ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 34
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Nọ́ńbà

      • Àwọn ààlà ilẹ̀ Kénáánì (1-15)

      • Wọ́n yan àwọn tó máa pín ilẹ̀ náà (16-29)

Nọ́ńbà 34:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 15:18; 17:8
  • +Jẹ 10:19; Di 4:38; Joṣ 1:4; 14:1; Jer 3:19; Iṣe 17:26

Nọ́ńbà 34:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Òkun Òkú.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 15:1, 2

Nọ́ńbà 34:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 1:36
  • +Nọ 13:26; 32:8
  • +Joṣ 15:1, 3

Nọ́ńbà 34:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Òkun Ńlá, Òkun Mẹditaréníà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:31; Joṣ 15:1, 4

Nọ́ńbà 34:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Òkun Mẹditaréníà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 1:4; 15:12

Nọ́ńbà 34:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àbáwọlé Hámátì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 13:21; 2Ọb 14:25
  • +Isk 47:15

Nọ́ńbà 34:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 47:17

Nọ́ńbà 34:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, adágún odò Jẹ́nẹ́sárẹ́tì tàbí Òkun Gálílì.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 3:16, 17; Joṣ 11:1, 2; Lk 5:1; Jo 6:1

Nọ́ńbà 34:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 15:1, 2
  • +Di 8:7-9

Nọ́ńbà 34:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 26:55; 33:54; Joṣ 14:2; 18:6; Owe 16:33

Nọ́ńbà 34:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 32:33; Di 3:12, 13; Joṣ 13:8

Nọ́ńbà 34:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 32:5, 32

Nọ́ńbà 34:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 3:32; 20:26; Joṣ 14:1
  • +Nọ 14:38; 27:18; Joṣ 19:51

Nọ́ńbà 34:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 1:4, 16

Nọ́ńbà 34:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 15:1
  • +Nọ 14:30; 26:65

Nọ́ńbà 34:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 19:1

Nọ́ńbà 34:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 18:11

Nọ́ńbà 34:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 19:40

Nọ́ńbà 34:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 46:20; 48:5; Joṣ 16:1
  • +Joṣ 17:1

Nọ́ńbà 34:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 16:5

Nọ́ńbà 34:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 19:10

Nọ́ńbà 34:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 19:17

Nọ́ńbà 34:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 19:24

Nọ́ńbà 34:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 19:32

Nọ́ńbà 34:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 34:18; Di 32:8; Joṣ 19:51; Iṣe 17:26

Àwọn míì

Nọ́ń. 34:2Jẹ 15:18; 17:8
Nọ́ń. 34:2Jẹ 10:19; Di 4:38; Joṣ 1:4; 14:1; Jer 3:19; Iṣe 17:26
Nọ́ń. 34:3Joṣ 15:1, 2
Nọ́ń. 34:4Ond 1:36
Nọ́ń. 34:4Nọ 13:26; 32:8
Nọ́ń. 34:4Joṣ 15:1, 3
Nọ́ń. 34:5Ẹk 23:31; Joṣ 15:1, 4
Nọ́ń. 34:6Joṣ 1:4; 15:12
Nọ́ń. 34:8Nọ 13:21; 2Ọb 14:25
Nọ́ń. 34:8Isk 47:15
Nọ́ń. 34:9Isk 47:17
Nọ́ń. 34:11Di 3:16, 17; Joṣ 11:1, 2; Lk 5:1; Jo 6:1
Nọ́ń. 34:12Joṣ 15:1, 2
Nọ́ń. 34:12Di 8:7-9
Nọ́ń. 34:13Nọ 26:55; 33:54; Joṣ 14:2; 18:6; Owe 16:33
Nọ́ń. 34:14Nọ 32:33; Di 3:12, 13; Joṣ 13:8
Nọ́ń. 34:15Nọ 32:5, 32
Nọ́ń. 34:17Nọ 3:32; 20:26; Joṣ 14:1
Nọ́ń. 34:17Nọ 14:38; 27:18; Joṣ 19:51
Nọ́ń. 34:18Nọ 1:4, 16
Nọ́ń. 34:19Joṣ 15:1
Nọ́ń. 34:19Nọ 14:30; 26:65
Nọ́ń. 34:20Joṣ 19:1
Nọ́ń. 34:21Joṣ 18:11
Nọ́ń. 34:22Joṣ 19:40
Nọ́ń. 34:23Jẹ 46:20; 48:5; Joṣ 16:1
Nọ́ń. 34:23Joṣ 17:1
Nọ́ń. 34:24Joṣ 16:5
Nọ́ń. 34:25Joṣ 19:10
Nọ́ń. 34:26Joṣ 19:17
Nọ́ń. 34:27Joṣ 19:24
Nọ́ń. 34:28Joṣ 19:32
Nọ́ń. 34:29Nọ 34:18; Di 32:8; Joṣ 19:51; Iṣe 17:26
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Nọ́ńbà 34:1-29

Nọ́ńbà

34 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé.

3 “‘Kí ààlà gúúsù yín bẹ̀rẹ̀ láti aginjù Síínì lẹ́gbẹ̀ẹ́ Édómù, kí ààlà gúúsù yín lápá ìlà oòrùn sì jẹ́ láti ìkángun Òkun Iyọ̀.*+ 4 Kí ààlà yín sì yí gba gúúsù, kó gba ibi tí wọ́n ń gbà gòkè ní Ákírábímù+ títí lọ dé Síínì, kó sì parí sí gúúsù Kadeṣi-báníà.+ Kó wá dé Hasari-ádáárì+ títí lọ dé Ásímónì. 5 Kí ààlà náà yí gba Àfonífojì Íjíbítì láti Ásímónì, kó sì parí sí Òkun.*+

6 “‘Ààlà yín ní ìwọ̀ oòrùn máa jẹ́ Òkun Ńlá* àti èbúté. Èyí ni yóò jẹ́ ààlà yín ní ìwọ̀ oòrùn.+

7 “‘Èyí ni yóò jẹ́ ààlà yín ní àríwá: Kí ẹ pààlà yín láti Òkun Ńlá dé Òkè Hóórì. 8 Kí ẹ pààlà yín láti Òkè Hóórì dé Lebo-hámátì,*+ kí ààlà náà sì parí sí Sédádì.+ 9 Kí ààlà náà lọ títí dé Sífírónì, kó sì parí sí Hasari-énánì.+ Èyí ni yóò jẹ́ ààlà yín ní àríwá.

10 “‘Ní ìlà oòrùn, kí ẹ pààlà yín láti Hasari-énánì dé Ṣẹ́fámù. 11 Kí ààlà náà lọ láti Ṣẹ́fámù dé Ríbúlà ní ìlà oòrùn Áyínì, kí ààlà náà sì gba ìsàlẹ̀ lọ kan gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ ìlà oòrùn Òkun Kínérétì.*+ 12 Kí ààlà náà lọ dé Jọ́dánì, kó sì parí sí Òkun Iyọ̀.+ Èyí ni yóò jẹ́ ilẹ̀+ yín àti àwọn ààlà rẹ̀ yí ká.’”

13 Mósè wá sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: “Èyí ni ilẹ̀ tí ẹ máa fi kèké+ pín bí ohun ìní, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ gẹ́lẹ́ pé kí wọ́n fún ẹ̀yà mẹ́sàn-án àti ààbọ̀. 14 Torí pé ẹ̀yà àwọn ọmọ Rúbẹ́nì gẹ́gẹ́ bí agbo ilé bàbá wọn, àwọn ọmọ Gádì gẹ́gẹ́ bí agbo ilé bàbá wọn àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè ti gba ogún+ tiwọn. 15 Ẹ̀yà méjì ààbọ̀ ti gba ogún tiwọn ní ìlà oòrùn agbègbè Jọ́dánì lẹ́gbẹ̀ẹ́ Jẹ́ríkò, lápá ibi tí oòrùn ti ń yọ.”+

16 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 17 Orúkọ àwọn ọkùnrin tó máa pín ilẹ̀ tí yóò di tiyín fún yín nìyí: àlùfáà Élíásárì+ àti Jóṣúà+ ọmọ Núnì. 18 Kí ẹ mú ìjòyè kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan tó máa pín ilẹ̀ tí ẹ máa jogún+ fún yín. 19 Orúkọ àwọn ọkùnrin náà nìyí: látinú ẹ̀yà Júdà,+ Kélẹ́bù+ ọmọ Jéfúnè; 20 látinú ẹ̀yà àwọn ọmọ Síméónì,+ Ṣẹ́múẹ́lì ọmọ Ámíhúdù; 21 látinú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì,+ Élídádì ọmọ Kísílónì; 22 látinú ẹ̀yà àwọn ọmọ Dánì,+ ìjòyè kan, Búkì ọmọ Jógílì; 23 látinú ẹ̀yà àwọn ọmọ Jósẹ́fù,+ láti ẹ̀yà àwọn ọmọ Mánásè,+ ìjòyè kan, Háníélì ọmọ Éfódì; 24 látinú ẹ̀yà àwọn ọmọ Éfúrémù,+ ìjòyè kan, Kémúélì ọmọ Ṣífútánì; 25 látinú ẹ̀yà àwọn ọmọ Sébúlúnì,+ ìjòyè kan, Élísáfánì ọmọ Pánákì; 26 látinú ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísákà,+ ìjòyè kan, Pálítíélì ọmọ Ásánì; 27 látinú ẹ̀yà àwọn ọmọ Áṣérì,+ ìjòyè kan, Áhíhúdù ọmọ Ṣẹ́lómì; 28 látinú ẹ̀yà àwọn ọmọ Náfútálì,+ ìjòyè kan, Pédáhélì ọmọ Ámíhúdù.” 29 Àwọn yìí ni Jèhófà pàṣẹ pé kí wọ́n pín ilẹ̀ náà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ilẹ̀ Kénáánì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́