ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 44
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ọlọ́run máa bù kún àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ (1-5)

      • Kò sí Ọlọ́run míì àfi Jèhófà (6-8)

      • Àwọn òrìṣà tí èèyàn ṣe kò já mọ́ nǹkan kan (9-20)

      • Jèhófà, Olùtúnrà Ísírẹ́lì (21-23)

      • Ipasẹ̀ Kírúsì ni wọ́n máa pa dà (24-28)

Àìsáyà 44:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 17:1, 7; 35:10, 11; Ais 41:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 62

Àìsáyà 44:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “láti ìgbà tí wọ́n ti bí ọ.”

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Adúróṣinṣin,” orúkọ oyè tí wọ́n fún Ísírẹ́lì.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 43:1; 44:21
  • +Ais 41:10; Jer 30:10
  • +Di 32:15; 33:5, 26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 62

Àìsáyà 44:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ilẹ̀.”

  • *

    Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:17
  • +Ais 32:14, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 62-64

Àìsáyà 44:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 61:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 62-64

Àìsáyà 44:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 13:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 64

Àìsáyà 44:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 33:5; Ais 33:22
  • +Ẹk 6:6; Jer 50:34
  • +Ais 41:4; 48:12; Ifi 22:13
  • +Di 4:35, 39; Ais 43:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 27-28

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 64-65

Àìsáyà 44:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 46:9
  • +Ais 43:9; 45:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 64-65

Àìsáyà 44:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:10
  • +Ais 43:10
  • +Di 32:4; 2Sa 22:32

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2007, ojú ìwé 10

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 64-65

Àìsáyà 44:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, àwọn ère náà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 10:14; 1Ọb 18:26; 1Kọ 8:4
  • +Sm 115:4, 5
  • +Jer 51:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 66

Àìsáyà 44:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ère dídà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 10:5; Iṣe 19:26

Àìsáyà 44:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 5:3, 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 66

Àìsáyà 44:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ohun èlò tí wọ́n fi ń gbẹ́ nǹkan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:19; 41:7; 46:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 66-67

Àìsáyà 44:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “sí ojúbọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:4; Di 4:15, 16; Iṣe 17:29
  • +Di 27:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 66-67

Àìsáyà 44:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “igi óákù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:20; Jer 10:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 67-68

Àìsáyà 44:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:4, 5; Le 26:1; Hab 2:18, 19

Àìsáyà 44:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 37:37, 38; 45:20; 46:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 67-68

Àìsáyà 44:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 10:8, 14; Ro 1:21-23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 68

Àìsáyà 44:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìtì igi gbígbẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 27:15

Àìsáyà 44:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 68

Àìsáyà 44:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 43:1; 44:1
  • +Ais 49:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 69-70

Àìsáyà 44:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 51:1; 103:12; Ais 1:18; 43:25; Jer 33:8; Iṣe 3:19
  • +Ais 1:27; 48:20; 59:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 69-70

Àìsáyà 44:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:13; 55:12
  • +Ais 60:21

Àìsáyà 44:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 44:6
  • +Job 26:7; Ais 40:22
  • +Ais 42:5; 48:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 70-71

Àìsáyà 44:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn wòlíì èké.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ho 9:7
  • +2Sa 15:31; Ais 29:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/1997, ojú ìwé 8-9

Àìsáyà 44:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 23:14; Ais 55:10, 11; Sek 1:6
  • +Sm 147:2
  • +Ais 60:10
  • +Ais 61:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 70-71

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 150-151

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/1997, ojú ìwé 8-9

Àìsáyà 44:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:15; Jer 50:38; Ifi 16:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 3

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 70-72

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 150-151

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/1997, ojú ìwé 9-11

    5/15/1993, ojú ìwé 5

    Ìwé fún Gbogbo Ènìyàn, ojú ìwé 27-28

    Ìmọ̀, ojú ìwé 18

Àìsáyà 44:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 1:1, 2; Ais 41:25; 45:1; 46:11; Da 10:1
  • +Ais 48:14
  • +2Kr 36:22, 23; Ẹsr 6:3; Ais 45:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 3

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 70-72

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 150-151

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 18-19

Àwọn míì

Àìsá. 44:1Jẹ 17:1, 7; 35:10, 11; Ais 41:8
Àìsá. 44:2Ais 43:1; 44:21
Àìsá. 44:2Ais 41:10; Jer 30:10
Àìsá. 44:2Di 32:15; 33:5, 26
Àìsá. 44:3Ais 41:17
Àìsá. 44:3Ais 32:14, 15
Àìsá. 44:4Ais 61:11
Àìsá. 44:5Sek 13:9
Àìsá. 44:6Di 33:5; Ais 33:22
Àìsá. 44:6Ẹk 6:6; Jer 50:34
Àìsá. 44:6Ais 41:4; 48:12; Ifi 22:13
Àìsá. 44:6Di 4:35, 39; Ais 43:10
Àìsá. 44:7Ais 46:9
Àìsá. 44:7Ais 43:9; 45:21
Àìsá. 44:8Ais 41:10
Àìsá. 44:8Ais 43:10
Àìsá. 44:8Di 32:4; 2Sa 22:32
Àìsá. 44:9Ond 10:14; 1Ọb 18:26; 1Kọ 8:4
Àìsá. 44:9Sm 115:4, 5
Àìsá. 44:9Jer 51:17
Àìsá. 44:10Jer 10:5; Iṣe 19:26
Àìsá. 44:111Sa 5:3, 7
Àìsá. 44:12Ais 40:19; 41:7; 46:6
Àìsá. 44:13Ẹk 20:4; Di 4:15, 16; Iṣe 17:29
Àìsá. 44:13Di 27:15
Àìsá. 44:14Ais 40:20; Jer 10:3
Àìsá. 44:15Ẹk 20:4, 5; Le 26:1; Hab 2:18, 19
Àìsá. 44:17Ais 37:37, 38; 45:20; 46:7
Àìsá. 44:18Jer 10:8, 14; Ro 1:21-23
Àìsá. 44:19Di 27:15
Àìsá. 44:21Ais 43:1; 44:1
Àìsá. 44:21Ais 49:15
Àìsá. 44:22Sm 51:1; 103:12; Ais 1:18; 43:25; Jer 33:8; Iṣe 3:19
Àìsá. 44:22Ais 1:27; 48:20; 59:20
Àìsá. 44:23Ais 49:13; 55:12
Àìsá. 44:23Ais 60:21
Àìsá. 44:24Ais 44:6
Àìsá. 44:24Job 26:7; Ais 40:22
Àìsá. 44:24Ais 42:5; 48:13
Àìsá. 44:25Ho 9:7
Àìsá. 44:252Sa 15:31; Ais 29:14
Àìsá. 44:26Joṣ 23:14; Ais 55:10, 11; Sek 1:6
Àìsá. 44:26Sm 147:2
Àìsá. 44:26Ais 60:10
Àìsá. 44:26Ais 61:4
Àìsá. 44:27Ais 42:15; Jer 50:38; Ifi 16:12
Àìsá. 44:28Ẹsr 1:1, 2; Ais 41:25; 45:1; 46:11; Da 10:1
Àìsá. 44:28Ais 48:14
Àìsá. 44:282Kr 36:22, 23; Ẹsr 6:3; Ais 45:13
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 44:1-28

Àìsáyà

44 “Wá fetí sílẹ̀, ìwọ Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi

Àti ìwọ Ísírẹ́lì, ẹni tí mo yàn.+

 2 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

Aṣẹ̀dá rẹ àti Ẹni tó dá ọ,+

Ẹni tó ràn ọ́ lọ́wọ́ látinú oyún:*

‘Má bẹ̀rù, Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi+

Àti ìwọ, Jéṣúrúnì,*+ ẹni tí mo yàn.

 3 Torí màá da omi sórí ẹni* tí òùngbẹ ń gbẹ,+

Màá sì mú kí odò ṣàn lórí ilẹ̀ gbígbẹ.

Màá da ẹ̀mí mi sórí ọmọ* rẹ +

Àti ìbùkún mi sórí àwọn àtọmọdọ́mọ rẹ.

 4 Wọ́n sì máa rú yọ bíi pé wọ́n yọ láàárín koríko tútù,+

Bí àwọn igi pọ́pílà ní etí omi tó ń ṣàn.

 5 Ẹnì kan máa sọ pé: “Ti Jèhófà ni mí.”+

Ẹlòmíì máa fi orúkọ Jékọ́bù pe ara rẹ̀,

Ẹlòmíì sì máa kọ ọ́ sí ọwọ́ rẹ̀ pé: “Ti Jèhófà.”

Á sì máa jẹ́ orúkọ Ísírẹ́lì.’

 6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun:

‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+

Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+

 7 Ta ló dà bí èmi?+

Kó pè, kó sọ ọ́, kó sì fi ẹ̀rí hàn mí!+

Látìgbà tí mo ti gbé àwọn èèyàn àtijọ́ kalẹ̀,

Jẹ́ kí wọ́n sọ àwọn ohun tó ń bọ̀

Àti ohun tí kò tíì ṣẹlẹ̀.

 8 Ẹ má ṣe jẹ́ kí jìnnìjìnnì bá yín,

Ẹ má sì jẹ́ kí ìbẹ̀rù sọ ọkàn yín domi.+

Ṣebí mo ti sọ fún ẹnì kọ̀ọ̀kan yín ṣáájú, tí mo sì kéde rẹ̀?

Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi.+

Ṣé Ọlọ́run kankan wà yàtọ̀ sí mi ni?

Rárá, kò sí Àpáta míì;+ mi ò mọ ìkankan.’”

 9 Gbogbo àwọn tó ń ṣe ère gbígbẹ́ ò já mọ́ nǹkan kan,

Àwọn ohun tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí kò ní ṣàǹfààní rárá.+

Bí wọ́n tiẹ̀ jẹ́ ẹlẹ́rìí wọn, wọn* ò rí nǹkan kan, wọn ò sì mọ nǹkan kan,+

Torí náà, ojú máa ti àwọn tó ṣe wọ́n.+

10 Ta ló máa ṣe ọlọ́run tàbí kó ṣe ère onírin*

Tí kò lè ṣàǹfààní rárá?+

11 Wò ó! Ojú máa ti gbogbo àwọn alájọṣe rẹ̀!+

Èèyàn lásán ni àwọn oníṣẹ́ ọnà.

Kí gbogbo wọn kóra jọ, kí wọ́n sì dúró.

Jìnnìjìnnì máa bò wọ́n, ojú sì máa tì wọ́n pa pọ̀.

12 Alágbẹ̀dẹ ń fi irinṣẹ́ rẹ̀* lu irin lórí ẹyin iná.

Ó ń fi àwọn òòlù ṣe é,

Ó ń fi apá rẹ̀ tó lágbára ṣe é.+

Ebi wá ń pa á, okun sì tán nínú rẹ̀;

Kò mu omi, ó sì ti rẹ̀ ẹ́.

13 Agbẹ́gi na okùn ìdíwọ̀n, ó fi ẹfun pupa sàmì sí i.

Ó fi ìfági fá a, ó sì fi kọ́ńpáàsì sàmì sí i.

Ó ṣe é kó lè rí bí èèyàn,+

Ó mú kó rẹwà bí èèyàn,

Kó lè jókòó sínú ilé.*+

14 Ẹnì kan wà tó jẹ́ pé iṣẹ́ rẹ̀ ni kó máa gé igi kédárì lulẹ̀.

Ó mú oríṣi igi kan, ìyẹn igi ràgàjì,*

Ó sì jẹ́ kó di igi ńlá láàárín àwọn igi igbó.+

Ó gbin igi lọ̀rẹ́ẹ̀lì, òjò sì mú kó dàgbà.

15 Ó wá di ohun tí èèyàn lè fi dáná.

Ó mú lára rẹ̀, ó sì fi yáná;

Ó dá iná, ó sì yan búrẹ́dì.

Àmọ́ ó tún ṣe ọlọ́run kan, ó sì ń sìn ín.

Ó fi ṣe ère gbígbẹ́, ó sì ń forí balẹ̀ fún un.+

16 Ó fi iná sun ìdajì rẹ̀;

Ìdajì yẹn ló fi yan ẹran tó ń jẹ, ó sì yó.

Ó tún yáná, ó wá sọ pé:

“Áà! Ara mi ti móoru bí mo ṣe ń wo iná yìí.”

17 Àmọ́ ó fi èyí tó ṣẹ́ kù ṣe ọlọ́run, ó fi ṣe ère gbígbẹ́ fún ara rẹ̀.

Ó ń forí balẹ̀ fún un, ó sì ń sìn ín,

Ó ń gbàdúrà sí i, ó sì ń sọ pé:

“Gbà mí, torí ìwọ ni ọlọ́run mi.”+

18 Wọn ò mọ nǹkan kan, wọn ò lóye nǹkan kan,+

Torí a ti lẹ ojú wọn pa, wọn ò sì lè ríran,

Ọkàn wọn ò sì ní ìjìnlẹ̀ òye.

19 Kò sí ẹni tó rò ó nínú ọkàn rẹ̀,

Tó ní ìmọ̀ tàbí òye, pé:

“Mo ti dáná sun ìdajì rẹ̀,

Ẹyin iná rẹ̀ ni mo fi yan búrẹ́dì, tí mo sì fi yan ẹran tí màá jẹ.

Ṣé ó wá yẹ kí n fi èyí tó kù ṣe ohun ìríra?+

Ṣé ó yẹ kí n máa sin ìtì igi* tí mo gé lára igi?”

20 Ó ń jẹ eérú.

Ọkàn rẹ̀ tí wọ́n ti tàn jẹ ti kó o ṣìnà.

Kò lè gba ara* rẹ̀, kì í sì í sọ pé:

“Ṣé irọ́ kọ́ ló wà lọ́wọ́ ọ̀tún mi yìí?”

21 “Rántí àwọn nǹkan yìí, ìwọ Jékọ́bù àti ìwọ Ísírẹ́lì,

Torí pé ìránṣẹ́ mi ni ọ́.

Èmi ni mo dá ọ, ìránṣẹ́ mi sì ni ọ́.+

Ìwọ Ísírẹ́lì, mi ò ní gbàgbé rẹ.+

22 Màá nu àwọn àṣìṣe rẹ kúrò bíi pé mo fi ìkùukùu* nù ún,+

Màá sì nu àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ kúrò bíi pé mo fi àwọsánmà tó ṣú bolẹ̀ nù ún.

Pa dà sọ́dọ̀ mi, torí màá tún ọ rà.+

23 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run,

Torí Jèhófà ti ṣe nǹkan kan!

Ẹ kígbe ìṣẹ́gun, ẹ̀yin ibi tó jìn ní ilẹ̀!

Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin òkè,+

Ẹ̀yin igbó àti gbogbo igi yín!

Torí Jèhófà ti tún Jékọ́bù rà,

Ó sì ń fi ẹwà rẹ̀ hàn lára Ísírẹ́lì.”+

24 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà rẹ,+

Ẹni tó dá ọ látìgbà tí o ti wà nínú oyún:

“Èmi ni Jèhófà, ẹni tó dá ohun gbogbo.

Èmi fúnra mi ni mo na ọ̀run,+

Mo sì tẹ́ ilẹ̀ ayé.+

Ta ló wà pẹ̀lú mi?

25 Màá mú kí iṣẹ́ àmì àwọn tó ń sọ̀rọ̀ asán* já sí pàbó,

Èmi sì ni Ẹni tó ń mú kí àwọn woṣẹ́woṣẹ́ máa ṣe bí òpònú;+

Ẹni tó ń da nǹkan rú mọ́ àwọn ọlọ́gbọ́n lójú,

Tó sì ń sọ ìmọ̀ wọn di ti òmùgọ̀;+

26 Ẹni tó ń mú kí ọ̀rọ̀ ìránṣẹ́ rẹ̀ ṣẹ,

Tó sì ń mú àsọtẹ́lẹ̀ àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀ ṣẹ délẹ̀délẹ̀;+

Ẹni tó ń sọ nípa Jerúsálẹ́mù pé, ‘Wọ́n máa gbé inú rẹ̀’+

Àti nípa àwọn ìlú Júdà pé, ‘Wọ́n máa tún wọn kọ́,+

Màá sì mú kí àwọn ibi tó ti dahoro níbẹ̀ pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀’;+

27 Ẹni tó ń sọ fún ibú omi pé, ‘Gbẹ,

Màá sì mú kí gbogbo odò rẹ gbẹ táútáú’;+

28 Ẹni tó ń sọ nípa Kírúsì+ pé, ‘Òun ni olùṣọ́ àgùntàn mi,

Ó sì máa ṣe gbogbo ohun tí mo fẹ́ délẹ̀délẹ̀’;+

Ẹni tó ń sọ nípa Jerúsálẹ́mù pé, ‘Wọ́n máa tún un kọ́’

Àti nípa tẹ́ńpìlì pé, ‘Wọ́n máa fi ìpìlẹ̀ rẹ lélẹ̀.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́