹ̀kan sí i;* 16 torí mo fẹ́ bẹ̀ yín wò tí mo bá ń lọ sí Makedóníà, kí n sì tún pa dà sọ́dọ̀ yín tí mo bá ń bọ̀ láti Makedóníà, lẹ́yìn náà kí ẹ sìn mí dé ọ̀nà Jùdíà.+ 17 Tóò, nígbà tí mo ní irú nǹkan yìí lọ́kàn, mi ò fojú kékeré wo ọ̀rọ̀ náà, àbí mo ṣe bẹ́ẹ̀? Àbí ẹran ara ló mú kí n fẹ́ ṣe bẹ́ẹ̀, tí mo wá ń sọ pé “Bẹ́ẹ̀ ni, bẹ́ẹ̀ ni” àmọ́ tí mo tún ń sọ pé “Bẹ́ẹ̀ kọ́, bẹ́ẹ̀ kọ́”? 18 Àmọ́ Ọlọ́run ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé pé ohun tí a sọ fún yín kì í ṣe “bẹ́ẹ̀ ni” kó tún wá jẹ́ “bẹ́ẹ̀ kọ́.” 19 Nítorí Ọmọ Ọlọ́run, Jésù Kristi, tí a wàásù rẹ̀ láàárín yín, ìyẹn nípasẹ̀ èmi àti Sílífánù* pẹ̀lú Tímótì,+ kò di “bẹ́ẹ̀ ni” kó tún wá jẹ́ “bẹ́ẹ̀ kọ́,” àmọ́ “bẹ́ẹ̀ ni” ti di “bẹ́ẹ̀ ni” nínú ọ̀rọ̀ tirẹ̀. 20 Nítorí bó ṣe wù kí àwọn ìlérí Ọlọ́run pọ̀ tó, wọ́n ti di “bẹ́ẹ̀ ni” nípasẹ̀ rẹ̀.+ Torí náà, ipasẹ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ni à ń ṣe “Àmín” sí Ọlọ́run,+ èyí tó ń fi ògo fún un nípasẹ̀ wa. 21 Àmọ́ Ọlọ́run ni ẹni tó ń mú kó dájú pé àwa àti ẹ̀yin jẹ́ ti Kristi, òun ló sì yàn wá.+ 22 Ó tún fi èdìdì rẹ̀ sórí wa,+ ó sì ti fún wa ní àmì ìdánilójú ohun tó ń bọ̀,* ìyẹn ẹ̀mí+ tó wà nínú ọkàn wa.

23 Mo fi Ọlọ́run ṣe ẹlẹ́rìí ara* mi pé torí kí n má bàa tún kó ẹ̀dùn ọkàn bá yín ni mi ò ṣe tíì wá sí Kọ́ríńtì. 24 Kì í ṣe pé a jẹ́ ọ̀gá lórí ìgbàgbọ́ yín,+ àmọ́ a jọ ń ṣiṣẹ́ kí ẹ lè máa láyọ̀, torí ìgbàgbọ́ yín ló mú kí ẹ dúró.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́