ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 32
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Diutarónómì

      • Orin tí Mósè kọ (1-47)

        • Jèhófà jẹ́ Àpáta (4)

        • Ísírẹ́lì gbàgbé Àpáta rẹ̀ (18)

        • “Tèmi ni ẹ̀san” (35)

        • “Ẹ bá àwọn èèyàn rẹ̀ yọ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè” (43)

      • Mósè máa kú sórí Òkè Nébò (48-52)

Diutarónómì 32:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2020, ojú ìwé 10

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2016, ojú ìwé 31-32

Diutarónómì 32:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:26
  • +1Kr 29:11; Sm 145:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2020, ojú ìwé 10-11

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 10/2020, ojú ìwé 2

Diutarónómì 32:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 22:31; Sm 18:2; 19:7; Jem 1:17
  • +Sm 33:5
  • +Di 7:9; 1Pe 4:19
  • +Di 25:16
  • +Jẹ 18:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 112

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2009, ojú ìwé 14

    9/15/2004, ojú ìwé 27

Diutarónómì 32:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:27; Ond 2:19; Sm 14:1
  • +Ais 1:4
  • +Sm 78:8; Lk 9:41

Diutarónómì 32:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 1:2
  • +Jer 4:22
  • +Ẹk 4:22; Di 32:18; Ais 63:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2008, ojú ìwé 5

Diutarónómì 32:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 13:14; Sm 44:1

Diutarónómì 32:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ìran èèyàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:5; Sm 115:16
  • +Jẹ 11:9
  • +Di 2:5, 19; Iṣe 17:26
  • +Jẹ 15:18; Ẹk 23:31

Diutarónómì 32:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:5; Di 7:6
  • +Sm 78:71

Diutarónómì 32:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 8:14, 15
  • +Jer 2:6
  • +Ne 9:19, 20
  • +Sek 2:8

Diutarónómì 32:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2001, ojú ìwé 9

    6/15/2001, ojú ìwé 26

    6/15/1996, ojú ìwé 11

Diutarónómì 32:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Jékọ́bù.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 1:31
  • +Ais 43:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2001, ojú ìwé 9

    6/15/2001, ojú ìwé 26

Diutarónómì 32:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 33:29
  • +Di 8:7, 8

Diutarónómì 32:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ọ̀rá àgùntàn.”

  • *

    Tàbí “wíìtì.”

  • *

    Ní Héb., “ọ̀rá kíndìnrín àlìkámà.”

  • *

    Tàbí “omi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 147:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2015, ojú ìwé 15

    9/15/2004, ojú ìwé 27

Diutarónómì 32:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Adúróṣinṣin,” orúkọ oyè tí wọ́n fún Ísírẹ́lì.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:20; Ne 9:25
  • +Ais 1:4; Ho 13:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 9/2021,

Diutarónómì 32:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 2:12; 1Ọb 14:22; 1Kọ 10:21, 22
  • +2Ọb 23:13; Isk 8:17

Diutarónómì 32:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 17:7; Sm 106:37; 1Kọ 10:20

Diutarónómì 32:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 106:21; Ais 17:10; Jer 2:32
  • +Di 4:34

Diutarónómì 32:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 2:14; Sm 78:59

Diutarónómì 32:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:17
  • +Di 32:5; Ais 65:2; Mt 17:17
  • +Ais 1:2

Diutarónómì 32:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mú kí n jowú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 96:5; 1Kọ 10:21, 22
  • +1Sa 12:10, 21
  • +Ho 2:23; Ro 9:25; 11:11; 1Pe 2:10
  • +Ro 10:19

Diutarónómì 32:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ṣìọ́ọ̀lù,” ìyẹn ibojì aráyé. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ida 4:11
  • +Emọ 9:2

Diutarónómì 32:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:53
  • +Di 28:21, 22
  • +Le 26:22

Diutarónómì 32:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ida 1:20
  • +Isk 7:15
  • +2Kr 36:17; Ida 2:21

Diutarónómì 32:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 12:22; Isk 20:14
  • +Ẹk 32:12; Nọ 14:15, 16
  • +Sm 115:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 5/2017,

Diutarónómì 32:28

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “tó kọ etí ikún sí ìmọ̀ràn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 13:15

Diutarónómì 32:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 81:13
  • +Ho 14:9
  • +Jer 2:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 35

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2008, ojú ìwé 8-11

    7/1/1999, ojú ìwé 32

Diutarónómì 32:30

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 24:24
  • +Ond 2:14; 1Sa 12:9

Diutarónómì 32:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 2:2
  • +Ẹk 14:25; 1Sa 4:8; Ẹsr 1:2, 3

Diutarónómì 32:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 7
  • +Ais 5:4; Jer 2:21

Diutarónómì 32:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 2:5

Diutarónómì 32:35

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Na 1:2; Ro 12:19; Heb 10:30
  • +Sm 73:12, 18

Diutarónómì 32:36

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “pèrò dà nípa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 10:30
  • +Ond 2:18; Sm 90:13; 106:45; 135:14

Diutarónómì 32:37

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 10:14

Diutarónómì 32:38

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹbọ wọn tó dáa jù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ho 2:8; 1Kọ 10:20, 21

Diutarónómì 32:39

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:4; 48:12
  • +Di 4:35
  • +1Sa 2:6; Sm 68:20
  • +2Kr 21:16, 18
  • +Nọ 12:13; Jer 17:14
  • +Ais 43:13

Diutarónómì 32:40

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 1:17; Ifi 10:5, 6

Diutarónómì 32:41

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Na 1:3
  • +Ais 1:24; 59:18

Diutarónómì 32:43

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wẹ ilẹ̀ àwọn èèyàn rẹ̀ mọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:2, 3; 1Ọb 8:43; Ro 3:29; 15:10
  • +2Ọb 9:7; Ifi 6:10
  • +Mik 5:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/1998, ojú ìwé 11-12, 17

    4/15/1991, ojú ìwé 12-13

Diutarónómì 32:44

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Orúkọ tí Jóṣúà ń jẹ́ gangan. Hóṣéà ni ìkékúrú Hòṣáyà, ó túmọ̀ sí “Ẹni Tí Jáà Gbà Là; Jáà Ti Gbà Là.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 15:3
  • +Nọ 11:28; Di 31:22, 23

Diutarónómì 32:46

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 11:18
  • +Di 6:6, 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2001, ojú ìwé 19

Diutarónómì 32:47

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 18:5; Di 30:19; Ro 10:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2008, ojú ìwé 5-6

Diutarónómì 32:49

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 27:12
  • +Di 34:1
  • +Jẹ 10:19; 15:18; Joṣ 1:3

Diutarónómì 32:50

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Àkànlò èdè yìí ni wọ́n fi ń sọ pé èèyàn kú.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 20:28; 33:38

Diutarónómì 32:51

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 20:12, 13
  • +Le 22:32; Ais 8:13

Diutarónómì 32:52

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 27:13, 14; Di 3:27; 34:4, 5

Àwọn míì

Diu. 32:3Jo 17:26
Diu. 32:31Kr 29:11; Sm 145:3
Diu. 32:42Sa 22:31; Sm 18:2; 19:7; Jem 1:17
Diu. 32:4Sm 33:5
Diu. 32:4Di 7:9; 1Pe 4:19
Diu. 32:4Di 25:16
Diu. 32:4Jẹ 18:25
Diu. 32:5Di 31:27; Ond 2:19; Sm 14:1
Diu. 32:5Ais 1:4
Diu. 32:5Sm 78:8; Lk 9:41
Diu. 32:6Ais 1:2
Diu. 32:6Jer 4:22
Diu. 32:6Ẹk 4:22; Di 32:18; Ais 63:16
Diu. 32:7Ẹk 13:14; Sm 44:1
Diu. 32:8Jẹ 10:5; Sm 115:16
Diu. 32:8Jẹ 11:9
Diu. 32:8Di 2:5, 19; Iṣe 17:26
Diu. 32:8Jẹ 15:18; Ẹk 23:31
Diu. 32:9Ẹk 19:5; Di 7:6
Diu. 32:9Sm 78:71
Diu. 32:10Di 8:14, 15
Diu. 32:10Jer 2:6
Diu. 32:10Ne 9:19, 20
Diu. 32:10Sek 2:8
Diu. 32:11Ẹk 19:4
Diu. 32:12Di 1:31
Diu. 32:12Ais 43:12
Diu. 32:13Di 33:29
Diu. 32:13Di 8:7, 8
Diu. 32:14Sm 147:14
Diu. 32:15Di 31:20; Ne 9:25
Diu. 32:15Ais 1:4; Ho 13:6
Diu. 32:16Ond 2:12; 1Ọb 14:22; 1Kọ 10:21, 22
Diu. 32:162Ọb 23:13; Isk 8:17
Diu. 32:17Le 17:7; Sm 106:37; 1Kọ 10:20
Diu. 32:18Sm 106:21; Ais 17:10; Jer 2:32
Diu. 32:18Di 4:34
Diu. 32:19Ond 2:14; Sm 78:59
Diu. 32:20Di 31:17
Diu. 32:20Di 32:5; Ais 65:2; Mt 17:17
Diu. 32:20Ais 1:2
Diu. 32:21Sm 96:5; 1Kọ 10:21, 22
Diu. 32:211Sa 12:10, 21
Diu. 32:21Ho 2:23; Ro 9:25; 11:11; 1Pe 2:10
Diu. 32:21Ro 10:19
Diu. 32:22Ida 4:11
Diu. 32:22Emọ 9:2
Diu. 32:24Di 28:53
Diu. 32:24Di 28:21, 22
Diu. 32:24Le 26:22
Diu. 32:25Ida 1:20
Diu. 32:25Isk 7:15
Diu. 32:252Kr 36:17; Ida 2:21
Diu. 32:271Sa 12:22; Isk 20:14
Diu. 32:27Ẹk 32:12; Nọ 14:15, 16
Diu. 32:27Sm 115:2
Diu. 32:28Mt 13:15
Diu. 32:29Sm 81:13
Diu. 32:29Ho 14:9
Diu. 32:29Jer 2:19
Diu. 32:302Kr 24:24
Diu. 32:30Ond 2:14; 1Sa 12:9
Diu. 32:311Sa 2:2
Diu. 32:31Ẹk 14:25; 1Sa 4:8; Ẹsr 1:2, 3
Diu. 32:32Jud 7
Diu. 32:32Ais 5:4; Jer 2:21
Diu. 32:34Ro 2:5
Diu. 32:35Na 1:2; Ro 12:19; Heb 10:30
Diu. 32:35Sm 73:12, 18
Diu. 32:36Heb 10:30
Diu. 32:36Ond 2:18; Sm 90:13; 106:45; 135:14
Diu. 32:37Ond 10:14
Diu. 32:38Ho 2:8; 1Kọ 10:20, 21
Diu. 32:39Ais 41:4; 48:12
Diu. 32:39Di 4:35
Diu. 32:391Sa 2:6; Sm 68:20
Diu. 32:392Kr 21:16, 18
Diu. 32:39Nọ 12:13; Jer 17:14
Diu. 32:39Ais 43:13
Diu. 32:401Ti 1:17; Ifi 10:5, 6
Diu. 32:41Na 1:3
Diu. 32:41Ais 1:24; 59:18
Diu. 32:43Jẹ 12:2, 3; 1Ọb 8:43; Ro 3:29; 15:10
Diu. 32:432Ọb 9:7; Ifi 6:10
Diu. 32:43Mik 5:15
Diu. 32:44Ifi 15:3
Diu. 32:44Nọ 11:28; Di 31:22, 23
Diu. 32:46Di 11:18
Diu. 32:46Di 6:6, 7
Diu. 32:47Le 18:5; Di 30:19; Ro 10:5
Diu. 32:49Nọ 27:12
Diu. 32:49Di 34:1
Diu. 32:49Jẹ 10:19; 15:18; Joṣ 1:3
Diu. 32:50Nọ 20:28; 33:38
Diu. 32:51Nọ 20:12, 13
Diu. 32:51Le 22:32; Ais 8:13
Diu. 32:52Nọ 27:13, 14; Di 3:27; 34:4, 5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
  • 39
  • 40
  • 41
  • 42
  • 43
  • 44
  • 45
  • 46
  • 47
  • 48
  • 49
  • 50
  • 51
  • 52
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Diutarónómì 32:1-52

Diutarónómì

32 “Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ̀yin ọ̀run, màá sì sọ̀rọ̀;

Kí ayé sì gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu mi.

 2 Ìtọ́ni mi máa rọ̀ bí òjò;

Ọ̀rọ̀ mi á sì sẹ̀ bí ìrì,

Bí òjò winniwinni sórí koríko

Àti ọ̀wààrà òjò sórí ewéko.

 3 Torí màá kéde orúkọ Jèhófà.+

Ẹ sọ bí Ọlọ́run+ wa ṣe tóbi tó!

 4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,

Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀.

Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+

Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+

 5 Àwọn ló hùwà ìbàjẹ́.+

Wọn kì í ṣe ọmọ rẹ̀, àwọn ló kan àbùkù.+

Ìran alárèékérekè àti oníbékebèke ni wọ́n!+

 6 Ṣé bó ṣe yẹ kí ẹ ṣe sí Jèhófà+ nìyí,

Ẹ̀yin òmùgọ̀ àti aláìlọ́gbọ́n èèyàn?+

Ṣebí òun ni Bàbá yín tó mú kí ẹ wà,+

Ẹni tó dá yín, tó sì fìdí yín múlẹ̀ gbọn-in?

 7 Ẹ rántí ìgbà àtijọ́;

Ẹ ronú nípa ọdún àwọn ìran tó ti kọjá.

Bi bàbá rẹ, á sì sọ fún ọ;+

Bi àwọn àgbààgbà rẹ, wọ́n á sì jẹ́ kí o mọ̀.

 8 Nígbà tí Ẹni Gíga Jù Lọ fún àwọn orílẹ̀-èdè ní ogún+ wọn,

Nígbà tó ya àwọn ọmọ Ádámù* sọ́tọ̀ọ̀tọ̀,+

Ó pààlà fún àwọn èèyàn+

Gẹ́gẹ́ bí iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+

 9 Torí àwọn èèyàn Jèhófà ni ìpín+ rẹ̀;

Jékọ́bù ni ogún+ rẹ̀.

10 Ó rí i nínú aginjù,+

Ní aṣálẹ̀,+ tó ṣófo, tó ń hu.

Ó yí i ká kó lè dáàbò bò ó, ó tọ́jú rẹ̀,+

Ó sì ṣọ́ ọ bí ọmọlójú+ rẹ̀.

 11 Bí ẹyẹ idì ṣe ń ru ìtẹ́ rẹ̀ sókè,

Tó ń rá bàbà lórí àwọn ọmọ rẹ̀ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ gúnyẹ̀ẹ́,

Tó ń na àwọn ìyẹ́ rẹ̀ jáde láti fi gbé wọn,

Tó ń gbé wọn sórí apá+ rẹ̀,

 12 Jèhófà nìkan ló ń darí rẹ̀;*+

Kò sí ọlọ́run àjèjì kankan pẹ̀lú rẹ̀.+

 13 Ó mú kó gun àwọn ibi gíga+ ayé,

Kó lè jẹ irè oko.+

Ó fi oyin inú àpáta bọ́ ọ

Àti òróró látinú akọ àpáta,

 14 Bọ́tà ọ̀wọ́ ẹran àti wàrà agbo ẹran,

Pẹ̀lú àgùntàn tó dáa jù,*

Àwọn àgbò Báṣánì àti àwọn òbúkọ,

Pẹ̀lú àlìkámà*+ tó dáa jù;*

O sì mu wáìnì tó tinú ẹ̀jẹ̀* èso àjàrà jáde.

 15 Nígbà tí Jéṣúrúnì* sanra tán, ó di ọlọ̀tẹ̀, ó sì ń tàpá.

O ti sanra, o ti ki, o sì ti kún.+

Ó wá pa Ọlọ́run tì, ẹni tó dá a,+

Ó sì fojú àbùkù wo Àpáta ìgbàlà rẹ̀.

 16 Wọ́n fi àwọn ọlọ́run àjèjì+ mú un bínú;

Wọ́n ń fi àwọn ohun ìríra+ múnú bí i.

 17 Àwọn ẹ̀mí èṣù ni wọ́n rúbọ sí, kì í ṣe Ọlọ́run,+

Wọ́n ń rúbọ sí àwọn ọlọ́run tí wọn ò mọ̀,

Àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ dé lẹ́nu àìpẹ́ yìí,

Sí àwọn ọlọ́run tí àwọn baba ńlá yín ò mọ̀.

 18 O gbàgbé Àpáta+ tó jẹ́ bàbá rẹ,

O ò sì rántí Ọlọ́run tó bí ọ.+

 19 Nígbà tí Jèhófà rí i, ó kọ̀ wọ́n,+

Torí àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ àtàwọn ọmọbìnrin rẹ̀ ṣẹ̀ ẹ́.

 20 Ó wá sọ pé, ‘Màá fojú pa mọ́ fún wọn;+

Màá wo ohun tó máa gbẹ̀yìn wọn.

Torí ìran oníwà burúkú ni wọ́n,+

Àwọn aláìṣòótọ́ ọmọ.+

 21 Wọ́n ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run+ mú mi bínú;*

Wọ́n ti fi àwọn òrìṣà+ wọn tí kò ní láárí múnú bí mi.

Torí náà, màá fi àwọn tí kì í ṣe èèyàn+ mú kí wọ́n jowú;

Màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀+ mú wọn bínú.

 22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,

Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+

Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,

Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè.

 23 Màá fi kún àwọn ìyọnu wọn;

Màá sì ta gbogbo ọfà mi lù wọ́n.

 24 Ebi+ máa tán wọn lókun,

Akọ ibà máa gbé wọn mì, wọ́n á sì pa run+ pátápátá.

Màá rán eyín àwọn ẹranko sí wọn,+

Àti oró àwọn ẹran tó ń fàyà fà lórí ilẹ̀.

 25 Ní ìta, idà máa mú kí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀ wọ́n;+

Nínú ilé, jìnnìjìnnì+ á bò wọ́n,

Ọ̀dọ́kùnrin àti wúńdíá,

Ọmọ ọwọ́ àti ẹni tó ní ewú lórí.+

 26 Ǹ bá sọ pé: “Màá tú wọn ká;

Màá mú kí àwọn èèyàn gbàgbé wọn,”

 27 Tí kì í bá ṣe pé mò ń bẹ̀rù ohun tí ọ̀tá máa ṣe,+

Torí àwọn elénìní lè túmọ̀ rẹ̀ sí nǹkan míì.+

Wọ́n lè sọ pé: “Ọwọ́ wa ti mókè;+

Jèhófà kọ́ ló ṣe gbogbo èyí.”

 28 Torí orílẹ̀-èdè tí kò ní làákàyè* ni wọ́n,

Kò sí ẹni tó ní òye láàárín wọn.+

 29 Ká sọ pé wọ́n gbọ́n ni!+ Wọn ì bá ro ọ̀rọ̀ yìí dáadáa.+

Kí wọ́n ro ibi tó máa já sí.+

 30 Báwo ni ẹnì kan ṣe lè lé ẹgbẹ̀rún kan (1,000),

Kí ẹni méjì sì mú kí ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) sá?+

Tí kì í bá ṣe pé Àpáta wọn ti tà wọ́n,+

Tí Jèhófà sì ti fi wọ́n lé ọ̀tá lọ́wọ́.

 31 Torí àpáta wọn kò dà bí Àpáta+ wa,

Àwọn ọ̀tá wa pàápàá ti mọ èyí.+

 32 Torí inú àjàrà Sódómù ni àjàrà wọn ti wá

Àti látinú ilẹ̀ onípele Gòmórà.+

Àwọn èso àjàrà onímájèlé ni èso àjàrà wọn,

Àwọn òṣùṣù wọn korò.+

 33 Oró ejò ni wáìnì wọn,

Oró burúkú àwọn ṣèbé.

 34 Ṣebí ọ̀dọ̀ mi ni mo tọ́jú rẹ̀ sí,

Tí mo sé e mọ́ ilé ìkẹ́rùsí+ mi?

 35 Tèmi ni ẹ̀san àti ìyà ẹ̀ṣẹ̀,+

Ní àkókò náà tí ẹsẹ̀ wọn máa yọ̀ tẹ̀rẹ́,+

Torí ọjọ́ àjálù wọn sún mọ́lé,

Ohun tó sì ń dúró dè wọ́n máa tètè dé.’

 36 Torí Jèhófà máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn+ rẹ̀,

Ó sì máa káàánú* àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,

Tó bá rí i pé okun wọn ti ń tán,

Tó sì rí i pé àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́ àtàwọn tó ti rẹ̀ ló ṣẹ́ kù.

 37 Ó máa wá sọ pé, ‘Àwọn ọlọ́run+ wọn dà,

Àpáta tí wọ́n sá di,

 38 Tó máa ń jẹ ọ̀rá àwọn ẹbọ wọn,*

Tó ń mu wáìnì ọrẹ ohun mímu+ wọn?

Jẹ́ kí wọ́n dìde wá ràn yín lọ́wọ́.

Kí wọ́n di ibi ààbò fún yín.

 39 Ẹ rí i báyìí pé èmi, àní èmi ni ẹni náà,+

Kò sí ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.+

Mo lè pani, mo sì lè sọni di alààyè.+

Mo lè dá ọgbẹ́+ síni lára, mo sì lè woni sàn,+

Kò sí ẹnì kankan tó lè gbani sílẹ̀ lọ́wọ́ mi.+

 40 Torí mo gbé ọwọ́ mi sókè sí ọ̀run,

Mo sì búra pé: “Bí mo ti wà láàyè títí láé,”+

 41 Tí mo bá pọ́n idà mi tó ń kọ mànà,

Tí mo sì múra ọwọ́ mi sílẹ̀ láti ṣèdájọ́,+

Màá san àwọn ọ̀tá+ mi lẹ́san,

Màá sì fìyà jẹ àwọn tó kórìíra mi.

 42 Màá mú kí ọfà mi mu ẹ̀jẹ̀ yó,

Idà mi á sì jẹ ẹran,

Pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ àwọn tí a pa àti àwọn ẹrú,

Pẹ̀lú orí àwọn aṣáájú ọ̀tá.’

 43 Ẹ bá àwọn èèyàn+ rẹ̀ yọ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè,

Torí ó máa gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,

Ó máa san àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lẹ́san,

Ó sì máa ṣe ètùtù fún ilẹ̀ àwọn èèyàn rẹ̀.”*

44 Mósè ka gbogbo ọ̀rọ̀ orin yìí sí àwọn èèyàn+ náà létí, òun àti Hóṣéà*+ ọmọ Núnì. 45 Lẹ́yìn tí Mósè bá gbogbo Ísírẹ́lì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí tán, 46 ó sọ fún wọn pé: “Ẹ fi gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo fi kìlọ̀ fún yín lónìí+ sọ́kàn, kí ẹ lè pàṣẹ fún àwọn ọmọ yín pé, kí wọ́n rí i pé àwọn ń tẹ̀ lé gbogbo ọ̀rọ̀ Òfin+ yìí. 47 Torí èyí kì í ṣe ọ̀rọ̀ tí kò wúlò fún yín, àmọ́ òun ló máa mú kí ẹ wà láàyè,+ ọ̀rọ̀ yìí sì máa mú kí ẹ̀mí yín gùn lórí ilẹ̀ tí ẹ̀ ń sọdá Jọ́dánì lọ gbà.”

48 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní ọjọ́ yìí kan náà pé: 49 “Gun òkè Ábárímù+ yìí lọ, Òkè Nébò,+ tó wà ní ilẹ̀ Móábù, tó dojú kọ Jẹ́ríkò, kí o sì wo ilẹ̀ Kénáánì, tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kó di tiwọn.+ 50 O máa kú sórí òkè tí o fẹ́ gùn yìí, a ó sì kó ọ jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ,* bí Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ ṣe kú sórí Òkè Hóórì+ gẹ́lẹ́, tí wọ́n sì kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀, 51 torí pé ẹ̀yin méjèèjì kò jẹ́ olóòótọ́ sí mi láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, níbi omi Mẹ́ríbà+ ti Kádéṣì ní aginjù Síínì, torí pé ẹ ò fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ lójú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ 52 Ọ̀ọ́kán ni wàá ti rí ilẹ̀ náà, àmọ́ o ò ní wọ ilẹ̀ tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́