ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 49
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Iṣẹ́ ìránṣẹ́ Jèhófà (1-12)

        • Ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè (6)

      • A tu Ísírẹ́lì nínú (13-26)

Àìsáyà 49:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “látinú oyún.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 55:4
  • +Ais 44:2; 46:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 136-137

Àìsáyà 49:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 51:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2008, ojú ìwé 15

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 282

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 137-138, 151

Àìsáyà 49:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 43:10
  • +Ais 44:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 138-140

Àìsáyà 49:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Jèhófà máa dá ẹjọ́ mi bó ṣe tọ́.”

  • *

    Tàbí “Owó iṣẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 140-141

Àìsáyà 49:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 56:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 140

Àìsáyà 49:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:6; Mt 12:18; Lk 2:30, 32
  • +Sm 98:2; Ais 11:10; 52:10; Iṣe 13:47

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 21-22

    1/15/2007, ojú ìwé 9-10

    12/15/1998, ojú ìwé 19

    3/15/1994, ojú ìwé 25

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 141-142

Àìsáyà 49:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kórìíra nínú ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 43:14
  • +Ais 53:3
  • +Di 7:9
  • +Ais 42:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 142-143

Àìsáyà 49:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìtẹ́wọ́gbà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 69:13
  • +Lk 1:69; 22:43; 2Kọ 6:2; Heb 5:7
  • +Ais 42:6, 7
  • +Ais 54:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 23

    12/15/1998, ojú ìwé 19

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 126-127

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 143-145, 151

Àìsáyà 49:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “Orí gbogbo òkè tí nǹkan kan ò ti hù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 102:19, 20
  • +Sm 112:4; Ais 9:2; Lk 1:68, 79

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 143-144

Àìsáyà 49:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 55:1; 65:13
  • +Ais 32:2
  • +Isk 34:23
  • +Sm 23:1, 2; Jer 31:9; Ifi 7:16, 17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 126-127

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 143-144

Àìsáyà 49:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 107:6, 7; Ais 11:16; 40:3, 4

Àìsáyà 49:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 30:4
  • +Ais 43:5, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 143-144

Àìsáyà 49:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:10
  • +Ais 55:12
  • +Ais 12:1; 40:1; 66:13
  • +Ais 44:23; 61:3; Jer 31:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 145-146

Àìsáyà 49:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 54:7
  • +Ida 5:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 146-148

Àìsáyà 49:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 44:21; Jer 31:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2021, ojú ìwé 25

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2020, ojú ìwé 18

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 250-251

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2012, ojú ìwé 15

    5/1/2008, ojú ìwé 8-9

    9/15/2007, ojú ìwé 21-22

    7/1/2003, ojú ìwé 18-19

    12/1/1998, ojú ìwé 32

    Ìgbàgbọ́ Òdodo, ojú ìwé 3

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 146-147

Àìsáyà 49:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 146-147

Àìsáyà 49:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 147-148

Àìsáyà 49:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 43:5, 6; 60:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 147-148

Àìsáyà 49:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 51:3
  • +Jer 30:18, 19
  • +Jer 51:34
  • +Jer 30:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 147-148

Àìsáyà 49:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 54:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 147-148

Àìsáyà 49:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 43:5; Jer 31:17
  • +Ida 1:1
  • +Ais 62:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 147-148

Àìsáyà 49:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òpó tí mo fi ṣe àmì.”

  • *

    Ní Héb., “Wọ́n máa gbé àwọn ọmọkùnrin rẹ sí àyà wọn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 1:3; Ais 11:10, 12; 62:10
  • +Ais 60:4; 66:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 148-149

Àìsáyà 49:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:10, 16
  • +Ais 60:14
  • +Mik 7:16, 17
  • +Ais 25:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 60-61

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 148-149

Àìsáyà 49:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 149-150

Àìsáyà 49:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 29:14; 46:27; Ho 6:11; Joẹ 3:1
  • +Ais 52:2; Jer 29:10; 50:34; Sek 9:11
  • +Ais 54:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 149-151

Àìsáyà 49:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Gbogbo ẹran ara.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 39:28
  • +1Ti 1:1
  • +Ais 41:14; 48:20
  • +Ais 60:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 150-151

Àwọn míì

Àìsá. 49:1Ais 55:4
Àìsá. 49:1Ais 44:2; 46:3
Àìsá. 49:2Ais 51:16
Àìsá. 49:3Ais 43:10
Àìsá. 49:3Ais 44:23
Àìsá. 49:4Ais 40:10
Àìsá. 49:5Ais 56:8
Àìsá. 49:6Ais 42:6; Mt 12:18; Lk 2:30, 32
Àìsá. 49:6Sm 98:2; Ais 11:10; 52:10; Iṣe 13:47
Àìsá. 49:7Ais 43:14
Àìsá. 49:7Ais 53:3
Àìsá. 49:7Di 7:9
Àìsá. 49:7Ais 42:1
Àìsá. 49:8Sm 69:13
Àìsá. 49:8Lk 1:69; 22:43; 2Kọ 6:2; Heb 5:7
Àìsá. 49:8Ais 42:6, 7
Àìsá. 49:8Ais 54:3
Àìsá. 49:9Sm 102:19, 20
Àìsá. 49:9Sm 112:4; Ais 9:2; Lk 1:68, 79
Àìsá. 49:10Ais 55:1; 65:13
Àìsá. 49:10Ais 32:2
Àìsá. 49:10Isk 34:23
Àìsá. 49:10Sm 23:1, 2; Jer 31:9; Ifi 7:16, 17
Àìsá. 49:11Sm 107:6, 7; Ais 11:16; 40:3, 4
Àìsá. 49:12Di 30:4
Àìsá. 49:12Ais 43:5, 6
Àìsá. 49:13Ais 42:10
Àìsá. 49:13Ais 55:12
Àìsá. 49:13Ais 12:1; 40:1; 66:13
Àìsá. 49:13Ais 44:23; 61:3; Jer 31:13
Àìsá. 49:14Ais 54:7
Àìsá. 49:14Ida 5:20
Àìsá. 49:15Ais 44:21; Jer 31:20
Àìsá. 49:18Ais 43:5, 6; 60:4
Àìsá. 49:19Ais 51:3
Àìsá. 49:19Jer 30:18, 19
Àìsá. 49:19Jer 51:34
Àìsá. 49:19Jer 30:16
Àìsá. 49:20Ais 54:1, 2
Àìsá. 49:21Ais 43:5; Jer 31:17
Àìsá. 49:21Ida 1:1
Àìsá. 49:21Ais 62:4
Àìsá. 49:22Ẹsr 1:3; Ais 11:10, 12; 62:10
Àìsá. 49:22Ais 60:4; 66:20
Àìsá. 49:23Ais 60:10, 16
Àìsá. 49:23Ais 60:14
Àìsá. 49:23Mik 7:16, 17
Àìsá. 49:23Ais 25:9
Àìsá. 49:25Jer 29:14; 46:27; Ho 6:11; Joẹ 3:1
Àìsá. 49:25Ais 52:2; Jer 29:10; 50:34; Sek 9:11
Àìsá. 49:25Ais 54:17
Àìsá. 49:26Isk 39:28
Àìsá. 49:261Ti 1:1
Àìsá. 49:26Ais 41:14; 48:20
Àìsá. 49:26Ais 60:16
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 49:1-26

Àìsáyà

49 Ẹ fetí sí mi, ẹ̀yin erékùṣù,

Kí ẹ sì fiyè sílẹ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè tó jìnnà.+

Jèhófà ti pè mí kí wọ́n tó bí mi.*+

Ó ti dárúkọ mi látìgbà tí mo ti wà nínú ikùn ìyá mi.

 2 Ó ṣe ẹnu mi bí idà tó mú;

Ó fi mí pa mọ́ sínú òjìji ọwọ́ rẹ̀.+

Ó ṣe mí ní ọfà tó ń dán;

Ó fi mí pa mọ́ sínú apó rẹ̀.

 3 Ó sọ fún mi pé: “Ìránṣẹ́ mi ni ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì,+

Ẹni tí màá tipasẹ̀ rẹ̀ fi ẹwà mi hàn.”+

 4 Àmọ́ mo sọ pé: “Lásán ni mo ṣe wàhálà.

Lásán ni mo lo okun mi tán lórí ohun tí kò sí rárá.

Àmọ́ ó dájú pé ìdájọ́ mi wà lọ́wọ́ Jèhófà,*

Èrè* mi sì wà lọ́dọ̀ Ọlọ́run mi.”+

 5 Ní báyìí, Jèhófà, Ẹni tó ṣe mí ní ìránṣẹ́ rẹ̀ látinú oyún,

Ti sọ pé kí n mú Jékọ́bù pa dà wá sọ́dọ̀ òun,

Kí a lè kó Ísírẹ́lì jọ sọ́dọ̀ rẹ̀.+

A máa ṣe mí lógo lójú Jèhófà,

Ọlọ́run mi á sì ti di okun mi.

 6 Ó sọ pé: “Ti pé o jẹ́ ìránṣẹ́ mi nìkan ò tó,

Láti gbé àwọn ẹ̀yà Jékọ́bù dìde,

Kí o sì mú àwọn tí a dá sí lára Ísírẹ́lì pa dà.

Mo tún ti fi ọ́ ṣe ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+

Kí ìgbàlà mi lè dé gbogbo ayé.”+

7 Ohun tí Jèhófà, Olùtúnrà Ísírẹ́lì, Ẹni Mímọ́+ rẹ̀ sọ nìyí, fún ẹni tí wọ́n kórìíra,*+ ẹni tí orílẹ̀-èdè náà kórìíra, fún ìránṣẹ́ àwọn alákòóso:

“Àwọn ọba máa rí i, wọ́n sì máa dìde,

Àwọn ìjòyè máa tẹrí ba,

Nítorí Jèhófà, ẹni tó jẹ́ olóòótọ́,+

Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì, ẹni tó yàn ọ́.”+

 8 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

“Mo dá ọ lóhùn ní àkókò ojúure,*+

Mo sì ràn ọ́ lọ́wọ́ ní ọjọ́ ìgbàlà;+

Mò ń ṣọ́ ọ kí n lè fi ọ́ ṣe májẹ̀mú fún àwọn èèyàn náà,+

Láti tún ilẹ̀ náà ṣe,

Láti mú kí wọ́n gba àwọn ohun ìní wọn tó ti di ahoro,+

 9 Láti sọ fún àwọn ẹlẹ́wọ̀n pé, ‘Ẹ jáde wá!’+

Àti fún àwọn tó wà nínú òkùnkùn+ pé, ‘Ẹ fara hàn!’

Etí ọ̀nà ni wọ́n ti máa jẹun,

Ojú gbogbo ọ̀nà tó ti bà jẹ́* ni wọ́n ti máa jẹko.

10 Ebi ò ní pa wọ́n, òùngbẹ ò sì ní gbẹ wọ́n,+

Ooru tó ń jóni ò ní mú wọn, oòrùn ò sì ní pa wọ́n.+

Torí pé Ẹni tó ń ṣàánú wọn máa darí wọn,+

Ó sì máa mú wọn gba ibi àwọn ìsun omi.+

11 Màá sọ gbogbo òkè mi di ọ̀nà,

Àwọn ojú ọ̀nà mi sì máa ga sókè.+

12 Wò ó! Àwọn yìí ń bọ̀ láti ọ̀nà jíjìn,+

Sì wò ó! àwọn yìí ń bọ̀ láti àríwá àti ìwọ̀ oòrùn

Àti àwọn yìí láti ilẹ̀ Sínímù.”+

13 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, sì máa yọ̀, ìwọ ayé.+

Kí inú àwọn òkè dùn, kí wọ́n sì kígbe ayọ̀.+

Torí Jèhófà ti tu àwọn èèyàn rẹ̀ nínú,+

Ó sì ń ṣàánú àwọn èèyàn rẹ̀ tí ìyà ń jẹ.+

14 Àmọ́ Síónì ń sọ ṣáá pé:

“Jèhófà ti pa mí tì,+ Jèhófà sì ti gbàgbé mi.”+

15 Ṣé obìnrin lè gbàgbé ọmọ rẹ̀ tó ṣì ń mu ọmú

Tàbí kó má ṣàánú ọmọ tó lóyún rẹ̀?

Tí àwọn obìnrin yìí bá tiẹ̀ gbàgbé, mi ò jẹ́ gbàgbé rẹ láé.+

16 Wò ó! Àtẹ́lẹwọ́ mi ni mo fín ọ sí.

Iwájú mi ni àwọn ògiri rẹ máa ń wà.

17 Àwọn ọmọ rẹ pa dà kíákíá.

Àwọn tó ya ọ́ lulẹ̀, tí wọ́n sì sọ ọ́ di ahoro máa kúrò lọ́dọ̀ rẹ.

18 Gbé ojú rẹ sókè, kí o sì wò yí ká.

Gbogbo wọn ń kóra jọ.+

Wọ́n ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ.

“Bó ṣe dájú pé mo wà láàyè,” ni Jèhófà wí,

“O máa wọ gbogbo wọn bí ẹni wọ ohun ọ̀ṣọ́,

O sì máa dè wọ́n mọ́ra bíi ti ìyàwó.

19 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn ilé rẹ ti pa run, ó ti di ahoro, ilẹ̀ rẹ sì ti di àwókù,+

Ó máa wá há jù fún àwọn tó ń gbé ibẹ̀,+

Àwọn tó gbé ọ mì káló+ sì máa jìnnà réré.+

20 Àwọn ọmọ tí wọ́n bí nígbà tí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀ ọ́ máa sọ ní etí rẹ pé,

‘Ibí yìí ti há jù fún mi.

Wá àyè fún mi, kí n lè máa gbé ibí.’+

21 O sì máa sọ lọ́kàn rẹ pé,

‘Ta ni bàbá àwọn ọmọ mi yìí,

Ṣebí obìnrin tó ti ṣòfò ọmọ ni mí, tí mo sì yàgàn,

Tí mo lọ sí ìgbèkùn, tí wọ́n sì mú mi ní ẹlẹ́wọ̀n?

Ta ló tọ́ àwọn ọmọ yìí?+

Wò ó! Wọ́n fi èmi nìkan sílẹ̀,+

Ibo wá ni àwọn yìí ti wá?’”+

22 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí:

“Wò ó! Màá gbé ọwọ́ mi sókè sí àwọn orílẹ̀-èdè,

Màá sì gbé àmì* mi sókè sí àwọn èèyàn.+

Wọ́n máa fi ọwọ́ wọn gbé àwọn ọmọkùnrin rẹ wá,*

Wọ́n sì máa gbé àwọn ọmọbìnrin rẹ sí èjìká wọn.+

23 Àwọn ọba máa di olùtọ́jú rẹ,+

Àwọn ọmọ wọn obìnrin sì máa di alágbàtọ́ rẹ.

Wọ́n máa tẹrí ba fún ọ, wọ́n á sì dojú bolẹ̀,+

Wọ́n máa lá iyẹ̀pẹ̀ ẹsẹ̀ rẹ,+

Wàá sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà;

Ojú ò ní ti àwọn tó bá gbẹ́kẹ̀ lé mi.”+

24 Ṣé a lè gba àwọn tí alágbára ọkùnrin ti mú kúrò lọ́wọ́ rẹ̀,

Àbí ṣé a lè gba àwọn tí ìkà mú lẹ́rú sílẹ̀?

25 Àmọ́ ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

“Kódà, a máa gba àwọn tí alágbára ọkùnrin mú lẹ́rú kúrò lọ́wọ́ rẹ̀,+

A sì máa gba àwọn tí ìkà mú sílẹ̀.+

Màá ta ko àwọn alátakò rẹ,+

Màá sì gba àwọn ọmọ rẹ là.

26 Màá mú kí àwọn tó ń fìyà jẹ ọ́ jẹ ẹran ara tiwọn,

Wọ́n sì máa mu ẹ̀jẹ̀ ara wọn yó bí ẹni mu wáìnì tó dùn.

Gbogbo èèyàn* sì máa mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,+

Olùgbàlà rẹ+ àti Olùtúnrà rẹ,+

Alágbára Jékọ́bù.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́