ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 42
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ìránṣẹ́ Ọlọ́run àti ohun tó máa ṣe (1-9)

        • ‘Jèhófà ni orúkọ mi’ (8)

      • Orin ìyìn tuntun sí Jèhófà (10-17)

      • Ísírẹ́lì fọ́jú, ó sì dití (18-25)

Àìsáyà 42:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 52:13
  • +Ais 49:7; Lk 9:35
  • +Mt 3:17; Jo 6:27; 2Pe 1:17
  • +Ais 61:1; Mt 3:16
  • +Mt 12:15-18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 80

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 22

    8/1/1998, ojú ìwé 5, 11

    1/15/1993, ojú ìwé 10

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 30-32

Àìsáyà 42:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 9:9; Mt 12:16, 19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2021, ojú ìwé 4

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 65, 80-81

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 30-32

Àìsáyà 42:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, koríko etí omi.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 11:28, 29; Heb 2:17
  • +Ais 11:3, 4; Mt 12:20; Jo 5:30; Ifi 19:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    12/2017, ojú ìwé 5

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2015, ojú ìwé 8

    1/15/2009, ojú ìwé 22-23

    10/1/2008, ojú ìwé 5

    6/15/2008, ojú ìwé 6

    3/15/1996, ojú ìwé 21

    11/15/1995, ojú ìwé 21

    10/1/1994, ojú ìwé 16-17

    1/15/1993, ojú ìwé 10

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 80-81

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 30-32

Àìsáyà 42:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìtọ́ni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 9:7; 49:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 80-81

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 23

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 30-31, 37

Àìsáyà 42:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:22, 26
  • +Jer 10:12
  • +Jẹ 2:7; Iṣe 17:24, 25
  • +Job 12:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 4

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 37-38

Àìsáyà 42:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:8
  • +Ais 49:6; Lk 2:29-32; Jo 8:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 21-23

    6/1/2005, ojú ìwé 9

    3/15/1994, ojú ìwé 25

    1/15/1993, ojú ìwé 10-11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 37-41

Àìsáyà 42:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 35:5
  • +Ais 61:1; 1Pe 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 24

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 37-40

Àìsáyà 42:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Èmi kì í bá ẹnì kankan pín ògo mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àlàyé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì, àpilẹ̀kọ 9

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 4

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2014, ojú ìwé 4

    7/1/2010, ojú ìwé 3

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 41

Àìsáyà 42:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:23; 43:19; 2Pe 1:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 41

Àìsáyà 42:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 96:1; 98:1; Ifi 14:3
  • +Ais 44:23
  • +Ais 51:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2001, ojú ìwé 27

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 41-42

Àìsáyà 42:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 35:1
  • +Jẹ 25:13; Ais 60:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 41-42

Àìsáyà 42:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 22:27; Ais 24:15; 66:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 41-42

Àìsáyà 42:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 59:17
  • +Ẹk 15:3
  • +1Sa 2:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 42

Àìsáyà 42:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 43

Àìsáyà 42:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ilẹ̀ etíkun.”

  • *

    Ìyẹn, koríko etí omi.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 107:33; Ais 44:27; 50:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 43

Àìsáyà 42:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 29:18; 35:5; Jer 31:8
  • +Ais 30:21
  • +Ais 60:1, 20
  • +Ais 40:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 43-44

Àìsáyà 42:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ère dídà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 44:10, 11; 45:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 44

Àìsáyà 42:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 6:9, 10; 43:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 44-45

Àìsáyà 42:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 56:10; Jer 4:22; Isk 12:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 44-45

Àìsáyà 42:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 33:31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 44-45

Àìsáyà 42:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìtọ́ni.”

Àìsáyà 42:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:15, 33; Jer 50:17
  • +Sm 102:19, 20
  • +Di 28:29, 52

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 45

Àìsáyà 42:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 45

Àìsáyà 42:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìtọ́ni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 2:12, 14; 2Kr 15:3, 6; Sm 106:41

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 45

Àìsáyà 42:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:22; Na 1:6
  • +Ais 9:13; Jer 5:3; Ho 7:9
  • +Ais 57:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 45

Àwọn míì

Àìsá. 42:1Ais 52:13
Àìsá. 42:1Ais 49:7; Lk 9:35
Àìsá. 42:1Mt 3:17; Jo 6:27; 2Pe 1:17
Àìsá. 42:1Ais 61:1; Mt 3:16
Àìsá. 42:1Mt 12:15-18
Àìsá. 42:2Sek 9:9; Mt 12:16, 19
Àìsá. 42:3Mt 11:28, 29; Heb 2:17
Àìsá. 42:3Ais 11:3, 4; Mt 12:20; Jo 5:30; Ifi 19:11
Àìsá. 42:4Ais 9:7; 49:8
Àìsá. 42:5Ais 40:22, 26
Àìsá. 42:5Jer 10:12
Àìsá. 42:5Jẹ 2:7; Iṣe 17:24, 25
Àìsá. 42:5Job 12:10
Àìsá. 42:6Ais 49:8
Àìsá. 42:6Ais 49:6; Lk 2:29-32; Jo 8:12
Àìsá. 42:7Ais 35:5
Àìsá. 42:7Ais 61:1; 1Pe 2:9
Àìsá. 42:8Ẹk 34:14
Àìsá. 42:9Ais 41:23; 43:19; 2Pe 1:21
Àìsá. 42:10Sm 96:1; 98:1; Ifi 14:3
Àìsá. 42:10Ais 44:23
Àìsá. 42:10Ais 51:5
Àìsá. 42:11Ais 35:1
Àìsá. 42:11Jẹ 25:13; Ais 60:7
Àìsá. 42:12Sm 22:27; Ais 24:15; 66:19
Àìsá. 42:13Ais 59:17
Àìsá. 42:13Ẹk 15:3
Àìsá. 42:131Sa 2:10
Àìsá. 42:15Sm 107:33; Ais 44:27; 50:2
Àìsá. 42:16Ais 29:18; 35:5; Jer 31:8
Àìsá. 42:16Ais 30:21
Àìsá. 42:16Ais 60:1, 20
Àìsá. 42:16Ais 40:4
Àìsá. 42:17Ais 44:10, 11; 45:16
Àìsá. 42:18Ais 6:9, 10; 43:8
Àìsá. 42:19Ais 56:10; Jer 4:22; Isk 12:2
Àìsá. 42:20Isk 33:31
Àìsá. 42:22Di 28:15, 33; Jer 50:17
Àìsá. 42:22Sm 102:19, 20
Àìsá. 42:22Di 28:29, 52
Àìsá. 42:24Ond 2:12, 14; 2Kr 15:3, 6; Sm 106:41
Àìsá. 42:25Di 32:22; Na 1:6
Àìsá. 42:25Ais 9:13; Jer 5:3; Ho 7:9
Àìsá. 42:25Ais 57:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 42:1-25

Àìsáyà

42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn!

Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+

Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+

Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+

 2 Kò ní ké jáde tàbí kó gbé ohùn rẹ̀ sókè,

Kò sì ní jẹ́ ká gbọ́ ohùn rẹ̀ lójú ọ̀nà.+

 3 Kò ní ṣẹ́ esùsú* kankan tó ti fọ́,

Kò sì ní pa òwú àtùpà kankan tó ń jó lọ́úlọ́ú tí wọ́n fi ọ̀gbọ̀ ṣe.+

Ó máa fi òótọ́ ṣe ìdájọ́ òdodo.+

 4 Kò ní rẹ̀ ẹ́, a ò sì ní tẹ̀ ẹ́ rẹ́ títí ó fi máa fìdí ìdájọ́ òdodo múlẹ̀ ní ayé;+

Àwọn erékùṣù sì ń dúró de òfin* rẹ̀.

 5 Ohun tí Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́, sọ nìyí,

Ẹlẹ́dàá ọ̀run àti Atóbilọ́lá tó nà án jáde,+

Ẹni tó tẹ́ ayé àti èso rẹ̀,+

Ẹni tó fún àwọn èèyàn inú rẹ̀ ní èémí,+

Tó sì fún àwọn tó ń rìn lórí rẹ̀ ní ẹ̀mí:+

 6 “Èmi Jèhófà, ti pè ọ́ nínú òdodo;

Mo ti di ọwọ́ rẹ mú.

Màá dáàbò bò ọ́, màá sì fi ọ́ ṣe májẹ̀mú fún àwọn èèyàn náà+

Àti bí ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+

 7 Kí o lè la àwọn ojú tó fọ́,+

Láti mú ẹlẹ́wọ̀n jáde kúrò nínú àjà ilẹ̀

Àti àwọn tó jókòó sínú òkùnkùn jáde kúrò ní ẹ̀wọ̀n.+

 8 Èmi ni Jèhófà. Orúkọ mi nìyẹn;

Èmi kì í fi ògo mi fún ẹlòmíì,*

Èmi kì í sì í fi ìyìn mi fún àwọn ère gbígbẹ́.+

 9 Wò ó, àwọn nǹkan àkọ́kọ́ ti ṣẹlẹ̀;

Ní báyìí, mò ń kéde àwọn nǹkan tuntun.

Kí wọ́n tó rú yọ, mo sọ fún yín nípa wọn.”+

10 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+

Ẹ yìn ín láti àwọn ìkángun ayé,+

Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń lọ sínú òkun àti gbogbo ohun tó kún inú rẹ̀,

Ẹ̀yin erékùṣù àti àwọn tó ń gbé inú wọn.+

11 Kí aginjù àti àwọn ìlú rẹ̀ gbé ohùn wọn sókè,+

Àwọn ìgbèríko tí Kídárì+ ń gbé.

Kí àwọn tó ń gbé níbi àpáta kígbe ayọ̀;

Kí wọ́n ké jáde láti orí àwọn òkè.

12 Kí wọ́n gbé ògo fún Jèhófà,

Kí wọ́n sì kéde ìyìn rẹ̀ ní àwọn erékùṣù.+

13 Jèhófà máa jáde lọ bí akíkanjú ọkùnrin.+

Ó máa mú kí ìtara rẹ̀ sọjí bíi ti jagunjagun.+

Ó máa kígbe, àní, ó máa kígbe ogun;

Ó máa fi hàn pé òun lágbára ju àwọn ọ̀tá òun lọ.+

14 “Ó ti pẹ́ tí mo ti dákẹ́.

Mo dákẹ́ jẹ́ẹ́, mo sì kóra mi níjàánu.

Bí obìnrin tó fẹ́ bímọ,

Màá kérora, màá mí hẹlẹhẹlẹ, màá sì mí gúlegúle lẹ́ẹ̀kan náà.

15 Màá sọ àwọn òkè ńlá àti àwọn òkè kéékèèké di ahoro,

Màá sì mú kí gbogbo ewéko wọn gbẹ dà nù.

Màá sọ àwọn odò di erékùṣù,*

Màá sì mú kí àwọn adágún omi tí esùsú* kún inú wọn gbẹ táútáú.+

16 Màá mú àwọn afọ́jú gba ọ̀nà tí wọn ò mọ̀,+

Màá sì mú kí wọ́n gba ọ̀nà tó ṣàjèjì sí wọn.+

Màá sọ òkùnkùn tó wà níwájú wọn di ìmọ́lẹ̀,+

Màá sì sọ ilẹ̀ tó rí gbágungbàgun di ilẹ̀ tó tẹ́jú.+

Ohun tí màá ṣe fún wọn nìyí, mi ò sì ní fi wọ́n sílẹ̀.”

17 A máa dá wọn pa dà, ojú sì máa tì wọ́n gidigidi,

Àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé ère gbígbẹ́,

Àwọn tó ń sọ fún àwọn ère onírin* pé: “Ẹ̀yin ni ọlọ́run wa.”+

18 Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ̀yin adití;

Ẹ wò, kí ẹ sì rí i, ẹ̀yin afọ́jú.+

19 Ta ló fọ́jú yàtọ̀ sí ìránṣẹ́ mi,

Tó dití bí ẹni tí mo rán níṣẹ́?

Ta ló fọ́jú bí ẹni tí a san lẹ́san,

Tó fọ́jú bí ìránṣẹ́ Jèhófà?+

20 O rí ọ̀pọ̀ nǹkan, àmọ́ o ò kíyè sí i.

O la etí rẹ sílẹ̀, àmọ́ o ò gbọ́.+

21 Nítorí òdodo rẹ̀,

Inú Jèhófà máa dùn láti mú kí òfin* níyì, kó sì ṣe é lógo.

22 Àmọ́ wọ́n ti kó àwọn èèyàn yìí lẹ́rù, wọ́n sì ti kó ohun ìní wọn lọ;+

Wọ́n ti sé gbogbo wọn mọ́ inú ihò, wọ́n sì ti fi wọ́n pa mọ́ sínú ẹ̀wọ̀n.+

Wọ́n ti kó ẹrù wọn láìsí ẹni tó máa gbà wọ́n sílẹ̀,+

Wọ́n sì ti kó ohun ìní wọn láìsí ẹni tó máa sọ pé: “Ẹ kó o pa dà!”

23 Ta ló máa gbọ́ èyí nínú yín?

Ta ló máa fiyè sílẹ̀, kó sì fetí sílẹ̀ torí àkókò tó ń bọ̀?

24 Ta ló ti mú kí wọ́n kó ohun ìní Jékọ́bù,

Tó sì mú kí wọ́n kó ẹrù Ísírẹ́lì?

Ṣebí Jèhófà ni, Ẹni tí a ṣẹ̀?

Wọ́n kọ̀ láti rìn ní àwọn ọ̀nà Rẹ̀,

Wọn ò sì ṣègbọràn sí òfin* Rẹ̀.+

25 Torí náà, Ó ń da ìhónú lé e lórí,

Ìrunú rẹ̀ àti ìbínú ogun.+

Ó jẹ gbogbo ohun tó yí i ká run, àmọ́ kò fiyè sí i.+

Ó jó o, àmọ́ kò fọkàn sí i.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́